id
stringlengths 23
24
| text
stringlengths 3
4.68k
| anger
float64 0
1
| disgust
float64 0
1
⌀ | fear
float64 0
1
| joy
float64 0
1
| sadness
float64 0
1
| surprise
float64 0
1
⌀ | language
stringclasses 28
values |
---|---|---|---|---|---|---|---|---|
yor_train_track_a_02495 | Ọpẹ o! Awọn akẹkọọ Fasiti Kogi ti wọn ji gbe ti gba itusilẹ | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02496 | O ma ṣe o, ijamba ọkọ gbẹmi eeyan mọkandinlogun ni Kwara | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02497 | Opebi aircraft crash: Ìgbìmọ̀ olùwádìí ni epo ló tán nínú bàálù tó já l'Eko | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | yor |
yor_train_track_a_02498 | “Mo ṣetán láti fi ọ̀kan nínú kíndìnrín mi sílẹ̀ fún ọmọ Ekweremadu” | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02499 | Ibadan killing, Linus Onwuamana: Àwọn jàndùkú agbébọn yìnbọn pa ọkùnrin oníṣòwò kan nílùú Ibadan | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02500 | Paul Sodje: Ọjọ́rùú ló yẹ kó pé ẹni ọdun 55, amọ́ tó kú ikú àìròtẹ́lẹ̀ | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02501 | Ọwọ tẹ Ọlamide atawọn ọrẹ ẹ, oni POS ni wọn lu ni jibiti n’llọrin | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02502 | Sanwoolu p’ohun da lori ọjọ mẹrinla to fun awọn Hausa to wa ni Alaba-Rago, o ni ki wọn maa ba iṣẹ wọn lọ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02503 | Oyo APC Crisis: Wàhálà awuyewuye ẹgbẹ́ òṣèlú APC gba ọnà míì yọ pẹlú ìyànsípò alága igun ìkejì | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02504 | Nitori ẹsun jibiti ori ẹrọ ayelujara, ọmọ ‘Yahoo’ mọkandinlọgbọn ko sọwọ EFCC l’Ọffa | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02505 | Ondo Gunmen attack: Èèyàn máàrún lo kàgbákò ikú òjijì | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02506 | Igbẹjọ Timothy Adegoke: Adedoyin ṣepe fawọn oniroyin ni kootu | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02507 | Europe Returnee: Fatmata ní oṣù mẹ́fà ni wọn fi bá òun ṣùn ní aṣálẹ̀ Sahara | 0 | 1 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02508 | Isinmi ranpẹ ni ẹgbẹ APC lọ l’Ọṣun, ọdun 2026 ni opin PDP | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02509 | Kwam 1 dá àwọn tó ń wọ́ ọ tuurutu nílẹ̀ pé ó jẹ́ gbèsè dollar iṣẹ́ orin kan l'Amẹ́rika | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02510 | Baba Ijesha: Ta ló yọ ojú òpó 'GoFundMe' tí wọ́n ṣí fún afurasí Olanrewaju Omiyinka kúrò lórí ayélujára? | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02511 | Osun 2022 APC primaries: Mi ò ní ìkùnsínú sí àwọn tó bá mi du àṣíá ìdíje gómìnà ní APC- Oyetola | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02512 | Alaafin Adeyemi: Lára àwọn òrékelẹ́wà ayaba náà ló dẹnu ìfẹ́ kọ Ọba Adeyemi fúnra wọn kí Kabiesi tó wàjà | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02513 | ‘Awọn alawo ti wọn fẹhonu han ni Fasiti Ifẹ ki i ṣe ara wa o’ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02514 | Ija pari, Arẹgbẹsọla ki Adegboyega ku oriire ọdun meji nipo gomina l’Ọsun | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02515 | ‘Awọn pasitọ kan l’Abuja ni wọn ṣatilẹyin fun Tinubu o, ki i ṣe CAN’ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02516 | Ọpẹ o, Gomina Akeredolu ti pada de lati ilu oyinbo to ti lọọ gba itọju | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02517 | Eyi ni ohun ti Ọba Ọgọmbọ sọ nipa bi Aṣiwaju Tinubu ṣe jawe olubori | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02518 | Gomina Abdurazaq bura fawọn kọmisanna tuntun ni Kwara | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02519 | Makinde ti banki, otẹẹli atawọn to jẹ ijọba ni gbese pa n’Ibadan | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02520 | Mamman Daura kò rìn ìrìnàjò sí ìbi kánkan,ko ko ko lara le! - Bashir Ahmad | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02521 | Khadija fi majele sinu ounjẹ awọn ọmọ iyaale ẹ, mẹta lo ku ninu wọn | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02522 | Ọmọ ẹgbẹ́ márùn ún lọ́dún mẹ́rin, Kí ló ń fa ikú ọ̀wọọ̀wọ́ lẹ́yìn Davido? | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | yor |
yor_train_track_a_02523 | Latifat Tijani: Ìjọba Naijiria ń ṣèlérí láti mọ́ rírì mi àmọ́ láti 2016, pàbó ló ń já sí | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02524 | Ọwọ tẹ meji ninu awọn to sun ọlọpaa jẹ lasiko SARS n’Ibadan | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02525 | Olukọ to ba tun ran akẹkọọ niṣẹ ti ko tọna l’Ondo yoo ri pipọn oju ijọba | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02526 | Pneumonia: Dókítà ní kòkòrò àìfojúrí ló ń fàá òtútù àyà | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02527 | Kí ló dé táwọn èèyàn kan fi ń ro ikú ro Kemi Afolabi? | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02528 | Ọlọ́pàá ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ti sanwó ìtaràn £2500 fún oníwàásù ọmọ Nàìjíríà tí wọn mú lọnà àìtọ́ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02529 | A fẹ́ àlàyé lórí owó Abacha tẹ fẹ́ gbà lọ́wọ́ Amẹ́ríkà - SERAP | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02530 | Lati din ọwọngogo ounjẹ ku, eyi lohun ti Tinubu paṣẹ pe ki wọn ṣe kiakia | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02531 | Tinubu lẹtọọ daadaa lati di aarẹ, ṣugbọn… Ọṣọba | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02532 | Adiẹ ti jẹ’fun ara wọn o: Umar pa Fulani ẹgbẹ ẹ l’Akoko, o lo n gbero lati ji oun gbe | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | yor |
yor_train_track_a_02533 | Chidinma ṣe pati daran, wọn sọ ọ sẹwọn ọdun meji tori bẹntiroolu to ha fawọn alejo ẹ | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02534 | Adajọ ju akọwe kootu to lu jibiti sẹwọn ọdun meje n’Ilọrin | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02535 | Sunday Igboho: Agbẹjórò ní kò sí ohun tó jọọ́ pé orílẹ́èdè Benin ń gbèrò láti dá Sunday Igboho padà sílé | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02536 | Eeyan mẹtadinlogun ti gba fọọmu lati dije dupo aarẹ ninu ẹgbẹ APC | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02537 | Nkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa Olaniyi Ben Agboola, olúdíje ẹgbẹ́ PRP nínú ìdìbò gómìnà ipinlẹ Ekiti | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02538 | Ika buruku ni oludasilẹ ileewe yii o, ohun to ṣe fọmọ ọdun mẹrin yii ko ṣee sọ sita! | 0 | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02539 | Makinde: Ẹgbẹ́ òṣèlú PDP ní àwọn kò padà lẹ́yìn Seyi Makinde, gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02540 | Ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ni ẹgbẹ PDP yoo yan oludije funpo gomina wọn l’Ọṣun | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02541 | Atiku gba ijọba nimọran: Lati dena itankalẹ Korona, ẹ fofin de awọn ọkọ ofurufu lati ilẹ Gẹẹsi | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02542 | Ẹ fọkan balẹ, ko si nnkan kan to maa ṣe esi ayẹwo oku Mohbad- Ọlọpaa | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02543 | N’Ijẹbu-Ode, lanlọọdu fibinu so ọmọ tẹnanti mọlẹ, lo ba na wọn bii ẹran | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02544 | Insecurity in Nigeria: Àwọn gómìnà ẹkùn Gúúsù fòfin de dída màálù ní gbangba | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02545 | Nitori ki n le baa fun ọkọ mi lọmu mu ni mo ṣe fẹẹ bimọ kẹrin | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02546 | Twitter Ban: $1.5bn ni Nàíjíríà sọnù torí bó ṣe ti ojú òpó ayélujára pa | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02547 | Oṣiṣẹ ileewosan alabọọde ko Korona ni Meiran, nijọba ba ti ibẹ pa | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02548 | Awọn ẹṣọ alaabo fibọn fọ ẹsẹ Raheem to n lọ jẹẹjẹ ẹ l’Ado-Awaye | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02549 | Ọ̀kan nínú àwọn ọmọ mẹ́rin tó fi Rofia ṣòògùn owó ti sùnlọ níbi tí wọ́n ti n jó orí rẹ- Olóri fijilante Abeokuta | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 1 | yor |
yor_train_track_a_02550 | Kalashnikov AK-47: Ohun mẹ́fà tó yẹ kí o mọ̀ nípa ìbọn AK-47 rèé | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02551 | Olowo Eko, Ọba Rilwan Akiolu, ti pada saafin ẹ l’Ekoo | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02552 | Missing Alpha Jet: Ayédèrú fídíò ni Boko Haram fi léde lórí ọkọ̀ òfúrufú ọmọgun Alpha Jet tó pòórá -NAF | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02553 | O ma waa ga o, agbebọn mura bii ẹlẹhaa, lo ba pa ọga ọlọpaa meji danu | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 1 | yor |
yor_train_track_a_02554 | Baba Suwe: Aya àkọ́fẹ́ olóògbé ṣàlàyé bí àkókó ìkẹyìn ọkọ́ rẹ̀ ṣe rí | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02555 | Sẹnetọ Balogun, aburo Olubadan, fẹẹ dara pọ mọ ẹgbẹ APC | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02556 | Ta ló pa ọmọ ẹgbẹ́ PDP l‘Oyo èyì tó fẹ́ fa wàhálà sílẹ̀ láàrin PDP àti APC? | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02557 | Fuel Scarity in Nigeria: NNPC kó èpo tuntun wọ Nàìjíríà, o kéde bí epo àdàlù bẹntiró ṣe wọ Nàìjíríà | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02558 | School Kidnap in Nigeria: Wo iye ìgbà tí wọ́n ti jí akẹ́kọ̀ọ́ gbé ní Nàìjíiríà | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02559 | Sunday Igboho: Ẹgbẹ́ Afenifere fèsì sí ẹ̀sùn pé wọ́n fi Igboho wé Ànọ́bì Muhammed (S.A.W) | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02560 | Herbal Doctor: Iléẹṣẹ́ ọlọ́pàá Eko tú àṣírí agbẹ̀bí alágbo tó ṣekú pa obìnrin kan | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02561 | Ron Jeremy: Òṣèré tó ti ṣe ''Blue film'' fún ọdún 40 ti wọ gàù pẹ̀lú ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀ | 0 | 1 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02562 | Àwọn tó sọ pé kò sí owó ní Nàìjíríà àfi ká yáwó ń pa irọ́ fáráàlú ni – Kwankwaso | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02563 | Kazeem Alli: Àwọn tọ jí alága NURTW Osun gbé ti bèèrè 15 mílíọ̀nù owó ìtúsílẹ̀ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02564 | Sowore: Àjọ DSS tọrọ àforíjìn lórí ìwà ti wọ́n hù nílé ẹjọ- Femi Falana | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02565 | Mother allegedly set daughter ablaze in Ogun: Ó gbẹnután! Ìyá da bẹntiró sí ará ọmọ ọdún mẹ́wàá tó sì dáná sun ún | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02566 | Ondo Doctors strike: Àwọn aláìsàn ń padà lọ sílé lẹ́yìn tí àwọn Dókítà bẹ̀rẹ̀ ìyànṣẹ́lódì ní Ondo | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02567 | Wọn fi oye Ọmowe da Sunday Igboho lola ni yunifasiti Amẹrika | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02568 | Awọn janduku kọ lu oloye ẹgbẹ APC meji nibi ipade kan ni Lafiagi | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02569 | Black lives Matter: Yomi Faparusi sọ ìrírí rẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ọlọ́pàá nílẹ̀ Amerika | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02570 | Wọn le olukọ-agba ti ko wa sileewe lọjọ Isinmi kuro lẹnu iṣẹ lEkiti | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02571 | Waste to Wealth: Ẹ̀gbin tìrẹ ni èròjà táwọn èèyàn míràn fi n ṣiṣẹ́ ajé, okoòwò ńlá ni | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02572 | Ọọni yan Toyin Kọlade ni Iyalaje Oodua | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02573 | Osun APC Primary: Àwọn jàndùkú da ìdìbò rú ní Ede àti Osogbo, wọ́n ṣá èèyàn ládàá - Adelani Baderinwa | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02574 | Osun bank robbery: Ọlọ́pàá ní àwọn olè jí N600,000 nínú ATM l'Osun, àmọ́ àwọn ọlọ́pàá ti lé wọn wọ inú igbó | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02575 | O tan! Ayu n lọ bi a ti kọwe rẹ lẹgbẹ PDP | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02576 | Tori MC Oluọmọ ati Portable, awọn eeyan fẹsun ṣiṣe ojuṣaaju kan ileeṣẹ ọlọpaa | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02577 | Ibrahim Mantu ti dágbére fáyé lẹ́yìn àìsàn ọjọ́ mẹ́wàá | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02578 | Tinubu ko lẹtọọ lati dupo aarẹ, tori olokoowo egboogi oloro ni – Peter Obi | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02579 | Bethel Baptist kidnap: Àwọn ajínigbé tú 28 nínú akẹ́kọ̀ọ́ 121 Bethel Baptist tí wọ́n jígbé sílẹ̀ | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02580 | Ikare Monarch: Ọdún méjìdínláàdọ́ta ní Oba Adegbite-Adedoyin ló lókè èèpẹ̀, kó tó mí kanlẹ̀ | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02581 | Wo àwọn nkan tí o kò fi ojú sí àmọ́ tó n fa àìrọ́mọbí fún ọ̀kunrin | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | yor |
yor_train_track_a_02582 | Ọkan pataki lara iran to le ba wa gbogun ti wahala eto aabo lorileede yii ni awọn Fulani-Oluwoo | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02583 | Ijọba Ogun bẹrẹ abẹrẹ ajẹsara to n dena arun digbolugi lara aja | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02584 | Ẹ lẹtọọ labẹ ofin lati ṣewọde ita gbangba, ṣugbọn ẹ ma fi ba dukia ijọba jẹ-Ijọba Eko | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02585 | SW Security: Ìpàdé ààbò wáyé nílẹ̀ Yorùbá, wọ́n fẹnu ọ̀rọ̀ jóná pẹ̀lú ilééṣẹ́ ọlọ́pàá | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02586 | Lagos missing children: Ọ̀kan lára ìyá àwọn ọmọ tó sọnù náà ti ń sínwín | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02587 | Afurasí ọkùnrin tó pa obìnrin ẹni ọdún 71, tó tún ta ọrùn ọwọ́ àti ẹsẹ̀ rẹ ní ìpínlẹ̀ Ogun bọ́ sọ́wọ́ Ọlọ́pàá | 0 | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02588 | "Tope Alabi: Ẹni tó kọ orin ""Oniduro Mi E se o"" fèsì" | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02589 | Ẹ dákun, ẹ yé bímọ 100 láàrin oṣù kan - Ààrẹ Tanzania rawọ́ ẹ̀bẹ̀ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02590 | Ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún dèrò àtìmọ́lé lẹ́yìn tó bú gómìnà ìpínlẹ̀ Yobe lórí ayélujára | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02591 | Portable Zazzu: Àlàyé rèé lórí ìdí tí wọn ṣe já mi sí ìhòòhò, wọn ní mo gbe kẹ̀kẹ́ Maruwa | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02592 | Ayẹyẹ ọdún Sango lẹ̀yìn ìpapòdà Alaafin Lamidi Adeyemi III wáyé, ohun tó ṣẹlẹ̀ níbẹ̀ rèé | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02593 | Dejo Tunfulu: Àwọn òṣèré tíátà bẹ̀rẹ̀ kíkọ́ ilé sórí ilẹ̀ gbajúgbajà adẹ́rìnínpòṣónú tó papò dà | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_02594 | Oyo PDP: Olórí ọ̀dọ́ farapa ni, ẹni tó wa ọ̀kọ́ ló kú | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.