id
stringlengths
23
24
text
stringlengths
3
4.68k
anger
float64
0
1
disgust
float64
0
1
fear
float64
0
1
joy
float64
0
1
sadness
float64
0
1
surprise
float64
0
1
language
stringclasses
28 values
yor_train_track_a_01895
Coronavirus: Ọmọ Nàìjíríà tó darí láti France wá labẹ àyẹwò lórí Coronavirus
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01896
Zamfara Bandits Attacks: Agbébọn pa ogún èèyàn torí wọn kò rí N40m ìsákọ́lẹ̀ abúlé wọn san
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01897
Eyi nidi ti mo fi n ṣọdun Olodumare – Oluwoo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01898
Corruption in High Places: Wo àwọn èèkàn ìjọba márùn ùn tí wọ́n fẹ̀sùn àjẹbánu kàn lábẹ́ ààrẹ Buhari
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01899
Ko sohun to kan ọga ọlọpaa patapata lori agbekalẹ ikọ Amọtẹkun -Oyelẹyẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01900
Àwọn òṣèré tíátà Yoruba sọ̀rọ̀ nípa Baba Suwe tó di olóògbé
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01901
Ondo rape apologist: Olùkọ́ kan di èrò ọgbà ẹ̀wọ̀n fún fífipá bá ọmọ ọdún mẹ́wàá lòpọ̀ ní ìpínlẹ̀ Ondo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01902
NYSC banujẹ lori agunbanirọ tawọn janduku yinbọn pa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01903
EndSARS: Àwọn ìyàwó àwọn ọlọ́pàá tó kú lásìkò ìwọ́de EndSARS ní sọ̀wédowo tí ọ̀gá àgbà ọlọ́pàá fún wọn kò gbówó jáde ní báǹkì
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01904
Odion Ighalo: Ẹlẹ́sẹ̀ ayò Ighalo ń ronú láti padà sí Super Eagles láìpẹ́
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01905
Ohun tó pa Yemi Adegunju, òṣèré tíátà tó jáde láyé rèé
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01906
Baba Ijesha: TAMPAN ní Iyabo Ojo, Nkechi Blessing àtàwọn míì tó bá tàbùkù ẹgbẹ́ rugi oyin
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01907
Àwoͅn awakòͅ ìgboro ti fagilé ìyansͅéͅlódì oͅlóͅsèͅ kan ní ìlú Eko
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01908
Eyi ni bi igbakeji ọga ọlọpaa patapata ṣe ṣubu lulẹ ninu ọfiisi rẹ, to si ku patapata
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01909
Mothers day: Lẹ́yìn Olorun, Ìyá mi ló kù- Papa Ajasco, Abiodun Ayeyinka
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01910
Baba Ijesha: Agbẹjọ́rò tuntun bẹ ilé ẹjọ́ kó sún ìgbẹ́jọ́ síwájú torí òun kò mọ ohun púpọ̀ nípa ẹjọ́ náà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01911
King of Bahrain robot bodyguard: Wo ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa ‘rọ́bọ́ọ̀tì Ọba Bahrain’
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01912
Ọdun Itunu Aawẹ: Tinubu ko irẹsi ranṣẹ si wọn ni Kano, Nasarawa
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01913
O ma ṣe o, Gomina Rotimi Akeredolu ti ku o!
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01914
Xenophobia Attack - Ilẹ South Afrika kò ní gbàgbé Nàìjíríà fún àtìlẹyìn wọn.
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01915
ICPC vs Kashamu: Irọ́ ni ICPC ń pa mọ́ Kashamu lórí ọ̀rọ̀ ọkọ̀ áńbúlàǹsì àti ẹ̀rọ amúnáwá
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01916
Covid-19 Wedding: Ọkọ àti Ìyàwó yìí ti dájọ́ sọ́ná ṣáájú Coronavirus
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01917
Eeyan meji ku nibi ija ọlọkada atawọn alakooso ọgba ẹwọn n’Ibadan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01918
Wo àwọn òṣìṣẹ̀ ìjọba tó ń gba owó ju ààrẹ lọ lórílẹ̀èdè Nàìjíríà
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01919
Portable bori ọta ẹ, o fẹṣẹ da batani si oṣere tiata yii lara
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01920
"Kemi Afolabi Adesipe: Oṣù kan ni mo fi gba ""Oxygen"" àmọ́ síbẹ̀ Olúwa dára!"
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01921
Nitori Sunday Igboho, ijọba fẹẹ fofin de ẹgbẹ Ilana Ọmọ Oodua, wọn fẹẹ kede ẹ bii ẹgbẹ afẹmiṣofo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01922
Gbogbo eͅnu la fi sóͅ pé a wà léͅyìn Peter Obi fún ààreͅ lóͅdún 2023 – Aféͅniféͅre
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01923
‘Ko sohun to maa di Atiku lọwọ, yoo dije pẹlu Tinubu lọdun 2027’
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01924
Makinde fẹẹ fi awọn to n tọrọ baara to ko kuro loju titi n’Ibadan sẹnu iṣẹ
0
0
0
1
0
1
yor
yor_train_track_a_01925
Sagamu Interchange - Ìjọba yóò ti afára Sagamu pa nítorí ìjàmbá iná
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01926
Godwin Emefiele: Mo bẹ́ orí fún gbogbo àgbẹ̀ àti olùfọkànsìn tó ń dáwó fọ́ọ̀mù Ààrẹ fún mi àmọ́ ẹ jẹ́ n lo óògùn ara mi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01927
Farmers-Herdsmen Clashes in Oyo: Àwọn afurasí Fulani mú ọ̀kan lára ọwọ́ fijilańté tí wọn gé lọ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01928
Sunday Igboho: Agbẹjọ́rò Igboho ní ìjọba Benin kò tíì rí ẹ̀sùn ọ̀daràn kankan fi kàn án láti oṣù mẹ́ta tó ti wà lẹ́wọ̀n
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01929
Ajọ Yoruba Agbaye fẹẹ ran ijọba apapọ lọwọ lori fifi ede abinibi kọ awọn akẹkọọ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01930
Ajinigbe koju ọlọpaa n’Ibeṣe, wọn pa ẹni kan, wọn ji eeyan meji gbe, ọlọpaa pa meji ninu awọn naa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01931
Sexual abuse: Ọkùnrin méjì dèrò àtìmọ́lé lẹ́yìn tí wọ́n fipá bá ọmọ alábágbé wọn tó jẹ́ ẹni ọdún 16 lòpọ̀
0
1
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01932
Lekki free toll: Àwọn ará ìpínlẹ̀ Eko kan sárá sí Sanwoolu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01933
Mi ò figbà kankan gbèrò láti ló sáà kan síi lórí ipò, ẹni tó dán an wò rí hmmn... – Ààrẹ Buhari
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01934
Abdulazeez Olajide Adediran Jandor: O ṣeni láànú pé owó Eko kò ṣiṣẹ́ fún ará Eko
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01935
Wọn ti sinku Hadiza, iyawo Oloogbe Shehu Shagari, ti Korona pa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01936
Ṣeun Kuti di afadura-jagun lahaamọ, Daddy G.O ni wọn n pe e bayii
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01937
Tírélà ti gba àárín èmi àti Ooni Ogunwusi rí àmọ́ ohun tó ṣẹlẹ̀ rèé - Olori Tobi Phillips
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01938
Emi ni ma a kẹsẹ bọ bata Buhari gẹgẹ bii aarẹ Naijiria lọdun 2023-Tinubu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01939
Ọmọ ọdun mọkandinlogun yii ba iyawo oniyawo lo pọ, lọkọ ba gun un pa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01940
Eto idibo to daa ju ninu itan orileede yii nijọba Buhari ṣe lọdun – Adeṣina
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01941
Ọdun Iṣẹṣẹ: Gomina Oyetọla kede ọjọ Ẹti gẹgẹ bii isinmi lẹnu iṣẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01942
Wo ìlú kan ní Italy tó ṣetán láti fún ọ ní N13.6 mílíọ̀nù tí o bá gbà láti gbé níbẹ̀
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01943
Diezani gan an ní Hushmummy tó ń bú àwọn Yahoo boys- Àwọn Ọmọ Naijiria lórí Twitter
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01944
Ipo Aarẹ ti mo fẹẹ du yii, lati kekere ni mo ti ni in lọkan – Tunde Bakare
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01945
SARS: Ileeṣẹ ọlọpaa ko san aadọta miliọnu tile-ejọ ni ki wọn san fun mi latọdun 2016 – Bankọle
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01946
Ibudo itọju arun Covid-19 Kwara jona, ọpọlọpọ dukia lo ṣofo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01947
Usman ṣa ọlọkada ladaa yannayanna, lo ba ji ọkada rẹ gbe sa lọ
0
1
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01948
Bishop Oyedepo: Ifedayo Olarinde tó ń jẹ́ Daddy Freeze tọrọ àforíjì pé o sọ ọ̀rọ̀ ẹ̀gbin sí David Oyedepo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01949
Alaga APC, Adamu, ni Ahmed Lawan lẹgbẹ awọn fa kalẹ funpo aarẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01950
2023 Presidential Election: Mí o búwọlu ìdupo ààrẹ ọdún 2023 fún Tinubu-Foluke Daramola
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01951
Gomina Abdulrazak gbe igbimọ ti yoo yanju aawọ Ọffa ati Ẹrinle kalẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01952
Nitori bi nnnkan ṣe ri nita, Portable olorin pin ounjẹ fawọn eeyan
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01953
Nigeria Independence Day: Aráàlú fa ìbínú yọ lórí ọ̀rọ̀ tí Buhari sọ fún àyẹyẹ òmìnira
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01954
Sunday Igboho sọrọ lati Kutọnu: Ẹ jẹ ka para wa pọ, ka gba ilẹ wa lọwọ awọn eeyan yii ko too pẹ ju
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01955
Ẹgbẹ onimọto Ọyọ: Makinde yan Ọmọlẹwa, Tokyo, Ejiogbe rọpo Auxiliary
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01956
Ẹ wo David to n pera ẹ lọlọpaa, aṣe igbo lo n ta l’Alaba
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01957
‘Ko sohun ti APC ko fi ni i wọle ibo 2023, gbogbo aye lo ri i pe iṣejọba Buhari peregede’
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01958
Ghana couple buries son alive: Ọkọ àti ìyàwó ri ọmọ ọdún kan àbọ mọlẹ láàyè
0
1
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01959
Olukọ meji, akẹkọọ mẹjọ, lawọn agbebọn tun ji gbe nileewe kan ni Kaduna
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01960
Niṣe lawọn eleyii maa ṣe bii ero ọkọ, foonu awọn ero ni wọn maa n dọgbọn ja gba
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01961
Ladọja atawọn agba ijoye Ibadan ti yan Balogun gẹgẹ bii ọmọ oye Olubadan
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01962
Ọkunrin yii fẹẹ ji tiransifọma adugbo tu, lo ba gan pa!
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01963
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ Páṣítọ̀ tó lu ìyàwó rẹ̀ pa, tó tún sin òkú rẹ̀ sílé wọn
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01964
Ọmọ ọdun mejila ti wọn ji ifun inu rẹ lasko iṣẹ abẹ ti ku
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01965
Awọn ọdọ adugbo dana sun ọkunrin kan, wọn lo ji ọmọ araadugbo awọn gbe Amuloko, n’Ibadan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01966
Ilé ti sú ọmọ mi torí ìdaṣẹ́sílẹ̀ ASUU ló ṣe lọ ṣiṣẹ́ nílé ìtura, tó fi pàdé ikú òjijì - Màmá Rachel Opadele
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01967
Ileeṣẹ ọlọpaa kilọ fawọn ọdọ: Ẹ ma daṣa ‘ma gba fẹnikẹni mọ’, o le da rogbodiyan sile laarin ilu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01968
A fara mọ bi Peter Obi ṣe lọ si ile-ẹjọ to ga ju lọ-Ẹgbẹ Afẹnifẹre
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01969
Gender discrimination: Ó pakasọ! Wo ìdí tí àgbẹ̀ kan fi kọ ìyàwó rẹ̀ tó bí ìbẹta sílẹ̀
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01970
Seyi Makinde: Ọmọ ẹgbẹ́ PDP Oyo tó bá ń bínú, ẹ kó mo kó mo rò yín wá ká yanjú ẹ̀
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01971
Idi ti mo fi ṣedasilẹ ‘Alternative High School’ fawọn ọmọbinrin l’Ọṣun -Rẹmi Tinubu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01972
Buhari fọwọ si i ki ipo aarẹ lọ si iha Guusu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01973
Osogbo JTF vs Youth Protest: Àwọn ẹbí Idris Ajibola ń fẹ́ ìdájọ́ lórí ikú ọmọ wọn
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01974
Akure Lady Suicide: A kò ní ṣe ìwádìí kankan lórí òṣìṣẹ́ Shoprite tí wọ́n ló gba ẹ̀mí ara rẹ̀ nílùú Akure-Ọlọ́páà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01975
BBC Komla Dumor Award 2022: Iléeṣẹ́ ìròyìn BBC ṣe ìfilọ́lẹ̀ àmì ẹ̀yẹ Komla Dumor
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01976
Dejo Tunfulu: Àwọn ọmọ olòógbé ní àwọn dókítà kò kọbi ara sí ìtọ́jú rẹ̀, ló tètè ṣekú pa á
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01977
Bi Kinsley ṣe fẹẹ wọn ṣọọṣi ni Festac lawọn agbebọn ji i gbe lọ l’Ekoo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01978
Kegel: Eré ìdárayá tí àwọn onímọ̀ sọ pé ó n fikún adùn ìbálòpọ̀ fún obìnrin, tó tún n fún ọkùnrin ní agbára
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01979
EndSARS Protest: Ojú àwọn ọmọ Nàìjíríà tí yóò farahàn níwájú adájọ́ rèé
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01980
World suicide prevention: Iye àwọn tó ti gbẹ̀mí ara wọn rèé láàrin ọdún mẹ́rin ìjọba Buhari ní Nàìjíríà rèé
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01981
Kwara: Wọn ti ọsibitu ile ijọba pa nitori iku Aminu Logun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01982
Awọn oṣiṣẹ banki to gbowo nla jade lakaunti onibaara ti rẹwọn he
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01983
Classroom collapse on pupils in Ogun: Muinat Ilebiyi gbẹ́mìí mì lójú ẹsẹ̀, ipò táwọn méjì tó kù wà rèé
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01984
SERAP sues Buhari: Àjọ SERAP gbé Ààrẹ Buhari lọ sílé ẹjọ́ nítorì kò wádìí N3B tó pòórá níléèṣẹ̀ ètò ẹ̀náwó
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01985
Atiku, PDP fẹ́ ṣàbèwò sí Wike láti parí aaáwọ̀ nínú ẹgbẹ́ náà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01986
Igbimọ to n ṣewadii ẹsun awọn ti SARS fiya jẹ pari ijokoo wọn lẹyin ọdun kan
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01987
PDP ni ki Buhari fi ọrọ ti Aarẹ ilẹ Amẹrika ti wọn ṣẹṣẹ dibo yan sọ kọgbọn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01988
Ọlọpaa le awakọ yii sẹnu ọkọ BRT, ni wọn ba lu u laludaku
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01989
Ni bayii, lọọya Naijiria le ṣiṣẹ ni UK, gẹgẹ bi ti UK naa ṣe ti le ṣẹ ni Naijiria
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01990
Dapọ Abiọdun gbe aba iṣuna 2022 lọ sile-igbimọ aṣofin Ogun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01991
Ọwọngogo Naira: Alaboyun ku nitori ọkọ rẹ ko rowo gba ni banki lati tọju rẹ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01992
Yoruba Language: BBC Yoruba ń gbìyànjú kí èdè má parun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01993
Ọwọ tẹ awọn ọrẹ mẹta yii, ẹya ara oku ni wọn ba lọwọ wọn l’Ekoo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01994
Díẹ̀ lára ìgbà tí Amotekun ti mú àwọn afurasí ọ̀dàrán ní Ondo
0
0
0
0
0
0
yor