id
stringlengths
23
24
text
stringlengths
3
4.68k
anger
float64
0
1
disgust
float64
0
1
fear
float64
0
1
joy
float64
0
1
sadness
float64
0
1
surprise
float64
0
1
language
stringclasses
28 values
yor_train_track_a_02195
Ṣeyi Makinde atawọn agba ẹgbẹ PDP fẹẹ fi Gbenga Daniel ṣe adari ẹgbẹ naa nipinlẹ Ogun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02196
Nitori owo olowo ti wọn ji mọ ọn lọwọ, Abraham binu bẹ somi n’Ilọrin
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02197
Oku dero ahamọ ni Kwara, ọmọ rẹ lo lu dokita lalubami lọsibitu
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02198
Pastor Adeboye on 2023 Election: Wọ́n bi mi pé ta ni yóò di ààrẹ Nàìjíríà lọ́dún 2023
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02199
Awada lasan ni bi awọn Mayetti Allah ba lawọn yoo koju ija si Yoruba-Gani Adams
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02200
Ara gomina Eko ti ya patapata, wọn ni Koro ti kuro lara ẹ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02201
Lẹyin iku Akeredolu, wahala n bọ ninu ẹgbẹ APC Ondo
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02202
Digbi ni mo ṣi wa lẹyin Wike, mi o ṣetan lati gba ipo kankan lọwọ Atiku-Mimiko
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02203
Wọn fẹsun buruku kan Purofẹsọ ọmọ Yoruba, wọn lo gbowo lọwọ awọn afẹmiṣofo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02204
Ọwọ tí tẹ mẹ́rin lára àwọn jàǹdùkú to ṣé ìkọlù sí ọkọ̀ ipolongo Adelabu ní ìpínlẹ̀ Oyo
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02205
Lai Muhammed kọlu awọn to sọna sileeṣẹ Tinubu, o ni ọta oniroyin ati dẹmokiresi ni wọn
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02206
Benue news: Èèyàn méjì kú lásìkò tí ṣọ́ọ̀ṣì dà wó ní Taraba, àwọn míràn farapa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02207
World Teachers Day: Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé rèé nípa ìlànà àkànṣe owó oṣù tuntun fáwọn òlùkọ́
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02208
Aisha Yesufu: Àbúrò ìyá mí tó ti wà di olùṣọ àgùntàn lóni fojú mí rí mọbo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02209
2023 Presidency: Adelé alága APC l'Eko ní àdéhùn wà láàrín Buhari àti Tinubu lórí ìdíje ipò ààrẹ lọ́dún 2023
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02210
Tinubu ki i ṣọmọ Eko, wọn mu mi deleewe to lọ n’Iragbiji – Bọde George
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02211
Oúnjẹ àràmọ̀ǹdà mọ́kànlá tí wọ́n ń jẹ lágbààyé rèé, ẹ tẹ́wọ́ gbàá
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02212
Ẹjẹ eeyan lawọn eleyii rọ sinu kẹẹgi ti wọn ba lọwọ wọn
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02213
Ọ̀gá Bello: Àìgbọ́n ló ń da àwọn òsèré tíátà tó ń jà lórí ayélujára láàmú
1
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02214
"Jàǹdùkú yawọ ilé Abẹnugan ilé aṣòfin US, bí wọ́n ṣe fọ́ ""hammer"" mọ́ ọkọ rẹ̀ lórí rèé"
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_02215
Oyo Chieftancy Coronation: Ìpapòda Aláàfin kò ní dá ètò ìfinijoyè Femi Gbajabiamila dúró- Ọyọmesi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02216
Ogun Pastor rapes choir member: Èmi àti ọmọ ẹgbẹ́ akọrin wa jọ yó ìfẹ́ ara wa ni, mi ò jẹ̀bi
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02217
Kemi Afolabi on Lupus: Wo bí Kemi Afolabi ṣe ń dúpẹ́ lọ́wọ́ àwọn tó ti kàn síì pẹ̀lú owó ìtọ́jú àìsàn Lupus
0
0
0
1
0
1
yor
yor_train_track_a_02218
Ọ̀lẹ ní àwọn DSS ní Naijiria, TV ni wọ́n máa ń wò nígbà tí mo wà ní páńpẹ́ wọn- Ṣowore
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02219
Yorùbá dùn lẹ́nu àwọn ọmọ yìí níbi ìdíje ẹgbẹ́ Àtúnbí Yorùbá
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02220
ṢEYIN NAA TI GBỌ IKILỌ TI BỌLA TINUBU ṢE FUN ỌBA ONIRU TUNTUN
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02221
Dino Melaye: Àsìkò ti to fún ọ̀rọ̀ ''Zoning'' ipò ààrẹ ní Naijiria láti dópin
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02222
Ijọba ti ni kawọn ileejọsin, otẹẹli,  ileewe atawọn mi-in maa ṣilẹkun l’Ogun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02223
Ogun rape: Bàbá ọdún 52 fi ipá bá ọmọ rẹ̀ ọdún mẹ́wàá lòpọ̀
0
1
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02224
Emmanuel n rin ni bebe ẹwọn, foonu lo ji l’Ado-Ekiti
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02225
Queen: Obabinrin Elizabeth ṣàfihàn orí adé mẹ́ta tó lè jé lẹ́yìn rẹ̀
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02226
Baba mí fí ọwọ́ sí Folarin gẹ́gẹ́ bíi Gómìnà, ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ àwọn méjèèjì- Ọmọ Alao Akala
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02227
Sotitobire: Ọkọ mi kò mọ̀ Jegede PDP rí, kódà kò fa ẹnikẹ́ni kalẹ̀ dípò Akeredolu- Bisola ìyàwó Alfa Sotitobire
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02228
ASUU Strike Nigeria: ASUU ti fòpin si ìyàsẹ́lódì olósù mẹ́sàn-an tí wọ́n gùnlé
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02229
Nigeria Independence Day: Ìyàpa ẹ̀yà, èdè àti ẹ̀sìn ló mú akùdé bá ìṣọ̀kan Nàíjíríà
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02230
EndSARS rememberance: Ohun táwọn afẹhóúhàn bèrè fún ní Lekki lónìí rèé
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02231
Mali sex slave returnee: Báàlù la rò pé a máa wọ̀ lọ Mali, ìrìn òṣù kan gbáko lá rìn láti Togo dé Mali
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_02232
Ile-ẹjọ ni ki ọlọpaa san owo itanran fun Agboọla, igbakeji gomina Ondo tẹlẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02233
Idasilẹ ọlọpaa ipinlẹ: Awọn aṣofin Eko ta ko ipinnu ọga ọlọpaa patapata
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02234
Wahala mi-in tu n bọ o! Awọn aafaa Ilọrin fẹẹ gbena woju obinrin to n ṣe ẹṣin Musulumi ati Kirisitẹni papọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02235
Wo ohun ti gómìnà Akeredolu sọ nípa ìkọlù tuntun tó wáyé nílùú Owo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02236
Hijaabu: Eyi ni bawọn Musulumi ṣe kọ lu wa -Rẹfurẹẹni Dada
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02237
DFL: Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ yìí tún ń kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ girama ní iṣẹ́ Asoná, bàtà àti báágì ṣíṣe
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02238
Radio Nigeria attack: Àwọn jàndùkú ba ọ̀kẹ́ àìmoye dúkìá jẹ́ lásìkò ìkọlù sí Amuludun FM n'Ibadan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02239
Gbenga Daniel darapọ mọ ẹgbẹ APC
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02240
Sowore ni àwọn ọmọ Nàìjíríà ló gba òun lọ́wọ́ àhámọ́ DSS
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02241
Impeached Kenya Governor: Sonko Mbuvi ní àwọn alájẹbánu tóun dí lọ́wọ́ ló yọ òun nípò
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02242
Ẹyin patapata nilẹ Hausa maa n wa to ba di ti ọrọ ẹkọ – El-Rufai
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02243
Nigeria vs Netherlands: Àtilẹ ló yẹ kí ìjọba ti máa mu ìdàgbàsókè bá eré bọ́ọ̀lù-Onigbinde
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02244
Adajọ da awọn ẹsun kan ti Atiku fi kan Tinubu nu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02245
Fresh $5.8bn loan: SERAP kìlọ̀ fún Buhari pé kó yé kó Nàìjíríà sí gbèsè
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02246
Yoruba Nation: Mo faramọ́ àtúntò 'Restructuring' tí kò lọ́wọ́ ìṣèlú nínú- Oba Ahmed Adekunle Makama ti Kuta
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02247
Burundi government fires workers with side chics: 'Bóo bá yan àlè lẹ́nu iṣẹ́ Ọba níbí, gbígba ilé lọ yá fún ọ nìyẹn!'
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02248
Baale ile yii gbe majele jẹ nitori ti ọrẹbinrin rẹ n yan ale
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02249
Oyo Party Politics: Lanlehin kéde ìparí gbogbo ètò láti darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèlú APC
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02250
A o ni i din owo-oṣu awọn oṣiṣẹ ku nitori ọrọ-aje to n ṣojojo- Gomina Dapọ Abiọdun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02251
Rape cases in Nigeria: Ọmọ ọdun 5 àti 14 ni Kalu wà nígbà tí obìnrin fipá ba lòpọ̀
0
1
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02252
Amotekun: Ìdí táwọn àgbà Nàìjíríà fi ń forí gbárí àti ohun tó yẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02253
Awọn janduku fẹẹ jo ileegbimọ aṣofin Ekiti
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02254
Oṣiṣẹ mọṣuari ge ori oku olokuu, o ta a fawọn afeeyan ṣetutu l’Abẹokuta
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02255
Jidah fọgi mọ Khadija lori titi to fi ku ni Kwara, o lajẹẹ ni
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02256
Tinubu lẹ́bọ lẹ́rù, a kò lè máa fi òun àti Atiku wé ara wọn – Dino Melaye
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02257
Iyaale ile dawati n’Ilọrin, lawọn ọdọ ba ya bo ile Baba Kofo ti wọn fura si
1
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02258
Awọn fijilante pa ajinigbe kan, wọn gba iya atọmọ ti wọn ji gbe silẹ ni Kwara
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02259
Bolaji Amusan: TAMPAN ń ṣiṣẹ́ lórí 'minimum wage àti insurance' òṣèré báyìí- Mr Latin
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02260
Tori Baba Ijẹṣa, awọn eeyan bu Yọmi Fabiyi, wọn lo ti kọyin sibi taye kọju si
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02261
Irọ́ lo pa! Ariwo Yorùbá Nation rẹ̀, ọgbọ́n àti dá ọmọ Yorùbá sínú láàsìgbò ni - Tinubu fún Akintoye lésì
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02262
Lekki Tollgate shooting: Fídíò táa ní lọ́wọ́ kò ṣàfihàn gbogbo ohun tó ṣẹlẹ̀ nírọ̀lẹ́ ọjọ́ náà - LCC
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02263
O ma ṣe o, awọn to n feeyan ṣoogun owo pa John ni Ọbantoko, oju ati ọwọ rẹ ni wọn ge lọ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02264
Grace Oshiagwu: Afurasí ní abọ́ oúnjẹ kan, ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta náíra lòun ń gbà lóri àwọn tó pa l'Akinyele
0
1
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02265
Ajọ SERAP kilọ fun Buhari: Tete yaa sọ fun ijọba Niger Republic ki wọn da owo to o fun wọn pada
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02266
Igbẹjọ ti bẹrẹ nile-ẹjọ to ga ju lọ lori ọrọ Tinubu, Atiku ati Peter Obi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02267
Awọn janduku ya wọ ileewe ẹkọṣẹ iṣegun UNIOSUN, wọn fẹẹ gbe oku lai ṣe akọsilẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02268
Bukola Akinade Senwele Jesu: Warisi, Zah zuh, Galalala, wo àwọn àṣàkàṣa tí Senwele ní kò bá òfin Ọlọ́run mu
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02269
Dare Adeboye: Ẹbí Adeboye ní àwọn kò ní pe Ọlọ́run ní ẹjọ́ lórí ìkú Dare Adeboye
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02270
Awọn aṣofin Eko koro oju si fiimu tawọn oṣere n gbe jade, wọn ni palapala ti pọ ju ninu ẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02271
Adajọ ju aafaa ajanasi ilu Ẹdẹ to lu jibiti miliọnu mẹwaa sẹwọn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02272
Amotekun: Aro tó wá láti ilú Ọyọ ló máa ń fi ẹranko náà dojú ìjà kọ àwọn ọ̀tá
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02273
Liz Truss ní olóòtú  ìjọba tí sáà rẹ̀ kéré jùlọ nínú ìtàn ilẹ̀ UK, ọjọ́ 45 ló lò nípò
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02274
Ajah-Lagos Mayhem: Ọkọ̀ àjàgbé tẹ ọlọ́kadà àti èrò rẹ̀ pa L'Eko, wàhálà bẹ́ sílẹ̀
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02275
Ẹwọn n run nimu Ṣeyi o, aṣẹwo lo fipa ba lo pọ n’Ilupeju-Ekiti
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02276
Rotten Tomatoes: Ìdí tí Tòmátò ẹ̀sà kò ṣe dára fún ìlera yín; wo àwọn kókó márùn-ún yìí
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02277
Ohun tí ó yé kóò kọ́ nípa ìròyìn òfégè ṣáájú ìdìbò 2023
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02278
Obi Cubana: Ilé ijó 'Hustle and Bustle' di tìtì pa lẹ́yìn ikú olùgbafẹ́ kan
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02279
Awọn ṣọja ṣawari ileeṣẹ ti wọn ti n ta ọmọ tuntun, ọpọlọpọ aboyun ni wọn ko kuro nibẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02280
Free Salihu Tanko Yakasai Dawisu: Lẹ́yìn o rẹ́yìn, gómínà Ganduje Kano yọ Dawisu ní íṣẹ́ nítorí o sọ̀rọ̀ tako Ààrẹ Buhari
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02281
Àwọn ọmọ ogun ilẹ̀ Nàìjíríà dóòlà ẹ̀mí ẹni méjì ní Owena ní Ondo
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02282
Mutiu Ajamajẹbi ti jẹbi o, ole lo ja ti wọn fi sọ ọ si atimọle ni Ṣaki
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02283
Buhari lifts Twitter ban: Buhari fún ọmọ Naijiria lẹ́bùn ayẹyẹ òmìnira, ó gbẹ́sẹ̀ kúró lórí Twitter pẹ̀lú ìkìlọ̀
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02284
Eto-ẹkọ lo gba eyi to pọ ju ninu eto-iṣuna ipinlẹ Ọṣun ọdun to n bọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02285
Okunnu ṣepe fawọn to ba Naijiria jẹ, o laye wọn maa bajẹ ni
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02286
Sunday Igboho: Oba Ogunwusi rọ Igboho láti máṣe dá òfin ṣe lọ́wọ́ ara rẹ̀
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02287
Ikunlẹ abiyamọ o! Wọn gun akẹkọọ Poli Iree pa sinu ile rẹ l’Ọṣun
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02288
Ogun: Ọkùnrín márùn ún fojúbalé ẹjọ́ lórí ẹ̀sùn ijà àti igbó fífà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02289
Tori awọn ọmọ mi ni mo ṣe fiṣẹ olowo nla silẹ ni Naijiria, ti mo n ṣe lebura niluu oyinbo- Ṣọla Ṣobọwale
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02290
Tadenikawo, Adesọji, Aderẹmi lorukọ ọmọ Ọọni tuntun
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02291
Lẹyin ti Pasitọ Joshua fipa ba obinrin kan sun tan lo fun un lọrun pa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02292
Lagos Explosion: Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ iléẹ̀kọ́ Bethlehem ń gbàdúrà òwúrọ̀ lọ́wọ́ ní ìbúgbàmù wáyé
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02293
Boko Haram: Wo àwọn ọmọ Nàìjíríà mẹ́fà tí UAE ń wá lórí ẹ̀sùn ṣíṣe àtìlẹ́yìn owó fún Boko Haram
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02294
"""Tẹ́ẹ bá mọ Adebutu dáadáa, ó máa ń ṣe èèyàn bí ẹni tí kò jẹ́ pàtàkì""; ""Irọ́ ńlá lẹ pa"" - Igun Adebutu àti Jimi Lawal"
1
0
0
0
0
0
yor