id
stringlengths
23
24
text
stringlengths
3
4.68k
anger
float64
0
1
disgust
float64
0
1
fear
float64
0
1
joy
float64
0
1
sadness
float64
0
1
surprise
float64
0
1
language
stringclasses
28 values
yor_train_track_a_02395
Ibrahim Magu: Ọ̀gá àgbà báńkì tẹ́lẹ̀ rojọ́ tako alága EFCC tẹ́lẹ̀, ó fẹ̀ṣùn ìbàjẹ́ kàn-án
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02396
Ogun Amotekun: Dapo Abiodun fa ikọ̀ aláàbò létí láti ṣọ́raṣe lórí ìkọjá àyè
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02397
Obasanjo ń jowú àṣeyọrí Buhari lọ ṣe ń kọ ìkọkúkọ nípa rẹ̀ - Iléeṣẹ́ ààrẹ
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02398
Iwuri nla lo jẹ fun mi: MC Olumọ ki ọmọ rẹ to kawe jade ni yunifasiti
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02399
Ogun Majek: Ọmọ, ẹbí àti àwọn òṣèré tíátà ló péjú sìnkú olóògbé
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02400
Anti Corruption War: Ìjọba bojú àánú wo àwọn gómìnà tẹ́lẹ̀ rí méjì tó ń sẹ̀wọ̀n lọ́wọ́ fẹ́sùn àjẹbánu
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02401
Laide Bakare ṣayẹyẹ ọjọọbi alarinrin fun Toyọsi Adesanya
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02402
Awọn eeyan Oro, ni Kwara, ti sọrọ soke: Yoruba pọnbele ni wa, ‘Orileede Oodua’ la fara mọ o
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02403
Awọn ajinigbe ji oniṣowo epo bẹntiroolu n’Iṣan-Ekiti
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02404
Ọwọ aṣọbode tẹ dẹrẹba oniṣowo to n ta ayederu oogun nipinlẹ Ọyọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02405
Fashola EndSARS Protest: Fashola rí kámẹ́rà he ní ibùdó ìṣẹ̀lẹ̀ Lekki Tollgate, àwọn ọmọ Nàìjíríà bá figbe ta
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02406
Muhammadu Buhari: Ọ̀pọ̀ ọmọ Naijiria ló ń jìyà nítorí ìwà àjẹbánu tó wà ní ẹ̀ka ètò ìlera - SERAP
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02407
Ondo Election 2020: Mo ṣèlérí N500 lóṣooṣù fún gbogbo ọmọ tuntun - Adeleye AAC
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02408
Makinde fọwọ si Lekan Balogun gẹgẹ bii Olubadan tuntun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02409
Ilẹ ya bo ọpọlọpọ awọn awakusa lojiji, nibi ti wọn ti n wa goolu lai gbaṣẹ
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_02410
Baba Ijẹṣa ki i ṣe ọmọ ẹgbẹ wa o- Mr LATIN
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02411
Lẹyin ti wọn gbowo, ajinigbe tu awọn ọmọ iya mẹta ti wọn gbe silẹ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02412
Ina jo ileeṣẹ SUBEB l’Akurẹ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02413
Guinea Coup: Àwọn ọmọogun orílẹ̀èdè Guinea ti gba ìjọba lọ́wọ́ ààrẹ Alpha Conde
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02414
Ayinla Kollington: Ìyàwó mí títí láéláé ni Salawa Abẹni
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02415
Social media abuse: Oyedepo ní àlòjù Twitter, Facebook àti Instagram máa ń ṣàkóbá fún àyànmọ́ ẹ̀dá
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02416
Ẹ ma mikan, ẹni to kunju oṣuwọn ni mo fẹẹ gbejọba silẹ fun-Buhari
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02417
Alimotu Pelewura: Akọni ajìjàgbara obìnrin, ìyálọ́jà àti olóṣèlú tó sun àtìmalé torí owó orí
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02418
Bashiru Olokada: Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ afurasí ọdọmọkùnrin mẹ́ta tó se'kú pa Bashiru ọlọ́kadà ní Ogere
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02419
Saraki gba Buhari nimọran lori eto aabo to mẹhẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02420
Ghana Reverend Father Kiss: Àlùfáà Obeng Larbi tọrọ àforíjì lọ́wọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tó fi ẹnu kò lẹ́nu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02421
Ọjọ keji lẹyin to ṣọjọọbi, Ṣọla Kosọkọ bimọ ọkunrin lantilanti
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02422
O ma ṣe o! Tirela akẹru re ja bọ lori biriiji Ọtẹdọla, eeyan kan ku
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02423
Yomi Fabiyi: Fíìmù ‘Owó orí ẹlẹ́wọ̀n’ jẹ́ ká mọ̀ pé ìgbà ìpọ́njú làá mọ ọ̀rẹ́
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02424
Wole Oluyede ADC Ekiti: Ibi tó yẹ kí Ekiti wà kọ́ ni eléyìí; Ẹ lẹ́ẹ ṣe ọ̀nà, a ò ríbi tó jásí o, àmọ́ tí mo bá di gómìnà...
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02425
"""Àna mi, ọmọ rẹ̀ méjì ló kú pẹ̀lú ọkọ́ ìyàwó tuntun àtàwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ lọ́jọ́ kejì ìgbéyàwó"""
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02426
Yakubu Dogara: Gómìnà Bauchi da ₦4bn owóyàá ìlú sápò iléeṣẹ́ àdáni kan
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02427
L’Agbado, Diran ba iyawo ẹ atijọ lo pọ lotẹẹli, lo ba gbabẹ ku
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_02428
Ẹ wo èrò àwọn ènìyàn lórí bí Gòmìná Akeredolu ṣe fòfin de NURTW, RTEAN nípínlẹ̀ Ondo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02429
Ti mo ba di aarẹ, ma a tu Sunday Igboho ati Kanu silẹ kiakia – Ṣoworẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02430
Awọn ajinigbe tun ji ọba alaye gbe ni Kogi
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02431
Buhari: PDP àtàwọn àjọ míì figbe ta lórí èsì ìwádìí Amẹ́ríkà nípa ìjọba Buhari
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02432
Awọn oṣere fi atilẹyin han fun Tinubu lati di aarẹ ni 2023
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02433
Bisi Akande atawọn agbaagba APC ilẹ Yoruba kan ṣepade bonkẹlẹ pẹlu Buhari
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02434
SWAT tijọba fẹẹ fi rọpo SARS yoo bẹrẹ igbaradi lọjọ Aje, ọsẹ yii
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02435
Eeyan meje padanu ẹmi wọn ninu ijamba ọkọ lọna Ilọrin s’Ibadan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02436
Lẹyin ọpọlọpọ ọdun to ṣegbeyawo, oṣere tiata yii bimọ obinrin
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02437
FRSC Covid 19 laws: Awakọ̀ ojú pópó san N26,000 nítorí ó lu òfin tó de ìtànkálẹ̀ ààrùn Covid-19
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02438
Ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ nìkan ló le tan ìṣòro ààbò, àwọn gómìnà 19 bọ́hùn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02439
Eyi ni bi ọkọ iya wa ṣe da bẹntiroolu si wa lara, to ṣana si i, to si pa mẹrin ninu wa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02440
Nitori owo iranwọ epo ti wọn yọ, awọn akẹkọọ ati oṣiṣẹ yoo maa wọkọ ọfẹ ni Kwara
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02441
Ọmọ Yahoo fi mọto tẹ eeyan mẹta pa l’Akurẹ, ni wọn ba lu oun naa pa
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_02442
Nigeria vs Benin: Paul Onuacha ló fi góòlù ra iyì fún Super Eagles
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02443
Lẹyin ọjọ meji lakata awọn ajinigbe, Oloye atawọn ọmọde mẹta ti wọn ji gbe gbominira ni Kwara
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02444
Lizzy Anjorin: Kìí ṣe ẹ̀ṣẹ̀ kí obìnrin gba ọmọ tọ́ tàbí kó san owó fún ẹni tí yóò ba gbé oyún
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02445
Bear attack Alaska woman: Bí ẹranko igbó ṣe bu ìdí obìnrin tó ń ṣe gáá lọ́wọ́ jẹ
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_02446
Coronavirus: Àjọ WHO ní àìsàn pàjáwìrì gbogbo àgbaye ló dé yìí
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02447
Facebook: Gbogbo ojú òpó ìròyìn èké ní èdé Afirika pátá ló ń lọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02448
Ẹgbẹ PDP Ekiti ṣepade apero lori ibo 2022
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02449
Lizzy Anjorin: Ẹ má bú mi, ọ̀pọ̀ òṣèré tíátà ni kìí bá mi yọ̀ fún ire mi
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02450
Lẹyin ti Wike kede ẹbun ogun miliọnu Naira, ọwọ tẹ ogbologboo ajinigbe ti wọn n wa l’Abuja
0
0
0
1
0
1
yor
yor_train_track_a_02451
Ti ẹ ba ni kawọn Fulani ma fi maaluu jẹko ni gbangba mọ, ẹ ni lati wa ọna miiran fun wọn-Gomina Kwara
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02452
Osun election tribunal: PDP ti fèsì sí ẹ̀bẹ̀ ẹsùn ẹjọ́ tí Gómìnà Gboyega Oyetọla pè lórí èsì ìdìbò gómìnà Osun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02453
Satchet Alcohol ban: Ìjọba àpapọ̀ yóò fòfin de títà àti rírà ọtí inú ọ̀rá bíi 'pẹlẹbẹ', 'pàrágà'
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02454
Ile-ẹjọ ṣekilọ: Buhari ati CBN ko gbọ fi kun ọjọ ti wọn yoo fi paarọ owo atijọ mọ
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02455
Nollywood: Àwọn òṣèré Yorùbá kan rèé tí kò sí lójú ìwòran mọ́ ṣùgbọ́n tí wọ́n ṣì wà láyé
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02456
Ilé ẹjọ́ tú ìgbéyàwó ọdún mẹ́wàá ká nítorí ẹ̀sùn ìbálòpọ̀ ọlọ́jọ́ gbọọrọ àti òògùn owó
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02457
Timothy Adegoke death case: Àwọn ẹbí Rahmon Adedoyin àti Timothy Adegoke ju òkò ọ̀rọ̀ lu ara wọn nílé ẹjọ́
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02458
Ọbasanjọ ti sọ iye ọdun to wu u lati lo laye o
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02459
Toyin Abraham: Ẹ wo ohun báwọn ọmọ ìṣọta ṣe ya bó màmá Ire lẹ́nu iṣẹ́
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02460
To bá ń ta Naira tàbí ra Naira lójú agbo ìnáwó, o ti wọ gàù - CBN
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02461
Eyi ni ọrọ ti Funkẹ Akindele sọ lẹyin esi idibo gomina Eko
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02462
Kidnapping in Ekiti: Àwọn ajínigbé kó sí gbaga ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Ekiti
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02463
APC àti PDP kọ́ ni ọ̀nà àbáyo - Sẹnétọ̀ Okunrounmu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02464
Mo n wa obinrin to le ba mi gbe oyun, emi naa fẹẹ bimọ ti yoo jogun mi – Bobrisky
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02465
Folajimi Olubunmi-Adewole: Àwọn òbí rẹ̀ ní adóòlá ẹ̀mí kò ṣaáyan tó láti dóòlà ọmọ náà ló fa ikú rẹ̀
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02466
Yoruba Nation: Ọ̀jọ̀gbọ́n Banji Akintoye ní ìjọba Nàìjíríà ti fowó ra àwọn alamí kan sáàrín àwa ajìjàgbara Yoruba Nation
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02467
Bandits killings: Àwọn jàndùkú agbébọn gbẹ̀mí èèyàn 24 ní Kaduna àti Katsina lópin ọ̀sẹ̀
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02468
Pẹlu eto tijọba ṣe, ko sẹni to le yọ wọle lati awọn ẹnuubode orileede yii mọ – Arẹgbẹṣọla
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02469
Tirela Dangote pa ọmọleewe n’Ilaro, lawọn eeyan ba dana sun un
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02470
Baba Faṣọranti fẹyin ti gẹgẹ bii olori ẹgbẹ Afẹnifẹre
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02471
India fòfin de iléeṣẹ́ tó pèsè oògun ikọ́ tó pa ọmọdé 69
1
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02472
Ṣé lóòótọ́ ni ẹkùn gúúsù Nàìjíríà ń san N25,000, tí àríwá ń san N10,000 fún ìwé ìrìnnà?
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02473
Ẹyin ara Yewa, nipinlẹ Ogun, ẹ ku amojuba Sunday Igboho
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02474
Nitori ẹsun jibiti, gende mọkanla ha sọwọ EFCC l’Ekoo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02475
Obadiah Mailafia: DSS ti fi igbákejì gómìnà CBN tó ní gómìnà kan ní Àríwá Naijiria ní Ọ̀gá Boko Haram sílẹ̀
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02476
Arẹwa obinrin kan gbẹmi ara rẹ l’Ekoo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02477
Aráàlù fọnmú lórí Pásítọ̀ tó ń gbẹ̀bí, pèsè ‘omi ayẹta’ fọ́mọ ìjọ
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02478
Wọn ti dana sun too geeti Lekki-Ikoyi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02479
MMA: Àwọn èrò ní ìwà àjẹbánu ní kò jẹ́ kí Nàíjíríà ní ohun èèlò tó yẹ ní pápákọ̀ òfurufú
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02480
Sanwo-Olu paṣẹ pe kawọn ileejọsin di ṣiṣi lati ọjọ keje, oṣu yii, l’Ekoo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02481
Awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun Ikorodu kọju ija si t’Odogbolu, lawọn ọlọpaa ba ko wọn
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02482
Dapọ Abiọdun fun awọn olukọ to fakọ yọ lẹbun ile ati owo nla nipinlẹ Ogun
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02483
Ogun Ritual murder: Ìjà ni tọkọtaya ní àwọn fẹ́ bá àbúrò mi àti ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀ parí kí wọ́n tó dá ẹ̀mí rẹ̀ légbodò - ẹ̀gbọ́n olóògbé
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02484
Mọgaji agboole fa irun abẹ tẹgbọn-taburo n’Ibadan, o loun fẹẹ fi tun ọjọọwaju wọn ṣe ní
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02485
Lẹyin oṣu meji tawọn agbofinro gba a lọwọ awọn to fẹẹ lu u pa, ọmọkunrin yii tun lọọ ji foonu
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02486
Adajọ ni ki wọn sanwo ‘gba ma binu’ fawọn aṣofin Ondo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02487
Plane crash: Díẹ̀ ló kù kí bàlúù arìnrìnàjò sílẹ̀ mímọ́ Hajj gbaná ní Minna
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02488
Buhari ti ki Obaseki ku oriire, o loun naa ba a yọ gidi
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02489
O parí! Joe Biden ní Covid-19 dohun ìgbàgbé l‘Amẹ́ríkà ṣùgbọ́n...
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02490
Wahala ree o! Awọn akẹkọọ mejidinlogun jẹ majele ninu ounjẹ nileewe l’Ọṣun
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02491
Tori ijamba ina nla, ijọba ti biriiji Apọngbọn pa l’Ekoo, wọn le awọn ontaja danu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02492
Seyi Makinde: Ìrírí, ọ̀gbọ́n àti ìmọ̀ ìgbìmọ̀ yìí yóò ṣèrànwọ́ fún ìjọba mi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02493
Lagos Flood: Wọ́n ṣì ń wa àwọn ọmọ méjì tí àgbàrá òjò wọ́ lọ ní Ketu l'Eko
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02494
Lizzy Anjorin: Fún ayẹyẹ ọdún kan ìgbéyàwó wọ́n, ọkọ Lizzy fi ọkọ̀ tá lọ́rẹ
0
0
0
1
0
0
yor