id
stringlengths
23
24
text
stringlengths
3
4.68k
anger
float64
0
1
disgust
float64
0
1
fear
float64
0
1
joy
float64
0
1
sadness
float64
0
1
surprise
float64
0
1
language
stringclasses
28 values
yor_train_track_a_02695
Ọọni Ileefe rọ awọn ọdọ lati gba alaafia laaye
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02696
Lẹyin ọdun mẹẹẹdogun: Ọbasanjọ ati Gani Adams pari ija, nitori iṣọkan ilẹ Yoruba
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02697
Ọmọ Pasitọ Adeboye dara pọ mọ awọn ọdọ to n ṣewọde SARS
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02698
EndSARS, EndSWAT Protests: Òbí agbábọ́ọ̀lù Kazim Tiamiyu Kaka àtàwọn míì tí ọlọ́pàá pa sọ̀rọ̀, omijé bọ́ lójú
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02699
Lẹyin Adamu, Kyari di adele alaga APC
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02700
Ọmọ Yoruba atata ni ọ, Ọọni atawọn gomina kan saara si Yẹmi Ọṣinbajo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02701
Canada ń ṣọ̀fọ̀ lẹ́yìn tí wọ́n rí òkú akẹ́kọ̀ọ́ 215 nílé ẹ̀kọ́ kan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02702
Ikọja aaye, Ibrahim fọwọ fa ọyan iyaale ile kan, ladajọ ba ju u sẹwọn
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02703
Ohun tó fa rògbòdìyàn lẹ́yìn tí wọ́n yan Ọba tuntun ní Ikirun rèé
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02704
Awọn ọlọpaa ti ri mẹtala ninu awọn ẹlẹwọn to sa kuro l’Ọyọọ nipinlẹ Ọṣun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02705
Nigerian Labour Congress: Ewú ńbẹ! tí ìjọba ìpínlẹ̀ bá sàkóso gbèndéke owó oṣù òṣìṣẹ́,wọ́n ò ní san N30,000, N10,000 ní wọ́n má á san
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02706
Awọn ọrẹ mẹrin tan oni-POS lọ sile akọku, wọn gbowo ọwọ ẹ, wọn si dana sun un l’Ogun
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02707
Adajọ ni ki Tunde lọọ lo iyooku aye ẹ lẹwọn, ọmọ ọdun meje lo fipa ba lo pọ l’Oṣogbo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02708
Aadọta naira ni baba agbalagba yii fi tan ọmọ ọdun mẹsan-an to fipa ba lo pọ ni Kwara
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02709
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ tọkọ-taya àti ẹnìkan f̀́ẹsùn ìjínigbé àti ìpànìyàn nípìnlẹ̀ Ogun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02710
Eto ẹkọ wa lara ohun to jẹ mi logun ju lọ- Tinubu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02711
Tinubu ko ẹri rẹpẹtẹ siwaju ile-ẹjọ to n gbọ ẹsun idibo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02712
Plane crash in Abuja: Àwọn kan sọ pé ejò lọ́wọ́ nínú lórí ìjàmbá ọkọ̀ bàálù náà - Alàgbà Julius Olasunkanmi
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02713
Nigerians in Oman: Ààrẹ Buhari, ẹ̀yin gómìnà ìpínlẹ̀ Yorùbá, ẹ rántí wa ní Oman, àwọn ọmọ Nàìjíríà
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02714
Olatunji James alákàrà Ó ta lẹ́nu: Ìwọ tó o bá ń tijú, o ò le dé 'bi gíga
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02715
Sunday Igboho: Àwọn ọlọ́paàá dí agbègbè iléeṣẹ́ ìjọ́ba Benin Republic táwọn 'Yoruba nation' fẹ́ lọ ṣe iwọ́de fún ìtúsílẹ̀ Sunday Igboho
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02716
Owo tẹ ayederu dokita, ẹni to ṣiṣẹ abẹ fun lo ku
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02717
Boko Haram: Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ní òun fẹ́ lo ẹṣin àti Ọ̀kadà láti ṣọ́ ìlú Abuja
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02718
Kazeem Tiamiyu: Wọ́n ti sin òkú agbábọ́ọ̀lù Remo Stars tí wọ́n sọ pé SARS pa ní Sagamu
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02719
Nitori to gba igbakeji rẹ leti ni gbangba, ijọba fofin de alaga ajọ ere bọọlu Eko
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02720
Agba ofifo lasan lawọn gomina to ṣofin pe ki wọn yee fi maaluu jẹko ni gbangba-Akowe Miyetti Allah
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02721
Wahala n’Ikire: Awọn janduku kọlu Ọba Akire, wọn tun ja awọn oloye ẹ lole rẹpẹtẹ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02722
"""Babaláwo ní n kò ṣe lò làwọn tó fẹ́ fi mí ṣòògùn owó fi dá mi padà"""
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02723
Wọn ti rí òku Ooreoluwa, ọmọ tọkọtaya tí wọ́n dáná sún ni Abeokuta lọ́jọ́ ọdún, wo ohun tí ọlọ́pàá Ogun tún sọ...
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02724
Nitori alaisan to ku sọdọ wọn, awọn mọlẹbi lu oṣiṣẹ ọsibitu ijọba lalubami l’Akurẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02725
Adajọ ti ran Victor lẹwọn ọdun mẹta, jẹnẹretọ lo ji gbe l’Akurẹ
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_02726
Ọlọpaa pa Fulani ajinigbe meji, ọwọ tun tẹ mẹta ninu wọn l’Ekiti
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02727
Idajọ ile-ẹjọ to ga ju lọ ki i ṣe opin irin-ajo mi nidii oṣelu- Peter Obi
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02728
OAU VC: Mọ̀ nípa ìlànà tí wọ́n n gbà yan VC fasítì ní Naijiria
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02729
Bi wọn ba pa Igboho, itajẹsilẹ ati ogun ni wọn n kọwe si yẹn-Gani Adams
1
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02730
Àwọn obìnrin orílẹ̀-èdè Iran ti lè wo bọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá báyìí
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02731
O ma ṣe o, ibọn ba ẹṣọ so-safe kan nibi ti wọn ti lọọ koju ajinigbe, lo ba gbabẹ ku
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02732
Wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ ètò ìsìnkú Asẹ́yìn tí ìlú Iseyin Oba Abdulganiy Salawudeen Adekunle Oloogunebi tó wàjà
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02733
Lẹyin ọdun mọkanla ti ọba wọn ti waja, wọn yan Onirun t’Irun Akoko tuntun
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02734
Igboora: Wòlíì ni mí, ṣùgbọ́n àwọn ọ̀gá tó kọ́ mi níṣẹ́ òògùn owó ní kí n má dárúkọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02735
Sẹyin naa ti gbọ pe wọn ti gbe Bobrisky kuro ninu ọgba ẹwọn to wa
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02736
Ọga INEC  ni bilionu mejidinlogun lawọn yoo fi ṣeto idibo Kogi, Bayelsa ati Imo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02737
Ọpọlọpọ dukia ṣegbe lasiko ija Yoruba ati Hausa ninu ọja Lafẹnwa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02738
Aàrẹ, igbákejì aàrẹ àti aàrẹ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin kọ̀wé fipò sílẹ̀ lọ́jọ́ kan náà
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02739
Nitori aaye igbọkọsi, ọmọ lanlọọdu gun ayalegbe baba rẹ pa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02740
Maiduguri IDP camp Atrocities: Ọmọ ọdún 14 gún ara rẹ̀ pa lẹ́yìn tí okùnrin ẹni ọdún 35 fi ipá balòpọ̀
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02741
O ma ṣe o, lẹyin ọsẹ kẹta ti baale ile yii ṣegbeyawo lo ku
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02742
Ọpẹyẹmi tan ọrẹ ẹ lọ sinu igbo, lẹyin to pa a tan lo ji ọkada rẹ gbe lọ l’Ondo
0
1
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02743
A ti n mura lati yanju wahala awọn agbẹ ati Fulani ni Kwara- NSCDC
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02744
Temitọpẹ at’ọrẹ ẹ lọọ ji mọto gbe nipinlẹ Delta, Ekiti lọwọ ti tẹ wọn
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02745
OAU Aishat Adesina : Àwọn aláṣẹ fásitì OAU ṣí iléèwé náà padà lẹ́yìn ikú akẹ́kọ̀ọ́, Aishat Adesina tó fa ìfẹ̀hónúhàn
0
0
0
1
1
0
yor
yor_train_track_a_02746
Ṣẹyin naa ti gbọ: Ṣọun Ogbomọsọ tuntun ti wa nipebi, ọjọ meje ni yoo lo nibẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02747
Ọdun Ọlọjọ: Asiko ti to fun awa ọmọ ilẹ Afrika lati wa ni iṣọkan- Bonge
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02748
Igbimọ agba ẹgbẹ APC Eko fontẹ lu saa keji Sanwo-Olu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02749
Nitori ẹsun idigunjale ati ifipabanilopọ, adajọ ni ki wọn lọọ yẹgi fun Deji atọrẹ ẹ l’Ekiti
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02750
Timothy Adegoke: Ètò tí n lọ láti mú ọmọ Adedoyin tí ìròyìn sọ pé ó darí bí wọ́n ṣe sin òkú Timothy ní Hilton Hotel
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02751
Ogun miliọnu lawọn agbebọn to ji agbẹ mẹrin gbe n’Ifọn n beerewọn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02752
Tirela kọ lu bọọsi n’Ijẹbu-Ode, lo ba pa eeyan mẹrin lẹsẹkẹsẹ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02753
Insecurity in Nigeria: Soyinka ní Buhari kò le jókòó síle ìjọba láti dojú Boko Haram bolẹ̀
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02754
Ọṣinbajo lo daa ju ninu gbogbo awọn to fẹẹ dupo aarẹ lẹgbẹ APC – Babangida Aliyu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02755
Awọn agbebọn ṣa baale ile pa mọnu ile ọti n’Ibadan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02756
Ẹ̀nikan fi ọ̀rọ̀ ọkọ bú mi àmọ́, Ọlọ́run ṣe oore tó já ayé láyà – Olorì Ooni Tobiloba
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02757
Ko si atako ati ibanilorukọjẹ to le ni ki n ma dupo aarẹ- Tinubu
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02758
Lẹyin ti wọn gba owo nla, awọn ajinigbe tu akẹkọọ mẹrin ti wọn ji gbe l’Akoko silẹ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02759
IPOB: Abia ń gbóná jain lọ́wọ́, Kumiyi kò gbọdọ̀ wá ṣe ìpàdé gbàgede tó fẹ́ ṣe!
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02760
Eyi ga o! Ninu kootu lawọn ọlọpaa ti nawọ gan Ọmọlara to waa jẹrii gbe ẹgbọn ẹ n’llọrin
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02761
Ọpẹ o! Ajeji ti wọn ji gbe n’Ibadan ti bọ lọwọ awọn ajinigbe
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02762
Ọwọ́ tẹ olóyún, ìyálọ́mọ àtàwọn afurasí míì tó gbé òògùn olóró
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02763
Wo àwọn ọna tí o le gbà tó bá jẹ́ pé alábágbé ilé rẹ ń yọ ọ lẹnu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02764
Didier Drogba: Agbabọọlu to fí okiki dáwọ ìjà ogun abẹ́lé dúró n'ilẹ baba rẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02765
Baba atọmọ dero ẹwọn ni Kwara, oku olokuu ni wọn lọọ hu
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02766
‘Wọn de mi lọwọ lẹsẹ fun ọjọ meji gbako ninu ojo, mi o gbadura iru iriri bẹẹ f’ọtaa mi’
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02767
National grid collapse: Ìtàkùn àpapọ̀ iná mọ̀nàmọ́ná 'National grid'ní Nàìjíríà tún ti paná pi
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02768
Awọn oṣiṣẹ ti kootu pa nipinlẹ Ogun, nitori aabo owo oṣu tijọba n fun wọn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02769
Prepaid Meter: Ọmọ Nàíjíríà figbe ta pé owó iná táwọn ń san ju iná táwọn ń lò lọ
1
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02770
Prince Charles and Camilla royal visit: BBC gbàlejò orí adé ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, ka bí wọn ṣé kàn sáárá sí àwọn akọroyin
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02771
Ibadan Hoodlums Fracas: Ẹ̀mí OPC méjì bọ́, ọ̀kan wà ní ‘Coma’, wọn jó ọ̀pọ̀ dúkìá
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02772
Nigeria's Under-19: Ẹ wo bí Ikọ̀ Cricket Naijiria ṣé mí àgbáyé titi
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02773
NYSC: O lé wọ sòkòtò tó tobi, sùgbọn kò si àyè fún yẹ̀rì
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02774
Lassa Fever: Wo iye ibùdó ìtójú ibà Lassa tó wà ní Nàìjíríà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02775
Ẹnikẹni to ba n sọrọ to le mu ki awọn eeyan binu si Buhari yoo ri pipọn oju ijọba -Garba
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02776
Ọkùnrin tó pa ìyá rẹ̀ jẹ́wọ́ fún mọ̀lẹ́bí lẹ́yìn ọ̀sẹ̀ méjì
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02777
Akẹkọọ poli gbe majele jẹ, nitori tọrẹkunrin ẹ loun ko ṣe mọ
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_02778
Ijamba ina fọpọ dukia ṣofo ni oteẹli Ọọni Ifẹ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02779
Obinrin di ọga agba patapata ni yunifasiti LASU fungba akọkọ
0
0
0
1
0
1
yor
yor_train_track_a_02780
Ileeṣẹ ọlọpaa binu si ọkan ninu wọn to gbe baagi fun iyawo Atiku
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02781
Eyi ni idi ti mo fi da awọn kọmiṣanna mi silẹ-Makinde
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02782
Okeho Robbery: Ó tó 60 mílíọ̀nù tí àwọn olè jí ṣùgbọ́n a kò rí kọ́bọ̀ gbà padà- Òṣìṣẹ́ banki
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02783
Ijamba mọto fọpọ ẹmi ṣofo lojuna marosẹ Eko s’Ibadan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02784
Mo gbọdọ lo awọn iriri ti mo ti ni, oye mi, ati anfaani ti mo ni fun Naijiria ati ẹyin ọmọ Naijiria
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02785
Awọn ajinigbe gbe iyawo ọga-agba ileeṣẹ ijọba Ekiti tẹlẹ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02786
Coronavirus Ghana: Ààrẹ Nana Akufo-Addo ti wọ́lé ìyàsọ́tọ̀ ọlọ́jọ́ mẹ́rìnlá
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02787
Ọpẹyẹmi, ọmọ Alabi Pasuma, gbaṣẹ ologun l’Amẹrika, ṣinkin ninu Paso n dun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02788
Iṣọ-oru niyawo Sunday lọ, lọkọ ẹ ba fipa ba ọmọ ọlọmọ lo pọ ko too de
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02789
Poverty in Nigeria: SERAP ní aráàlú ló ń jẹ ìyà torí ìwà àjẹbánu ní ẹ̀ká ìlérá, ètò ẹ̀kọ́ àti ìpèsè omi
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02790
Sunday Igboho: Ẹ fún mi ní ₦500bn lórí dúkìá mi tẹ bàjẹ́ àti títẹ ẹ̀tọ́ mi lójú mọ́lẹ̀
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02791
Ọja ni Iya Abdulrahman ni ko lọọ gbe fun onibaara rẹ n’llọrin ti wọn fi pa a
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02792
Wo ọkùnrin tó ní ìpèníjà ara, tó tún ń jà fún ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02793
Ẹwọn ọdun meje ni adajọ ju ọlọpaa to yinbọn paayan l’Ekoo si
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02794
'Àwọn tó pa Bamise nínú BRT ba ojú ara àbúrò mi jẹ́ yánkan-yànkan'
0
0
0
0
1
0
yor