id
stringlengths
23
24
text
stringlengths
3
4.68k
anger
float64
0
1
disgust
float64
0
1
fear
float64
0
1
joy
float64
0
1
sadness
float64
0
1
surprise
float64
0
1
language
stringclasses
28 values
yor_train_track_a_02595
Idajọ kootu: Tinubu, Oyetọla ki Adeleke ku oriire
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02596
Wọn ti mu awọn ọmọọta ti wọn da wahala silẹ laarin Hausa ati Yoruba l’Oṣogbo
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02597
Ijọba fofin de awọn alumọjiri to n tọrọ baara loju popo n’llọrin
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02598
Umai Emery: Villarael yan akọ́nimọ̀ọ́gbá Arsenal tẹ́lẹ̀, Emery gẹ́gẹ́ bí akọ́nimọ̀ọ́gbá rẹ̀ tuntun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02599
UK Covid Vaccine: Abẹ́rẹ́ àjẹsára Covid-19 yóò dé sí Nàìjíríà nínú oṣù kíní ọdún 2021
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02600
Kééré o! Ilé aṣòfin America buwọ́lu ìgbèyáwò akọsákọ àti abosábo
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02601
Ni Mọdakẹkẹ, Hammed ati Ayọbami ṣa Wasiu pa, wọn lo n fowo to ri nidii iṣẹ Yahoo ṣakọ sawọn
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02602
Ẹwọn n run nimu ọmọkunrin yii, ayederu owo Naira ni wọn ba lọwọ ẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02603
Ile-ẹjọ to ga ju lọ nilẹ wa da Adeleke lare
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02604
Awọn ọdọ ilu dana sun Gaa Seriki awọn Fulani n’Igangan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02605
Ondo Rape: Pásítọ̀ ní ẹ̀mí èsù ló gbé òun wọ̀ títí òun fi fi ipá bá olóyún oṣù mẹ́jọ lòpọ̀!
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02606
Sunday Igboho: Oloye Toluwalase ti ìlú Àjàṣé-Ilé ní ẹ̀wọ̀n ní ìjìyà fún ṣiṣe ayédèrú ''Passport'' ní Benin Republic
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02607
Divorce: Ilé ẹjọ́ tú ìgbéyàwó ọdún mọ́kànlá ká nítórí pé ìyàwó fí ìbálòpọ̀ dun ọkọ rẹ̀
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_02608
Lekki Toll Gate: Wọ́n ti fi iṣẹ́ ikú ránṣẹ́ sí Mr macaroni torí ó tako ṣíṣí ẹnu bodè Lekki padà
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02609
Ọmọbinrin yii ti fọwọ ara ẹ kọwe sọgba ẹwọn, ọlọpaa lo yinbọn pa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02610
Ọkọ ọlọpaa kọ lu kẹkẹ Marwa n’llọrin, eeyan meji lo ku
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02611
June 12 protest: Ọlọ́pàá yin tíá gaàsì lu àwọn olùwọ́de l'Eko, wọ́n ní ìjà àráàlù
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02612
Funsho Adeolu: Ìwọ̀kuwọ̀ àti ìrìnkurìn obìnrin míì ń fa ìfipábánilòpọ̀
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02613
Xenophobia: Àwọn ọ̀dọ́ kan ń ṣèwọ́de láti pè fún lílé àwọnjì kúrò ní South Africa
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02614
Mama Rainbow dẹni ọgọrin ọdun laye
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02615
Nitori b’awọn Fulani ṣe tun paayan meji l’Owode-Ketu, awọn eeyan sa kuro niluu
0
0
1
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02616
Yellow Fever in Nigeria: Àrún ibà pónjú ti pa ènìyàn 172 ni Nàìjíríà - WHO
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02617
Ọmọ ọdún mẹ́jọ tú àṣírí f'áwọn ọlọ́pàá bí bàbá rẹ̀ ṣe fún ìyá rẹ̀ lọ́rùn pa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02618
Aarẹ Buhari fun Ize-Iyamu ni asia ẹgbẹ APC lati dije sipo gomina l’Edo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02619
Kaadi idibo: Ijọba kede ọjọ Ẹti gẹgẹ bii isinmi fawọn oṣiṣẹ l’Ọṣun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02620
Rògbòdìyàn Iraq fẹjú si, àdó olóró àti ìbọn ń dún lákọlákọ
0
0
1
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02621
Iyabo Ojo: Ojú ọkọ mi ní àwọn adigunjalè ti fipá bá mi lòpọ̀ ní ìgbà karùn-ún
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02622
Ọlọ́run fẹ́ gbé Ekiti gorí ẹṣin ló ṣe ní kí ń díje gómìnà nínú ẹ́gbẹ́ ẹlẹ́ṣin - Segun Oni
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02623
Ijọba Eko bẹrẹ ayẹwo fawọn to n lọ silẹ Mẹka
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02624
Sunday Igboho: Ìkọlù tí ẹ̀ṣọ́ aláàbò ṣe sí Sunday Igboho, Inú wa kò dún sí ìjọba''
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02625
O tan! Joe Biden ti wọle o, oun laarẹ Amerika tuntun
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02626
Kàyééfì Promo: Ìyá, ọmọ tuntun àti olubi ló wà níbùdó ìgbókùsí, àmọ́ òkú ọmọ di àwátì
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02627
Azeez niyawo oun n yan ale, lo ba lu u pa toyun-toyun ni Ṣaki
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02628
Lẹyin ti lanledi pa tẹnanti rẹ tan lo ju oku rẹ si kanga l’Oke-Agbe
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02629
Fayose jẹ agbẹjọ́rò rẹ̀ ní gbèsè ₦900m, ló bá dèrò iléẹjọ́
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02630
Ọwọngogo Naira:Awọn ọmọlooku lawọn ko gba owo atijọ, ni wọn ba gbe POS kalẹ fawọn eeyan
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02631
Awọn aṣọbode ba ọdun Ileya jẹ mọ awọn fayawọ oniṣowo ipinlẹ Ọyọ ati Ọṣun lọwọ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02632
Seyi Makinde: Àwọn obìrin tó dé láti Lebanon sọ ọmọ wọn tuntun jòjòló ní Seyi Makinde
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02633
Ọlọ́run ní kò sí iṣẹ́ tí màá ṣe tí yòó là mí àfi ajíhìnrere - Ojo Ade
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02634
Abba Kyari: Adájọ́ ṣe àfikún sáà tí afurasí yóò ló ní àhámọ́, kó le rọrùn fún NDLEA láti ṣe ìwádìí ẹ̀sùn rẹ̀ lókè òkun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02635
Wọn ma ni wọn ko ri ọmọkunrin adẹrin-in poṣonu nni, Cute Abiọla
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02636
Ta ni ọmọ ẹ̀lẹ̀ yìí, Olorì Tobi Phillips tó ṣẹ̀ṣẹ̀ wọ ààfin Ooni Ife?
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02637
Jumọkẹ binu para ẹ l’Ondo, nitori ti wọn fun un niwee gbele ẹ lẹnu iṣẹ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02638
Covid-19 second wave: ''Ìjọba kò tíì pàṣẹ ìlànà ìtakété-síra-ẹni padà nínú BRT la ò ṣe tíì ma tẹ̀le''
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02639
Ijọba apapọ ṣe ifilọlẹ owo Naira ori ẹrọ ayelujara (eNaira)
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02640
ICPC: Kò fẹ́ẹ̀ sí adájọ́ tó gbọ́ ẹ̀hónú ìbò tí wọn kò fi rìbá lọ̀
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02641
Child Abuse: Oyinye Mbadike ní ìbátan òun mu ọti yó ni òun ṣe dín dùǹdú ìyà fun
0
1
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02642
Lẹyin ipade ti wọn ba Buhari ṣe, APC ti gba pe ilẹ Hausa ni alaga wọn yoo ti jade
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02643
Usman fẹẹ fiyawo rẹ ṣoogun owo, lo ba lẹdi apo pọ pẹlu babalawo lati ji i gbe n’Ilọrin
0
1
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02644
Awọn adigunjale kọ lu banki mẹta n’Ikẹrẹ-Ekiti, eeyan mẹta ni wọn pa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02645
Awọn janduku kọ lu ile Sunday Igboho n’Ibadan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02646
A ti bẹ̀rẹ̀ ètò báyìí lát bẹ́ àwọn Bàbá ńlá wa lọ́wẹ̀ sáwọn tó ṣe ìkọlù sí Ọwọ- Olowo
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02647
N ko kabaamọ rara pe mo kuro lọfiisi gẹgẹ bii igbakeji gomina Ondo-Agboọla
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02648
Awọn ọlọpaa ti mu ọmọbinrin ti ọrẹkunrin ẹ ku sinu otẹẹli ti wọn jọ sun mọju
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02649
Yoruba Nation: Ààrẹ ẹgbẹ VOR sọ pé kí ọmọ Yorùbá di ààrẹ Naijiria kọ́ ni ọ̀nà àbáyọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02650
Aṣiri ohun ti wọn ko ṣe kọlu Aafin mi ree- Oluwoo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02651
Àwọn eèyàn PDP àti APC ti ba ǹkan jẹ́ púpọ̀ ni mo ṣe kúrò níbẹ̀- Rabiu Kwankwaso
0
1
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02652
Sunday Igboho: Ooni, Olujinmi, Olugbon, Akin Osuntokun àtàwọn àgbàgbà Yorùbá forí korí
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02653
Ikoyi house collapse: Ìjọba ìpínlẹ̀ Eko sọ̀rọ̀ lórí ẹni tó ni ilé alájá 21 tó dà wó ní Ikoyi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02654
Kaduna killings: Afurasí mẹ́jọ ti wọ gbaga agbófinró nítorí ìpànìyàn Gúúsù Kaduna
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02655
BBC Africa Eye: Ìwádìí tú àṣírí bí ààrẹ orílẹ̀-èdè DR Congo ṣé lú owó aráàlú ní pónpó
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02656
'Ikú yá ju ẹ̀sín lọ ni mo ṣe dáná sun ara mi'
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02657
Sudan Coup: Mọ̀ si nípa ọ̀gágun Abdel Fattah al-Burhan tó darí ìdìtẹ̀gbàjọba ní Sudan
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02658
Ibo abẹle APC l’Ondo: Eyi ni orukọ awọn ti yoo kopa
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02659
Abẹwo Ladọja si Ọba Balogun: Emi o ni ikunsinu kankan si Olubadan ilẹ Ibadan tuntun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02660
Timothy Adegoke: Rahmon Adedoyin ti sọ̀rọ̀ lórí àbájáde ìwádìí òkú ‘autopsy’ Timothy Adegoke tó kú sílé ìtura rẹ̀ nílé Ifẹ̀
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02661
Inu oṣu keji lawọn akẹkọọ Fasiti Ọbafẹmi Awolọwọ yoo pada sileewe
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02662
Lẹyin to yege ibo aarẹ, Tinubu ṣabẹwo si Ọba Akiolu l’Ekoo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02663
O digba ta a ba ṣe ohun to yẹ ka ṣe ki iṣoro aabo yii too dopin – Babangida
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02664
Fadlullah Adebayo Death in Ukraine: Mọ̀lẹ́bí figbe ta pé ejò lọ́wọ́ nínú lórí ikú akẹ́kọ̀ọ́ tó kú lọ́jọ́ kejì tó dé ilé ẹ̀kọ́ nílẹ̀ òkèèrè
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02665
Gomina Kwara gbe igbimọ kalẹ ti yoo ṣiṣẹ lori ọlọpaa ibilẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02666
Bisọla da omi gbigbona sọkọ ẹ lara l’Ọta, o lọmuti ni
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02667
Ìjìyà ìkọlù sí ọlọ́pàá Nàìjíríà, Njẹ́ ó mọ, àwọn nkan tó lè mú aráàlú tasẹ̀ àgẹ̀rẹ̀ lábẹ́ òfin?
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02668
Gbajabiamila: Wo tuntun tí Gbajabiamila fẹ́ kí ilé aṣojúṣòfin dáwọ́lé lórí ẹni tó bá fẹ́ du ipò òṣèlú
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02669
Wọn tun n bakan bọ: Wọn ni ọga ọlọpaa pata ni yoo maa dari eto Amọtẹkun o
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02670
Fayose, Reno Omokri vs Aisha Buhari: Olùdíje ààrẹ tó bá jẹ́ ìpè Iftar Aisha Buhari kò tó ọkùnrin, ẹ má ṣé dìbò fún un
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02671
Ẹ má ṣe àṣìṣe láti dìbò yan àwọn apààyàn lọ́dún 2023 – Jonathan
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02672
Ijọba Buhari ti da Ọga yunifasiti Eko pada sipo  ẹ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02673
Ijọba apapọ ṣi ẹnubode mẹrin, o ni kawọn yooku ṣi wa ni titi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02674
Global Vaccine crisis: Ìgbẹ́kẹ̀lé nínú abẹ́rẹ́ àjẹsára ń di òkú l'ágbáyé!
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02675
Farmers-Herders Clash: Darandaran tó fẹ yìnbọn pa olókó rí ẹ̀wọ̀n gbéré he l‘Ekiti
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02676
MC Oluọmọ kilọ fawọn Ibo l’Ekoo: Tẹ o ba ti ni i dibo fun Sanwo-Olu, ẹ jokoo sile yin o
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02677
Wọ́n ti búrawọlé fún obìnrin méje tí wọ́n dìbò yàn gẹ́gẹ́ bíi gómìnà ní Kenya
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02678
Baba Ijesha: Lẹ́yìn tí a gbọ́ àwíjàre lẹ́nu Dele Matti tó jẹ́ olùdarí eré Ọkọ Iyabọ àti Yomi Fabiyi, a ríi pé wọ́n jẹ̀bi- TAMPAN
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02679
Nitori bi wọn ṣe fi kun owo ile awọn akẹkọọ, ẹgbẹ ajafẹtọọ binu sawọn alaṣẹ Fasiti Ibadan
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02680
Awọn ọlọpaa SARS le awọn ọmọ Yahoo pa l’Oṣogbo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02681
Ile-ẹjọ to ga ju lọ sun igbẹjọ lori nina Naira atijọ pẹlu tuntun si ọjọ kẹta, oṣu Kẹta
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02682
Ọba Akiolu bẹ orileede Gẹẹsi lati ran Naijiria lọwọ lori ipenija eto aabo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02683
O ma ṣe o, akẹkọọ Fasiti Ifẹ ro gbogbo ẹ pin, lo ba gbe majele jẹ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02684
Yahaya fẹẹ gbẹsan ija ti Kabiru ba a ja, lo ba gun un lọbẹ pa l’Ebute Mẹta
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02685
Buhari ti paṣẹ: Ẹnikẹni tẹ ẹ ba ti ri pẹlu ibọn AK-47, ẹ yinbọn pa a
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02686
Àwọn iléeṣẹ́ bàlúù ní Nàìjíríà yí ohùn padà lórí wíwọ́gié ìrìnnà òfúrufú nítórí owó epo bàlúù, wọ́n ní àwọn ti da ọ̀rọ̀ náà rò
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02687
Mò ń bọ̀ láìpẹ́ láti tú àṣìrí PDP, Atiku – Gomina Wike
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02688
Sunday Igboho: Ìgbẹ́jọ́ yóò wáyé láti mọ̀ bóyá wọ́n ó fa Igboho lé ìjọba Naijiria lọ́wọ́
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02689
Nitori eto aabo to mẹhẹ, ṣifu difẹnsi ṣi ẹka tuntun ni Kwara
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02690
Diego Maradona lọ̀! Ẹ jẹ́ ká gbafẹ́ pẹ̀lú àwọn àwòdamiẹnu àwòrán nípa ìgbé ayé rẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02691
Yẹmi Ọṣinbajo ti ni awọn akọsilẹ rere lati di aarẹ lọdun 2023-Ẹmia Ilọrin
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02692
Ìjọba ti ileẹ̀kọ́ pà lẹ́yìn tí àwọn jàndùkú ṣèkọlù sí Osogbo, ìpínlẹ̀ Osun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02693
EndSARS Protest: Àwọn olùwọ́de Endsars ló já sọ́ọ̀bù kìí ṣe torí ebi - Femi Adesina
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02694
Nkechi Blessing: Blessing ní ìkébé òun tóbí ju ohun tí òun lè dọwọ́ bò lọ, gbogbo èèyàn ló mọ̀
0
0
0
0
0
0
yor