id
stringlengths
23
24
text
stringlengths
3
4.68k
anger
float64
0
1
disgust
float64
0
1
fear
float64
0
1
joy
float64
0
1
sadness
float64
0
1
surprise
float64
0
1
language
stringclasses
28 values
yor_train_track_a_02295
A maa bẹrẹ si i san afikun owo-oṣu ninu oṣu kọkanla- Dapọ Abiọdun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02296
Ọlọpaa mẹrin wọ gau ni Kwara, agunbanirọ ni wọn fipa gbowo lọwọ ẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02297
Elon Musk jábọ́ kúrò nípò ẹni tó lówó jù lágbáàyé; Wo olówó tuntun tí Forbes kéde
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02298
Doctors strike: Awọn Dokita 'NARD' da iṣẹ silẹ lati bere ẹtọ wọn lọwọ ijọba
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02299
Awọn Ọmọọba binu si lemọọmu agba Ogbomọṣọ, wọn lo ṣe ohun tẹnikan ko ṣe ri
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02300
African Idols: Kí ló lè mú kí àlùfáà ìjọ Aguda máa kó ère ìṣẹ̀nbáyé pamọ́?
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02301
Aisha Buhari: Ọ̀pọ̀ aráàlú ní Aisha ti pariwo ṣáájú pé Buhari kọ ló ń darí ìjọba
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02302
Bobrisky: Ẹ má ṣe ìdájọ́ mi, mo ṣún mọ́ Ọ́lọ́run, máà sì lọ sí Mecca láìpẹ́
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02303
Onifayawọ yinbọn pa aṣọbode lẹnu iṣẹ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02304
2023: Tinubu jafafa, o si ni iriri lati gbe orileede yii goke agba – Oyetọla
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02305
Hausa ti lanlọọdu gba sile gun un pa nitori ọrọ ti ko to nnkan n’Ibadan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02306
O ma se o, awọn agbebọn yinbọn pa Dokita, wọn tun ji ọmọ ẹ obinrin gbe lọ ni Kwara
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02307
CBN paṣẹ: Ẹ maa na gbogbo owo atijọ ati tuntun lọ titi dipari ọdun yii
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02308
Atunto nikan lo le yanju ọrọ ẹlẹyamẹya ni Naijiria-Akeredolu
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02309
Ko si orileede to le dagbasoke lai si atilẹyin awọn eeyan inu rẹ – Arẹgbẹṣọla
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02310
Rúkèrúdò ẹgbẹ́ òṣèlú PDP l‘Osun tún búrẹ́kẹ́ si
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02311
Adewole Adebayo, Olùdíje sípò Aàrẹ lẹ́gbẹ́ SDP: Mo faramọ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ láti mójútó aàbò Nàìjíríà lásìkò yìí
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02312
Rumuekpe Port Harcout explosion: Èèyàn 25 jóná níbi ọ̀pá epo tó fọ́
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02313
Ileegbimọ aṣofin Ogun fẹ ki ofin ma-fẹran-jẹko ni gbangba bẹrẹ kia
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02314
Ala ti ko le ṣẹ ni ki n dara pọ mọ ẹgbẹ APC – Makinde
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02315
Ọjọ keji ti wọn ti n wa Dele, oku ẹ ni wọn ri l’Ekoo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02316
Elisha yii yoo pẹ ni Kirikiri o, ọmọkunrin ti ko ju ọdun mẹsan-an lọ lo fipa ba lo pọ
1
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02317
"Coronavirus Update in Nigeria: 'Ẹ sọ́ra fún ""Christmas Carol"", ẹ̀yin tẹ́ẹ sì wà lókè òkun ẹ má wálé o!'"
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02318
Ọmọ ọdún mẹ́sàn-án tó n gbé àṣà Yorùbá lárugẹ́ sọ nkan tó jẹ́ ìwúrí fún tó fi n ṣe bẹ̀ẹ́
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02319
Ọwọ ọlọpaa atawọn ọlọdẹ tẹ ikọ adigunjale ti wọn jẹ obinrin l’Oṣogbo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02320
Kókó ìròyìn t'òní: Awuyewuye Dino Melaye, iléeṣẹ́ ológun lórí ìkọlù Màìdúgùri
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02321
Nitori awọn agbẹ onirẹsi mẹtalelogoji tawọn Boko Haram bẹ lori ni Borno, PDP sọko ọrọ si Buhari
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02322
Eefin jẹnẹretọ pa baale ile kan l’Ogun, iyawo rẹ wa lẹsẹ-kan-aye ẹsẹ-kan-ọrun lọsibitu
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02323
Ọwọ ti tẹ ọkan ninu awọn ajinigbe to yinbọn pa awakọ l’Akunnu Akoko
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02324
Oluwo: Mo fẹ́ kí gbogbo ọmọ Nàíjíríà gbà mí lórí ìyà tí Oluwo fi jẹ mi, ni mó ṣe pe ẹjọ́
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02325
Christmas Message: Wo bí o ṣe lè dáàbò bo ara rẹ lásòkò ọdún Keresimesi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02326
Kí ló dé táwọn àkàndá ẹ̀dá ṣe ń fẹ̀hónúhàn, èyí tó fa rògbòdìyàn l‘Eko?
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02327
Nigeria Borders open: Onímọ̀ ọrọ̀ ajé ní ìlànà tẹ́tẹ́ títa ní ìjọba ń lò fétò ọ̀rọ̀ ajé
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02328
Igbakeji ọga ọlọpaa tuntun fun Ẹkun kọkanla bẹrẹ iṣẹ l’Oṣogbo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02329
O ma ṣe o, ile wo pa ọmọ ikoko ati iya rẹ l’Akurẹ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02330
Ẹ wo ọmọ iya meta ti wọn n digunjale n’Ijẹbu
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02331
Esi idibo Eko: Eyi ni iṣẹ ti Tinubu ran si awọn ololufẹ rẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02332
FUNAAB kidnap: Akẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n gbé lọ ló ń rán ara rẹ̀ nílé ìwé
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02333
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ adigunjalè, afipábánilòpọ̀ 15 l'Ondo
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02334
Ìtàn ayé Aposteli Timothy Obadare: Afọ́jú oníwàásù tó wo ọ̀pọ̀ sàn lọ́wọ́ àjàkálẹ̀ ìkọ́ ní Iléṣà
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02335
SARS: Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Remo Stars ní ikọ̀ SARS ló pa agbábọ́ọ́lú òun
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02336
Eyi lohun to ṣẹlẹ nigba ti Portable olorin ati Pasuma kọrin ni ṣọọṣi Sẹlẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02337
Ẹ jade lati dibo fẹni to ba wu yin, a ti ṣeto aabo to peye-Kọmisanna ọlọpaa Kwara
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02338
Abuja-Kaduna Train Attack: Àwọn èèyàn torí kó yọ nínú rélùwèé Kaduna si Abuja bá BBC sọ̀rọ̀ nípa bí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ṣe wáyé
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02339
Yaba building collapse: Ilé alájà mẹ́ta dàwó ní Yaba nílùú Eko, àwọn èèyàn há sábẹ́ ilé náà
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02340
Opurọ buruku ni Eyitayọ Jẹgẹdẹ, ko sẹni to fẹẹ pa a – Akeredolu
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02341
Àlàyé rèé lórí ohun tó fa ìpàdé tó ń wáyé lọ́wọ́ láàrín Obasanjo, Tinubu, àtawọn ọbalayé ilẹ̀ Yorùbá l'Abeokuta
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02342
Ẹgbẹ PDP ati APC sọko ọrọ sira wọn nitori bi Fayemi ṣe ti ileewe pa fun ọsẹ meji l’Ekiti
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02343
Eyi nidi ta a fi ni ọdun iṣẹṣe ko gbọdọ waye- Ẹmia Ilọrin
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02344
Nitori bi wọn ṣe na Kano Pillars, Makinde fun Shooting Stars ni miliọnu kan Naira
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02345
INEC fi ọjọ mẹfa kun ọjọ idibo abẹle awọn ẹgbẹ oṣelu ilẹ wa
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02346
Adewale Ayuba ṣile olowo nla, o tun di Aarẹ Bọbaṣelu n’Ikẹnnẹ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02347
Yinka Ayefele ni ìkómọ àwọn ìbẹ́ta òun kò tíì lè wáyé báyìí àyàfi tí òun bá gba páálí wọn l'Ámẹ́ríkà
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02348
Ọwọ tẹ Abubakar atawọn ọrẹ ẹ ti wọn n ta burẹdi atoogun fawọn ajinigbe
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02349
Awọn agbebọn kọ lu teṣan ọlọpaa ni Benue, wọn ba pa mẹrinla ninu wọn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02350
Coronavirus: Ọmọ ilẹ̀ Italy tó kó Coronavirus wọ Naijiria kò ní àrùn náà mọ́
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02351
Plateau Killing: Ẹgbẹ̀ CAN àti NSCIA ké gbàjarè bi wàhálà se n rúgbó
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02352
Ọpẹyẹmi loun jẹbi ẹsun ole jija, l’adajọ ba ni ko lọọ fẹwọn jura l’Ondo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02353
Ondo Murder: Awọn ọlọ́pàá kò tíì mọ ibi tí wọn sin òkú ọmọ náà sí
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_02354
Leyin ti wọn so yigi, iyawo gomina Kwara tun gba ile ati ṣọọbu fun Risikatu, obinrin toju rẹ yatọ
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02355
Dele Odule: Ọ̀pọ̀ ìwà ọdaràn òdé òní ló wà láti inú sinimá
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02356
Ole mẹta ja mọto gba l’Ondo, wọn lasidẹnti l’Ogun, lẹnikan ba ku ninu wọn
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02357
Lori ọrọ SARS: Sanwo-Olu gbe igbimọ oluwadii kalẹ fun idajọ ododo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02358
Prison Congestion: Ìdí rè é tí Adájọ́ àgbà ìpínlẹ̀ Ogun fí ṣíjú àánú wo ẹlẹ́wọ̀n 20
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02359
Eeyan kan ku, ọpọ fara pa ninu ijamba ọkọ to waye lori biriiji Third-Mainland l’Ekoo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02360
Ogun Church Kidnapping: Agbébọn ń bèèrè N6m lórí èèyàn mẹ́ta tí wọn gbé ní ṣọ́ọ́ṣì
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02361
Sunday Igboho lulẹ̀ nílé ẹjọ́, adájọ́ sọ̀kò ọ̀rọ̀ sí ajìjàgbara
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02362
Kí ló pa dókítà àjọ FIFA tó kú níbí ìdíje Ghana vs Nigeria ní Abuja? Àjọ NFF sọ̀rọ̀
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02363
Ogun tí Russia ń gbé kojú wá ń parí lọ díẹ̀díẹ̀ - Ààrẹ Ukraine, Zelensky
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02364
Haa, Obi gbe Tinubu lulẹ l’Ekoo
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02365
Fòpin sí ìjíròrò tí ò ń bá Kwankwaso ṣe – Àwọn alátìlẹyìn Peter Obi kìí nílọ̀
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02366
Ekiti man to die by hanging: Wọ́n ṣèdájọ́ ikú fún ẹni ọdún 42 l'Ekiti lẹ́yìn tó pa Ọba aládé
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02367
Ohun márùn ún tí ejò ń jẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02368
Yomi Alliyu SAN: Wo àwọn nkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa Yomi Alliyu, agbẹjọ́rò fún Sunday Igboho
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02369
Kayode Fayemi: Alágídí àti oníwàkuwà ni Oshatuyi tó fi ókọ̀ gbá mi tó tún ń pariwo pé gómìnà rán agbófinró láti na òun
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02370
Ẹ sọ fún Ademọla Adeleke kó yé sáré kìtìkìtì, sáré kàtàkàtà mọ́, kó gbára dúró gba ìwé ìpẹ̀jọ́ mi – Gómìnà Oyetola
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02371
Àwọn afurasí darandaran ṣoró ní ìpínlẹ̀ Ondo, wọ́n pa ènìyàn mẹ́ta, jó ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé àti oko.
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02372
Àdó olóró North Korea fò gba Japan kọjá, aráàlú fẹsẹ̀ fẹ
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02373
Olóṣèlú bẹ̀rẹ̀ àpárá tórí ọ̀pọ̀ olùwọ́de lẹ́yìn Peter Obi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02374
Coronavirus in Nigeria: K1 de Ultimate ní káwọn ọmọ Nàìjíríà tí kò bá ńidìí láti jáde ó gbé inú ilé wọn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02375
Eniola Badmus: Gbajúgbajà òṣèré tíátà di aṣojú LAWMA ní ìpínlẹ̀ Eko
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02376
Ko ti i si ijọba kan ni Naijiria yii to gbogun ti iṣẹ ati oṣi bii tiwa o – Buhari lo wi bẹẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02377
Ibo ọdun 2023 yii jẹ ọkan lara awọn eto idibo to daa ju nilẹ wa- Lai Mohammed
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02378
Iwo ritual killining: Monsuru ní ọtí lòun fi owó mu lẹ́yìn tí òun bá ta ẹ̀yà ara àwọn tí òun bá pa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02379
Ọwọ tẹ ayederu lọọya to tun n pe ara ẹ lọba l’Ekiti
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02380
Ọpẹ o, ijọba ti ṣi gbogbo ileewe pada nipinlẹ Eko
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02381
Ile-ẹjọ gba Oyetọla laaye lati sayẹwo awọn iwe idibo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02382
‘Èmi kọ́ ni mo ń jí ènìyàn gbé, tèmi ni láti fi ilé woͅn hàn'
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02383
Ẹ kilọ fun Fayẹmi ko ma ta ilẹ wa fawọn Fulani o-PDP Ekiti
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02384
ICC: Ẹ̀rí wà pé àwọn ológun Nàíjíríà ń hùwà ìka sí Boko Haram àti ọmọnìyàn
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02385
Eid-el-Malud: Ijọba apapọ kede ọjọ Aje to n bọ bii isinmi lẹnu iṣẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02386
Nàíjíríà méjì ló wà, kí Yorùbá gba òmìnira lọ̀nà àbáyọ - Akintoye
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02387
Sierra Leone Tanker explosion: Ìjàmbá iná sọ lásìkò tí táńkà epo àti ọkọ̀ akérò forí sọra
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02388
Shiite: Kò ní sí ìwọ́de mọ́ yíká Nàíjíríà láti bu ọ̀wọ̀ fáwọ̀n èèyàn tó dá sí wa
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02389
Ẹ gbadura fun  Kollington Ayinla o, wọn lẹsẹ-kan-aye ẹsẹ-kan-ọrun lo wa lọsibitu bayii!
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02390
Omiyale fọpọ dukia ṣòfò l’Akurẹ, Ọrẹ ati Okitipupa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02391
Oyebanji di gomina Ekiti tuntun
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02392
Gbese ree o, ijọba gba ọja lori awọn to n taja loju titi l’Ekoo, ni wọn ba bu sẹkun
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02393
Teachers retirement age and years of service: Ìrírí àwọn àgbà olùkọ́ ṣì wúlò fún àwa ọ̀dọ́
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02394
ASUU Strike: Ẹ má torí ìyansẹ́lódì ASUU dá ètò òṣèlú rú- Ààrẹ ilé aṣòfin àgbà sì ẹgbẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ NANS
0
0
0
0
0
0
yor