id
stringlengths
23
24
text
stringlengths
3
4.68k
anger
float64
0
1
disgust
float64
0
1
fear
float64
0
1
joy
float64
0
1
sadness
float64
0
1
surprise
float64
0
1
language
stringclasses
28 values
yor_train_track_a_02095
Loootọ nijọba jẹbi, ẹyin ọdọ, a tọrọ aforiji-Ọsinbajo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02096
Ọlọpaa dero atimọle l’Ekiti, eeyan meji lo yinbọn pa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02097
Gomina Seyi Makinde wọle pade pẹlu Ladọja, Lekan Balogun atawọn agba oye Ibadan
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02098
Ibadan Bullion Van Robbery: Olùbádámọ̀ràn fétò àbò fún gómìnà Oyo ṣí aṣọ lójú àwọn tó ṣe onígbọ̀wọ́ ìdigunjalè ọkọ̀ agbówórìn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02099
Iru ifẹ wo ree: Nitori ti ọkunrin ja a kulẹ, akẹkọọ-binrin yii binu gbẹmi ara ẹ
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_02100
Yusuf Buhari and Zahra Bayero wedding :wo àwòrán àwòdamiẹnu níbi ìgbéyàwó ọmọ ààrẹ Buhari
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02101
Awọn adajọ bii mẹjọ ni yoo ṣoju Sunday Igboho nile-ẹjọ ni Benin
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02102
Oluwatosin atawọn ẹgbẹ ẹ ja tirela to kun fun simẹnti gba, wọn ṣa dẹrẹba ladaa yannayanna
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02103
Isbae u, boyfriend mummy wa: Ẹ foríjìnmí, ẹlẹ́ran ara ni mí- Gbajúgbajà adẹ́rìnpòṣónú, Bae_U Adebayo Ridwan Abidemi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02104
O ma ṣe o! Agbabọọlu yii si ṣubu lulẹ lori papa, lo ba ku patapata
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02105
Amotekun: Toogun ní àwọn sá fún ariwo ni wọ́n ṣe ń ṣàyẹ̀wò fún ọ̀dọ́ 47,000 tó bèèrè iṣẹ́
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02106
Ọmọọdọ yii dẹ adigunjale si ọga ẹ n’Ifaki-Ekiti, wọn gbowo nla lọwọ ẹ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02107
Ile-ẹjọ ṣẹ Oyetọla lẹyin, wọn ni ko yẹ ko kopa ninu ibo gomina to kọja
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02108
Ọpẹ o, wọn ti tu awọn ọmọ ijọ Ridiimu tawọn agbebọn ji gbe ni Kaduna silẹ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02109
Olusegun Obasanjo: Ààrẹ àná orílẹ́èdè Nàìjíríà ní òun ò lè padà sí ẹgbẹ́ òṣèlú PDP mọ́ láyé
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02110
Ọba Ẹlẹkọle ti Ikọle dawati laafin, ni gbogbo ara ilu ba n jaya
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02111
Ẹwọn n run nimu Kingsley, ọmọ ọdun mẹtala lo fipa ba laṣepọ ni Kwara
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02112
Ọbasanjọ ṣabẹwo si Olubadan ti wọn ṣẹṣẹ yan
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02113
Igbanisiṣẹ fun ikọ Amọtẹkun bẹrẹ l’Ekiti
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02114
Buhari driver: Kò sẹ́ni tó lè ní kí Buhari má gba ìtọ́jú nílẹ̀ òkèèrè - Amúgbálẹ́egbẹ́ Ààrẹ
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02115
Bisi Alimi: Inú mi dùn sí bí Gabon ṣe fòǹtẹ̀ lu òfin pé kí akọ máa fẹ́ akọ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02116
Awọn dokita lugbadi arun Korona lọsibitu ijọba n’Ibadan, ni wọn ba ti i pa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02117
A ti ṣetan lati ṣeto owo ta a le fi ran awọn darandaran lọwọ – Tinubu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02118
Wọn lawọn Fulani tun dana sun ina oorun (Solar) tawọn araalu Awowo n lo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02119
Ọwọ tẹ wọn o: awọn to n fi ọkada ja foonu gba nIlọrin
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02120
Ọrẹ meji gbadajọ ẹwọn ọdun mọkanlelogun, nitori ẹsun idigunjale
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02121
EFCC: Ọmọ Nàíjíríà ń bèèrè pé báwo ní àjọ náà ṣé mọ èké babaláwo?
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02122
Awọn oloṣelu kan ti n ko awọn akekọọ jọ lati ṣewọde tabuku ijọba Tinubu- DSS
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02123
Adajọ ti ran Pasitọ Enock lẹwọn gbere, ọmọ ijọ rẹ lo fipa ṣe ‘kinni’ fun l’Omuo-Ekiti
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02124
June 12: Ọ̀gá àgbà ọlọ́pàá ní Nàìjíríà sọ lórí ìfẹ̀hónúhàn táwọn èèyàn fẹ́ ṣe lásìkò àyájọ́ ìjọba awarawa
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02125
Aláàfin of Oyo dead: Wọ́n ti fẹ́ gbé Alaafin lọ ibi itẹ́, wo bí àwọn ènìyàn ìlú Oyo ṣe ń kẹ́dùn Ọba Adeyemi
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02126
Lẹyin ti wọn fi maaluu jẹ oko rẹ, awọn Fulani tun pa Sunday nipakupa l’Akoko
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02127
Wanted by EFCC: Mompha fèsì Ó ní ìdúnkokò ni wọ́n ń ṣe láti gba N140m lọ́wọ́ òun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02128
Kootu ti ọkunrin yii ti ji batiri mọto yọ naa ni wọn ti ju u satimọle
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02129
Bi ọlọpaa tabi ṣọja ba fiya jẹ Yoruba kan lọna aitọ, a maa sọ ọ dogun mọ wọn lọwọ ni- Sunday Igboho
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02130
Ileeṣẹ ọlọpaa doola ẹmi arinrin-ajo mẹrin ninu mẹfa tawọn ajinigbe ji gbe ni Kwara
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02131
Abacha loot: Wọ́n tún ṣàwárí ọ̀pọ̀lọpọ̀ owó tí Abacha jí kó ní UK
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02132
Ghana: Kàyééfì! Ẹ wó ìyàwó tó ṣán ọkọ rẹ̀ mọ́lẹ̀ tó sí bẹ lórí !
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02133
Eedi ree o! Ibọn ọlọdẹ ṣeeṣi yin, o pa ọmọde mẹta, awọn mẹrin wa nileewosan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02134
Jumoke Oyeleke: Wo ẹ̀bùn ńlá tí ìjọba fi ta ìyá tó pàdánù ọmọ rẹ̀ lásìkò ìwọ́de lọ́rẹ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02135
Wón ní àwọn ni Lébìrà, Lébìrà ní wón á ṣe ...! - Tinubu sọ òkò ọ̀rọ̀ sì ẹgbẹ́ òṣèlú Labour Party
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02136
Dino Melaye: Ẹ̀yin ara Ondo, ẹ kígbe pé kò fẹ́ èrú ìbò, kí ìbò yín má ba à wọmi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02137
Catholics in Nigeria: Father Mbaka ní kò sí wàhálà láàrín òun àti ìjọ Kátólìkì
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02138
Àlàyé rèé lórí ìdí tí mo fi dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèlú - Dele Odule
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02139
Ọpẹ o! Ija pari laarin awọn afọbajẹ Ibadan, Ladọja loun ko ba wọn ṣẹjọ mọ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02140
Mi o ni i ṣatilẹyin fun aarẹ lati ilẹ Hausa – El-Rufai
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02141
Ìtàn Mánigbàgbé: Òwe ‘aṣọ kò bá Ọ́mọ́yẹ mọ́... kọ́ wa láti máa ní ṣùúrù
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02142
Iru ki waa leleyii, ọkada meji fori sọ tirela l’Abẹokuta, lo ba tẹ wọn pa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02143
Isabel dos Santos: Obìnrin tó lówó jùlọ ní Africa 'ja orílẹ̀-èdè rẹ̀, Angola lólè' fi kó ọ̀rọ̀ jọ
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02144
Oluwoo we lawani fun Imaamu Agba tuntun niluu Iwo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02145
Unknown gunmen attack: Àwọn agbébọn kọlu àgọ́ ọlọ́pàá ní Anambra, wọ́n tún pa ẹ̀ṣọ́ aláàbò kan ní Enugu
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02146
Happy Independence day nigeria 2021: Bí a ṣe fòfin mú Sunday Igboho, Nnamdi Kanu ti tú àṣírí àwọn tó ń ṣagbátẹrù wọn
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02147
Marijuana Use: Àwọn onímọ̀ ìjìnlẹ̀ ṣàlàyé ewu àti ànfàní tó wà nínúi igbó mímu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02148
Gender Based Violence: Àjàkálẹ̀ àrùn míì ní ìfìpábánilòpọ̀ níbí pẹ̀lú adúrú obìnrin tí wọ́n ṣeé sí
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02149
Adanu nla ni iku Alaafin jẹ fun iran Yoruba – Oluwoo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02150
NDLEA mu awọn meji to n ta egboogi oloro fawọn agbebọn ni Kwara
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02151
Àwọn afurasí adigunjalè kun àwọn ènìyàn lọ́rùn, jà wọ́n lólè, fipá bá wọn lòpọ̀
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02152
Harry and Meghan: Olóòtú Canada ní ọ̀rọ̀ gbọ́dọ̀ wáyé nípa ìgbésẹ̀ wọ̀n
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02153
Lọjọ kan ṣoṣo, arun Korona pa eeyan marun-un nipinlẹ Ọṣun
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02154
Afurasí tó kó òkú ajá, ejò, olóngìnní 183 sínú 'freezer' kó sí pańpẹ́ ọlọ́pàá
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02155
Timothy Adegoke Vs Rahmon Adedoyin: Ẹbí Adedoyin korò ojú sí ọ̀rọ̀ tó ń lọ lórí ayelujára nípa ìgbẹ́jọ́ wọn
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02156
Awọn tọọgi ya bo sẹkiteriati APC l’Ọṣun, alubami ni wọn lu awọn ọmọ ẹgbẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02157
Int'l Anti-Corruption Day: Àwọn kan ní ìwà àjẹbánu ń peléke síi n'íjọba Buhari, àwọn míì ní Buhari ń gbìyànjú
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02158
Fulani herdsmen attack: Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ láti ẹnu ọba ìlú tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ti wáyé
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02159
Oyo traders crisis: Ẹgbẹ́ oníṣòwò ṣèwọ́de lórí ìyànsípò YK Abass gẹ́gẹ́ bí bàbálọ́jà tuntun
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02160
Ademodi Maria 12 year old boxer: Mo máa kọ́kọ́ bí ẹ́ pé ṣé o lè nà mí kí n tó wá fi àgbà hàn ẹ́
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02161
Amotekun: Akeredolu àti PDP tahùn síra wọn lórì owó oṣù òṣìṣẹ́ l'Ondo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02162
Aráàlú yarí lórí ọ̀wọ́ngógó, ìyanṣẹ́lódì bẹ̀rẹ̀ kàákirí South Africa
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02163
Wo àwọn gómìnà tó tí jẹ ní ìpínlẹ̀ Osun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02164
Irọ lawọn ọlọpaa n pa, a ko ba wọn já ti ọga wọn fi yinbọn mọ wa l’Orílé-Igbọ́n – Ọga Amọtẹkun
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02165
"Kí ló dé tí àwọn ọ̀dọ́ ìlú fárígá lọ dáná sun ""mortuary"" ọlọ́dani kan?"
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02166
Tinubu ki Atiku ku oriire, o lawọn maa jọ dije dupo aarẹ laipẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02167
Aarẹ ilẹ Amẹrika ti korona kọlu sọ pe ara oun ti ya o
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02168
Tinubu tun ṣabẹwo si Buhari l’Abuja, o ni inu oun dun si bawọn ondije funpo aarẹ ṣe n pọ si i
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02169
Ijọba ko ni i kede ofin konile-gbele nitori arun Koronafairọọsi- Lai Muhammed
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02170
O ma ṣe o,  awọn janduku pa eeyan mẹtala ninu mọlẹbi kan naa ni Kogi
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02171
Ẹ takete si aṣilo oogun, Gomina Abdulrazaq rọ awọn ọdọ ni Kwara
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02172
Ọsibitu aladaani to ba tọju alarun Korona l’Ọṣun yoo jiyan rẹ niṣu- Ẹgbẹmọde
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02173
Ọwọ tẹ ọmọ Yahoo pẹlu ori eeyan tutu atawọn eya ara mi-in l’Ondo
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02174
Awọn ọdọ ṣewọde ni Kutọ, wọn ni ki Buhari maa lọ
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02175
Ọwọ tẹ Rasaki ati Wasiu nibi ti wọn ti n ja awọn onimọto lole lori biriiji Ọtẹdọla
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02176
Ẹ̀sùn àìmọ̀dí gbé Theophilous dọ́gbà ẹ̀wọ̀n, ìwé ẹ̀rí ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ méjì ló gbé jáde
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02177
Lẹyin ọdun mẹtalelogun to ti n jokoo, Yinka Ayefẹlẹ ti le dide kọrin bayii
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_02178
Àlàyé rèé lórí bí 'Popular Jingo' ṣé dí inagijẹ akọrin Juju tó bí Wale Thompson 'Lalalẹ Friday'
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02179
Tinubu gba awọn ọdọ nimọran: Ẹ yee ba dukia jẹ lasiko tẹ ẹ ba n fehonu han
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02180
Oyo PDP Crisis: Abass Oloko ní igun tó ń fapá jánú kò le dá borí ìbò tẹ́lẹ̀ kí Seyi Makinde tó dé
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02181
Orúkọ ọmọ ni Yorùbá gbà pé ó máa ń ro ọmọ nílẹ̀ Oodua
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02182
Nitori ọwọngogo ounjẹ, Akeredolu fofin de gbogbo ẹgbẹ oniṣowo nipinlẹ Ondo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02183
Sunday Igboho: Wo bí àwọn ọmọ Yorùbá ṣe tako ìhàlẹ̀ láti dá ìbò 2023 dúró
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02184
Peter Obi ti sọrọ:  Ile-ẹjọ to ga ju lọ nilẹ yii maa gbẹtọ mi fun mi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02185
Yoruba Nation: Ẹ̀yin òṣìṣẹ́ ìjọba, ìyà ń bọ̀ fúń yín bí Nàìjíríà bá túká pẹ́rẹ́ - Oluwo
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02186
Lizzy Anjorin: Ẹ̀yin tẹ bímọ fún ọkọ mi, ẹ kó ọmọ wa ká ṣe àyẹ̀wò DNA fún wọn
1
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02187
Aago ọwọ kan ṣoṣo ti mo mọ Aarẹ Tinubu lo n ṣi n wọ, ile mi daa ju tiẹ lọ – Shettima
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_02188
Aṣiṣe nla ni bi mo ṣe fi Agbọọla ṣe igbakeji mi – Akeredolu
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02189
Tinubu ló sanwó ta fi gbé òkú Moji Olaiya wá láti òke òkun - Jide Kosoko
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02190
Amotekun ìpínlẹ̀ Ondo ti ń wá àwọn òṣìṣẹ́ ojú ọ̀nà mẹ́ta tí wọ́n jí gbé lágbègbè Akoko
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02191
Nitori ọlọkada to paayan, awọn ọdọ dana sun ọkada bii ogun n’Isọlọ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02192
Samuel Okwaraji: Ó pé ọdún mọ́kànlélọ́gbọ̀n tí Samuel Okwaraji ṣubú lójú ìjà
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_02193
PDP yoo ṣeto idibo abẹle funpo aarẹ ninu oṣu karun-un
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_02194
Idibo 2023: ijọba fẹsun ibanilorukọjẹ kan ẹgbẹ oselu PDP, ni Kwara
0
0
0
0
0
0
yor