id
stringlengths
23
24
text
stringlengths
3
4.68k
anger
float64
0
1
disgust
float64
0
1
fear
float64
0
1
joy
float64
0
1
sadness
float64
0
1
surprise
float64
0
1
language
stringclasses
28 values
yor_train_track_a_02795
Ọpẹ o, Sanni Abacha ti tun fi miliọnu dọla rẹpẹtẹ ranṣẹ sawọn ọmọ Naijiria lat’ọrun
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02796
Ti mo ba di aarẹ, mi o ni i yan ẹnikẹni tọjọ ori ẹ ba ju marundinlogoji lọ sipo – Saraki
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02797
Bi Makinde ṣe sọ Kọlẹẹji Alayande di yunifasiti yoo gbe eto ọrọ aje ipinlẹ Ọyọ larugẹ- Ogundoyin
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02798
Awọn obi pe ọmọ wọn atiyawo ẹ lẹjọ, tori wọn o rọmọ bi lẹyin ọdun mẹfa igbeyawo wọn
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02799
Wo èèyàn mẹ́wàá tí ọlọ́pàá ta níbọn lọ́dún 2022
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02800
Awọn gomina ẹgbẹ PDP marun-un (G-5) wọle ipade l’Ekoo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02801
Iku n rọ dẹdẹ lori ọmọ Naijiria yii o, egboogi oloro lo gbe tọwọ ọlọpaa fi tẹ ẹ ni India tẹ ẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02802
Tori burẹdi ati omi ti Samson ji, adajọ sọ ọ sẹwọn ọdun mẹta
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02803
Man selling body parts, Ibadan: Ọwọ́ ikọ̀ Amọtẹkun ba Mutiu Abdul-Rasheed, afurasí tó ń ta ẹ̀yà ara èèyàn ní Ibadan
0
1
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02804
EndSARS Protest Update: Seun Kuti dá ẹgbẹ́ tí baba rẹ̀, Fela Kuti dá silẹ̀ ní ọdún 1979 padà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02805
World Cancer Day: Onímọ̀ sáyẹ́ńsì ní ká tètè ṣe àwárí àrùn jẹjẹrẹ ọyàn ni ọ̀nà àbájọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02806
Timi Osukoya: Ọ̀pọ̀ olórin ẹ̀mí ló ń kọrin torí owó tàbí afẹ ayé
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02807
EFCC arrests Juju priest: EFCC fi ṣìkún òfin mú Oníṣegùn tó lu aláìsàn ní jìbìtì
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02808
Igangan attacks: Gani Adams ní ó tó ọjọ́ mẹ́ta tí OPC ti ń pariwo pé àwọn agbébọn kan ńgbèrò àti kọlu Ibarapa, àwọn agbófinro kò dáhùn ni
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02809
Sunday Igboho: Agbẹjọ́rò kéde ọjọ́ tó ṣeéṣe káwọn afurasí tí DSS kó, kúrò lọ́gbà ẹ̀wọ̀n
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02810
Queen Elizabeth II: Wo ǹkan míì tí àwọn eèyàn ń sọ̀ nípa ìgbé ayé Obabìnrin ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02811
Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá pọkún ètò ààbò ní òpópónà márosẹ̀ Èkó sí Ìbàdàn nítorí ìjínigbé
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02812
Wọn paayan meji, wọn ṣe ọpọ agbofinro leṣe ninu ija Fúlàní ati Yorùbá ni ipinlẹ Ọyọ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02813
Sex Abuse: Lóòótọ́ ní àṣìṣe wáyé nípa bá ṣè kojú ìṣẹlẹ ifipabọmọdé l'òpọ̀ - Póópù
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02814
Oluwo ṣọtun sosi, ko ba ibi kan jẹ, eyi lawọn orukọ to sọ ọmọ rẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02815
Eyi lọrọ ti Aarẹ Tinubu sọ lori idajọ ile-ẹjọ to ga ju lọ loni-in
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02816
Ohun tí à ń fẹ́ kí ìjọba ṣe rèé – Àwọn tó farapa lásìkò ìwọ́de EndSARS
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02817
Pastor Adeboye ṣáájú ìwọ́de àdúrà lòdí sí ìpànìyàn ní Nàìjíríà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02818
Indian girl killed: Bí àwọn ẹbí ọmọdébìnrin yìí ṣe nàá títí tó fi gbé ẹ̀mí mì
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02819
Iyawo mi lọọ fi iwe ile ti mo kọ yawo lai sọ fun mi, mi o fẹ ẹ mọ-Bọboye
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02820
Cure for coronavirus: Ìjọba ti sún wa kan ògiri ló jẹ́ kí a daṣẹ́ sílẹ̀ - ẹgbẹ́ àwọn dókítà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02821
Awọn akẹkọọ poli yii naa n ṣowo egboogi oloro
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02822
Lẹyin ọdun mọkanla ninu okunkun, Adeleke tun ẹrọ amunawa ṣe fawọn eeyan Obokun
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02823
Ẹ wo Adeolu to n faṣọ Sifu Difẹnsi jale l’Ayetoro
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02824
Ooni: EFCC, ẹ se àtúnse sí ìgbé ayé àwọn ọdaràn tẹ bá mú
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02825
Amọtẹkun bẹrẹ idanilẹkọọ fawọn oṣiṣẹ tuntun l’Ondo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02826
Iyawo Ọmọọba Harry kọ lẹta si Oluwoo o, eyi lohun to wa nibẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02827
Ibi ti Alaaji ti to fun epo bẹntiroolu lo ti ku sinu mọtọ ẹ nileepo kan n’Ibadan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02828
Timothy Adegoke: Kò pẹ́ táa bẹ̀rẹ̀ ẹ̀jọ́ lórí ikú àbúrò mi ni Adedoyin tó ni hòtẹ́ẹ̀lì rán lawyer kó gbé owó wá - Ẹ̀gbọ́n Timothy
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02829
Èèyàn mẹ́rin farapa yánayàna níbi òde orin Asake nílùú London.
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02830
Awọn oluranlọwọ igbakeji gomina Kwara ti ko arun Korona
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02831
Makinde ṣabẹwo si Olunlọyọ, o fun un ni mọto olowo nla
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02832
Sanwo-Olu ni yoo ṣaaju ipolongo ibo Akeredolu l’Ondo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02833
Olori Alaafin Ọyọ ṣọjọọbi, o tun ṣile olowo nla
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02834
Ijọba Ọṣun yoo bẹrẹ si i san owo-oṣu oṣiṣẹ to kere ju tuntun laipẹ – Adeleke
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02835
Ọta ilọsiwaju lawọn ti wọn maa n ba dukia ijọba jẹ lasiko rogbodiyan – Arẹgbẹṣọla
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02836
O n rugboo bọ o! awọn Fulani darandaran doju ija kọ awọn Amọtẹkun l’Ọṣun
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02837
Oyebade Adebimpe: Kò ṣeéṣe kí n lóyún, kí n sì gbe pamọ́ lọ́jọ́ orí mi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02838
Lati le gba kaadi idibo, Akeredolu kede isinmi ọjọ kan fawọn oṣiṣẹ ipinlẹ Ondo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02839
#justiceforDonDavis: Orí ayélujára n gbóná janjan fún ariwo ìdájọ́ fún akẹ́kọ̀ọ́ kan níléèwé Kumuyi
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02840
Yoruba Nation rally: ''Ìwọ́de Yorùbá Nation kò ní wáyé mọ́ nílùú Igboho torí a kò fẹ́ wàhálà''
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02841
Dẹrẹba ọkọ ero dana sun oṣiṣẹ ajọ to n dari ọkọ, eyi lohun to fa a
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02842
Laarin oṣu meji, Ọọni Ogunwusi ṣe mọmi-n-mọ-ọ fun olori mẹrin
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02843
Awọn ọdẹ ibilẹ pa ọkan lara awọn ajinigbe to n daamu wọn Itapaji-Ekiti
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02844
Ọrọ baba atọmọ lọrọ emi ati Ọọni Ifẹ, mo ti pe wọn lori foonu-Sunday Igboho
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02845
Awọn mẹrin ku ninu ijamba ọkọ l’Ọrẹ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02846
Wọn ti gbaṣọ lọrun ọlọpaa yii o, o lọọ fipa gbowo lakaunti ẹni to fẹsun kan
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02847
Jurgen Klopp: Akọ́nimọ̀ọ́gbá Liverpool tọwọ́ bọ̀wé àdéhùn tuntun tí yóò múu wà nípò di ọdún 2026
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02848
Governors 100 days: Gbadamosi ní àwọn ojú ọ̀nà Eko ń bàjẹ́ si lásìkò Sanwo-Olu
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02849
Wo àtúnṣe òpópónà tíjọba fẹ́ ná ₦248bn lé lórí lọ́dún 2023
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02850
Sunday Igboho: Ọlọrun to ja fun Yoruba laye Abacha yoo ja fun wa lasiko yii-Kọle Ọmọlolu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02851
Buhari ti gbìyànjú lórí ètò aàbò, ó ti gé ìyẹ́ apa ISWAP ṣùgbọ́n má a gbìyànjú síi- Bola Tinubu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02852
APC Aspirants Screening: Wo ọjọ́ tí ìgbìmọ̀ àyẹwò yóò bẹ̀rẹ̀ iṣẹ lórí àwọn olùdíje tí wọn fí fọ́ọ̀mù ṣọ̀wọ̀ fun ipò labẹ àsìá APC
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02853
Wọn fẹẹ lu Taju pa n’Ibadan, iyawo ẹ lo purọ ole mọ ọn
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02854
Nítòótọ́ ni à máa ṣe 'Stop and Search' sùgbọ́n à kò gbé agbègbè kankan tìpa ni Eko rárá- Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Eko
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02855
Nigeria insecurity: David Jemibewon faraya lórí báwọn jàǹdùkú ṣe ń borí ọmọogun Nàíjíríà
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02856
Tinubu 2023 Presidency: Ẹ kà nípa òhun tí ẹgbẹ́ ọmọ Igbo sọ lórí èròngbà Tinubu láti du ipò ààrẹ Nàìjíríà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02857
Eto ikaniyan yoo mu igba ọtun wọ ilẹ Naijiria – Hundeyin
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02858
Èèyàn mẹ́tàdínlógún farapa lẹ́yìn ìṣẹ̀lẹ̀ ilẹ̀ rírì ní Croatia
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02859
Akẹ́kọ̀ọ́jáde LAUTECH dá ìwé ẹ̀rí padà, ó fẹ́ kíléẹ̀kọ́ dá gbogbo owó ẹ̀kọ́ tó san padà
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02860
Iyawo Tinubu gba awọn ọmọ Naijiria nimọran: Ẹ yaa pada sidii iṣẹ agbẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02861
Ọjọ kejidinlogun, oṣu yii, lawọn ileewe alakọọbẹrẹ ati girama yoo wọle l’Ekoo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02862
Sunday Igboho: Gbẹ̀fẹ́ ní àkókò tí mo lò lọ́gbà ẹ̀wọ̀n, àìsúnmọ́ aya mi nìkan ní ìyàtọ̀ pé ń kò sí nílé
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02863
Ayẹwo ti fihan pe ọmọ mi gan mọna nileewe Chrisland ni o-Adeniran
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02864
Russia Boxer: Abẹ̀ṣẹ́kùbíòjò dágbére fáyé lásìkó ìjà rẹ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02865
Tunde Kelani ṣafihan fiimu itan igbesi aye Ayinla Ọmọwura
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02866
Ogun Cult Clash: Ìjọba fajúro sí ìkọlù àwọn ọmọ ẹgbẹ́ òkùnkùn
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02867
Ọpẹ o, ara Kollington Ayinla ti ya, eyi lọrọ to sọ lọsibitu to wa
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02868
Wọn fa aworan ti wọn fi ki Aregbeṣọla ku oriire ọjọọbi ya l’Oṣogbo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02869
Awọn agbebọn ji olori adugbo atawọn mẹta mi-in gbe l’Ọwọ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02870
Awọn to n gba Buhari nimọran lo n ṣi i lọna- Lawan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02871
Pasitọ to n ba ọmọ ọdun mẹta ṣerekere ninu ṣọọṣi ti dero Kirikiri, l’Ekoo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02872
Dele Momodu: Mo ni gbogbo àmúyẹ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní 2023
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02873
Agbara mi ko gbe wahala ipo aarẹ daadaa mọ, mo n rọju ni- Buhari
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02874
Oyetọla gbe aba eto-iṣuna ọdun 2021 lọ fawọn aṣofin l’Ọṣun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02875
Adejare Adeboye: Olúwa yóò dá gbogbo ohun ta sọnù ní 2020 padà ní ilọ́po méje fún wa
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02876
Wọ́n lù mí, kódà wọ́n ya aṣọ mọ́ mi lọ́rùn ní Alaba- Lawal Waheed
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02877
Maaluu ti Ojo yoo fi ṣegbeyawo lo fẹẹ lọọ ra ti wọn fi pa a, ti wọn si ge ẹya ara rẹ lọ ni Kwara
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02878
ALGON Oyo: Aleshinloye ní ìdájọ́ ilé ẹjọ́ tó ga jùlọ làwọn ń tẹ̀lé, kò sì yẹ kó fa ìjà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02879
Bi ẹnikẹni ba kọlu yin, ẹyin naa ẹ kọlu wọn – Ọga ọlọpaa patapata
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02880
Mọto sọ ijanu rẹ nu, lo ba ṣeku pa tẹgbọn-taburo ni Kwara
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02881
Eyi ni bi owo Ọtẹdọla ṣe ran aṣofin ilẹ wa kan lewọn ọdun meje
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02882
Awọn janduku ya wọ teṣan ọlọpaa n’Ibadan, wọn yinbọn pa kọburu kan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02883
T.B Joshua: ...Àwọn ọmọ ẹ̀yin ń sọ̀fọ̀, ìdá mẹ́ta àǹgẹ́lì Olorun dójútí Lucifa tó lọ- Pasito Chris Okotie
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02884
To ba n lọ bo ṣe n lọ yii, awọn agbebọn maa fẹyin Naijiria balẹ laipẹ – Gomina Ortom
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02885
Ohun tí àwọn èèyàn ń sọ rèé lẹ́yìn tí adari àwọn agbésùnmọ́mí Zamfara, Bello Turji ní òun ti ronúpìwàdà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02886
Lẹyin ti baale ile yii pa iyawo ẹ tan loun naa gbe majele jẹ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02887
Dino Melaye, olùdíje sípò kẹẹ̀ta lábẹ́ àsìá PDP tó gba fọ́ọ̀mù ipò Gómìnà Kogi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02888
Ọmọ Ajimọbi naa fẹẹ dupo aṣofin ipinlẹ Ọyọ
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02889
Iru Aarẹ ti ko gba gbẹrẹ bii Buhari yii lo daa fun Naijiria – Fẹmi Adeṣina
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02890
Woman pushing police inspector: Obìnrin kan tó ti Ọ̀gá Ọlọ́pàá lulẹ̀ dèrò ilé ẹjọ́ Badagry
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02891
Ìgbìmọ̀ tó gbọ́ awuyewuye ìbò ààrẹ ní Kenya bẹ̀rẹ̀ ìjọ́kòó
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02892
A o ti i yan Gbadegẹṣin sipo Alaafin o- Ọyọmesi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02893
O ma ṣe o, ijamba ọkada gbẹmi ọkunrin kan lọna Ikirun si Oṣogbo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02894
Nítorí owú jíjẹ, ọkọ Zarka gé imú aya rẹ̀ dànú!
0
1
0
0
1
0
yor