id
stringlengths
23
24
text
stringlengths
3
4.68k
anger
float64
0
1
disgust
float64
0
1
fear
float64
0
1
joy
float64
0
1
sadness
float64
0
1
surprise
float64
0
1
language
stringclasses
28 values
yor_train_track_a_01795
Poor roads in Ekiti state: Femi: Ká yọ tòṣèlú kúrò, Fayemi, àwọn òpópónà Ekiti ti di ẹgẹrẹmìtì, Babafemi Ojudu làá mọ́ Gómìnà Fayemi
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01796
Kílódé tí ẹnu ń kun Seyi Makinde lórí ìpolongo ìbò tí Peter Obi fẹ́ ṣe ní'badan lónìí?
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01797
Ọba tuntun jẹ ni Lafiagi
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01798
Bàbá mi wà nínú ilé tí wọn sun di eérú, ń kò mọ̀ bóyá ó jóná mọ́lé ni tàbí wọn ji gbé lọ - Aṣòfin
0
0
1
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01799
Eyi lohun tileewe Fasiti KWASU sọ nipa akẹkọọ wọn to dawati
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01800
Peter Obi wọle ni ibudo idibo akọkọ ni Aso Rock
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01801
Ẹ wo Jimọh to ṣẹyun fọmọ aburo ẹ lẹẹmeji l’Abẹokuta, o tun ti fun un loyun ẹlẹẹkẹta
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01802
Ijọba, ẹgbẹ oṣiṣe fọwọ si owo oṣu tuntun l’Ekiti
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01803
Abidemi ko janduku lọ sileewe nitori ọmọ ẹ ti olukọ ba wi, wọn fẹẹ ṣa tiṣa naa pa l’Abẹokuta
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01804
Boko Haram: Oluwatobi Adeigba, Ọkọ mi ń lọ siṣẹ́ fún àjọ INEC ló kàgbákò ikú - Opó Adeigba
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01805
Eyi nidi ti Makinde fi rọ ọba Ibadan yii loye
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01806
India: Ẹ wo ọmọ tuntun jòjòló tí wọ́n gbé sin láàyè nínú ìkòkò
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01807
A ko ni i ran awọn kan to n ṣaisan ninu wa lọwọ nitori…-Mr Latin
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01808
Students attack Police: Ìjà ní DPO wà parí láàrín àwọn akẹ́kòó ilé ẹ̀kọ́ gírámà kí wọn tó fí oko fọ lórí
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01809
Delta Accident: Orí yọ dírẹ́bà ọkọ̀ tó jóná ráúráú ní Delta
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01810
Wumi Toriọla ṣile olowo nla, gbogbo aye lo n ki i ku oriire
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01811
Ibeji ọran! Ọwọ EFCC tẹ Taye ati Kẹhinde ti wọn n ṣe Yahoo
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01812
O ṣẹlẹ, babalawo ku sori iyawo pasitọ to gbe lọ sotẹẹli
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_01813
Sunday Igboho: Àwọn ẹgbẹ́ aláriwo tó gbìyànjú láti fún mi ní ówó gan, mo kọ̀ọ́- Agbẹ́jòrò Sunday Igboho
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01814
Ibrahim Chatta: Ó gba àwọn òṣèré tíátà nímọ̀ràn láti máa ṣaájò ẹgbẹ́ wọn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01815
Ọgbọn ẹgbẹrun Naira kere fawọn oṣiṣẹ, ilọpo meji rẹ ni agbalẹ mi n gba- Oshiomhole
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01816
Ṣé lóòtọ́ ni àwọn jàndùkú kọlu Atiku àti ikọ̀ ìpolongo rẹ̀ ní Borno?
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01817
Eyi ni lẹta tuntun ti Ọbasanjọ kọ si Buhari
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01818
LGBTQI in Ghana: Ààrẹ Ghana yarí pé ìjọba òun kọ́ ní yóò buwọ́lu ìgbéyàwó akọ sákọ àti abo sábo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01819
Ramon Abass Hushpuppi, gbajúmọ̀ oníjìbìtì rí ẹ̀wọn he ní America
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01820
O ma waa ga o! Ṣẹgun naa tun fipa ba ọmọ bibi inu ẹ laṣepọ l’Abẹokuta
0
1
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01821
Emi ki i ṣe ọmọ Maria o, ẹ ma fi mi we Jesu-Tinubu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01822
Abuja accidents: Àjọ FRSC ní ọ̀kànlélúgba èèyàn(201) ló dèrò ọ̀run nínú ìjàmbá ọkọ̀ l'Abuja
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01823
Fuel scarcity: SERAP kọ̀wé sí Buhari pé kó tan iná wádìí gbogbo owó tí wọ́n ti ná lórí ibùdó ìfọpo ní Nàìjíríà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01824
Cute Abiọla pin owo-oṣu rẹ akọkọ nipo oludamọran fawọn opo ati arugbo ni Kwara
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01825
Mattawale Bandits: Wo ìdí tí Gómìnà fí ní kí wọn yìnbọn pa ọlọ́kadà tó bá tápà sí òfin kónílé-ó-gbélé alẹ́
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01826
Adeyemi Olubunmi Crown: Láti ìgbà ti mo ti fún ọkọ mi ni ẹ̀bùn mọ́tò ni ìfẹ́ wa ti yàtọ̀
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01827
Iṣẹ́ yóò wà lọ́pọ̀ yanturu l’Ekiti tí mo bá di gómìnà - Adeyinka Ali, olùdíje ẹgbẹ́ APP
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01828
Olu Jacobs: Joke Silva sọ̀rọ̀ lórí ìlera ọkọ rẹ̀, ó ní ó ń bá àìsàn tó ń mú ni gbàgbé nǹkan ló ń ba jà
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01829
Wo àwọn asọ ìgbèyàwó àràmọ́ndà, kóo fojú lóúnjẹ òpin ọ̀sẹ̀
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01830
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ akẹ́kọ̀ọ́ tó mú ìbọn ìléwọ́ lọ ilé ìwé ni Cross River
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01831
Mourinho kò ọ́rọ́ rẹ̀ jẹ,o padà wá dì akọ́nimọ̀ọ́gbá tuntun fún ikọ̀ Tothenham
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01832
Nkechi Blessing: Àgbo tí yóò mú mi tíírín ti jẹ́ kí ìbàdí mi lọ sílẹ̀
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01833
OPC: Àwọn àgbà ilẹ̀ Yoruba ní OPC àti Boko Haram kò jọra, kí wọn má fi ewúrẹ́ wé ẹkùn
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01834
2023 Presidential Election: Wo Ìyá ẹni ọdún 102 tó fẹ́ díje du ipò Ààrẹ Naijiria lọ́dún tó ń bọ̀
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01835
Ijọba ipinlẹ Ekiti fun awọn ẹlẹwọn mejila lominira
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01836
Sheu Sani kò lu jibiti, irọ́ ńlá ní wọ́n ń pa mọ́ọ- Agbẹnusọ Shehu Sani
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01837
BBC Investigation on IPOB: Mọ̀ síi nípa IPOB tó ń gbé orí ayélujára dá rúgúdú sílẹ̀ nítorí ọ̀rọ̀ Biafra
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01838
Ọwọ tẹ Intercessor, ọkunrin to n ji iṣu awọn agbẹ wa ni Ṣaki
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01839
Violence against Women: Àlùfáà Joel Olugbenga: Bíbélì kò ní kéèyàn dúró títí ọkọ rẹ̀ yóò fi lù ú pa
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01840
Baba Ijesha in court: Iléẹjọ́ sún ìgbẹ́jọ́ Baba Ijesha di oṣu kẹ́jọ lẹ́yìn tí wọ́n fọ̀rọ̀ wá ọmọ́débìnrin tọ́rọ̀ kàn lẹ́nuwò
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01841
Ọkunrin yii gun iya ẹ lọbẹ pa, o lajẹẹ ni
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01842
Dino Melaye: Mo jẹ́ afọ́jú tẹ́lẹ̀, àmọ́ mo ti ríran pé wọn gba wa ni bí Buhari ṣe di ààrẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01843
Buhari ki Soludo, gomina Anambra tuntun ku oriire, o loun maa ṣiṣẹ pẹlu rẹ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01844
O ma ṣe o, kọntena kaṣu ja lu mọto oṣiṣẹ fasiti l’Ọṣun, oju-ẹsẹ lo ku
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01845
Ojodu accident: Ìjọba ti iléẹ̀kọ́ Ojodu pa, Ó ní àlàyé ohun tó ṣókùnkùn nípa ìjàmbà tírélà tó pa akẹ̀kọ̀ọ́ níbẹ̀ ńbọ̀ láipẹ̀
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01846
Awọn tọọgi da ipolongo ibo Jẹgẹdẹ ru l’Ọwọ, eeyan marun-un lo fara pa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01847
Akure Murder: Ọlọ́pàá bẹ̀rẹ̀ ìwádìí àwọn olólùfẹ́ yìí tí wọ́n bá okú wọn ní ilé ìgbọ̀nsẹ̀ wọn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01848
Nitori ti wọn lo ayederu iwe-ẹri, awọn alaṣẹ Kwara Poly le akẹkọọ mẹfa danu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01849
Aye ti waa bajẹ o! Wọn ba ọkan eeyan meji lọwọ Wasiu atawọn ọrẹ ẹ
0
1
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01850
NDLEA visa clearance: Ọwọ́ agbófinró tẹ obìnrin tó gbé 'cocaine' sínú ojú ara rẹ̀ l'Abuja
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01851
Koko iroyin: Ìjọ Àgùdà ni ẹ̀jẹ̀ pọ̀ ní Nàíjíríà, Àwọn asòfin gbára wọn lẹ̀sẹ́ l‘Ondo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01852
Awọn agbebọn kọ lu awọn oloye ilu Ọwọ, wọn pa ẹni kan, wọn ṣe ẹlomi-in leṣe
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01853
Ọrọ Ezekiel yii ki i ṣoju lasan o: Lẹyin to tẹwọn de lo tun lọọ ji ẹrọ amule-tutu gbe ni Sango
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01854
Awọn ọlọpaa lẹtọọ lati gbe ibọn, ki wọn le fi daabo bo araalu lọwọ ewu-Adamu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01855
Ijọba ipinlẹ Kwara fẹẹ gba ẹgbẹrun kan abọ olukọ siṣẹ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01856
Ẹ gbé àwọn Ahmed Idiris àti àwọn yòókù rẹ̀ lọ sí ọgbà ẹ̀wọ̀n Kuje- Adajọ Adeyemi Ajayi
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01857
Awọn mọlẹbi wolii Sẹlẹ ti ọmọọṣẹ rẹ dana sun n’Ileefẹ ni: Ẹ gba wa o, awọn oloṣelu kan ti fẹẹ doju ẹjọ ru
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01858
Yinka Ayefele: Ìrọ́ ni pé ń kò le ṣe bíi ọkùnrin, mò ń ta pútú dàadáa
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01859
Ẹ ba mi wa ṣọja to lu ọmọ mi pa jade o, Baba Yinka figbe bọnu n’Ileṣa
1
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01860
Aabọ owo oṣu Kẹwaa nijọba san fawọn ASUU
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01861
Uttar Pradesh: Èèyàn mẹ́tàlá jáde láyé léyìn tó wọ́n já sínú kànga níbi ayẹyẹ ìgbéyàwó
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01862
Nitori ikọlu Fulani, awọn gomina ilẹ Yoruba fẹẹ pawọ-pọ lori eto aabo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01863
Meje lara awọn janduku ti wọn fẹẹ fipa gba gareeji ti wa lakolo ọlọpaa l’Ọṣun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01864
Depression: Akẹ́kọ̀ọ́ Auchi Poly tó wà ni ND2 pokùnso ní ìpínlẹ̀ Edo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01865
Nigeria Bad roads: Àwọn obìnrin abúlé yìí ń pàdánù ọmọ látàrí òpópónà tó mẹ́hẹ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01866
O ti ṣẹlẹ, awọn ẹgbẹ Ajẹ lorileede Naijiria kilọ fun Ọṣinbajo, wọn ni ko ma dupo aarẹ
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01867
EndSars Protest: Ǹkan mẹ́ta ti Gómìnà Babajide Sanwo-Olu pinu fún àwọn ọlọ́pàá ìpińlẹ̀ Eko
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01868
Gani Adams ṣefilọlẹ ẹṣọ alaabo Oodua ni Kwara
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01869
Doctors‘ Strike: Àwọn dókítà tó ń woṣẹ́ níran ní UCH sọ̀rọ̀ lórí ẹ̀dùn ọkàn wọn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01870
Attempted Murder: Ọwọ́ sìkún àjọ ọlọ́pàá ba Wòlíì Akute, Pasitọ Ayodele Omope tó yìnbọn lu ẹní tó sá wọ ilé ìjọsìn rẹ̀
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01871
Lẹyin iku ọmọ wọn, Davido olorin ati Chioma ṣegbeyawo bonkẹlẹ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01872
Mike Ifabunmi, àwọn òṣèré Yorùbá kí BBC Yorùbá kú ayẹyẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01873
Lagos Rape: Bàbá fojú ba iléẹjọ́ lórí ẹ̀sùn pé ó fún ọmọbínrín rẹ̀ lóyún, ó tún ṣẹ́yún fún un!
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01874
Dino Melaye vs Iyabo Ojo: Sẹ́nétọ̀ ní lórí irọ́ ní ọ̀rọ̀ ìfẹ́ tí wọn ló wà láàrin òun àtàwọn òṣèré tíátà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01875
Igbimọ tijọba gbe kalẹ lori awọn ọmọ-kewu ti wọn fiya jẹ ni Kwara ni ọna ti wọn gba lu wọn ko daa
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01876
Badagry building collapse: Èèyàn mẹ́rin kú sábẹ́ ilé alájà kan tó dàwó ní Badagry
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_01877
Nitori ẹgbẹrun lọna ọgọrun-un Naira, Inuwa sọ ọrẹ rẹ loko pa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01878
Saudi Arabia: Jí foonu ọkọ rẹ̀ wò, kóo fi ẹ̀wọ̀n jura
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01879
Ọdẹ adugbo yii ti wọ gau, ẹwọn gbere ladajọ sọ ọ si
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01880
Ikọ Amọtẹkun mu afurasi ajinigbe l’Ekiti
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01881
Awọn gomina PDP pariwo: Owo tijọba Buhari n ya yii ti pọ ju o
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01882
Fulani deegun ẹja si wọn lọrun l’Ayetẹ, o ni pipa loun yoo pa Yoruba to ba gba ọna ile oun kọja
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01883
Domestic Violence: Obìnrin kan wọ gàù lẹ́yìn tó kan ìṣó mọ́ ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ lórí ní Enugu
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01884
Eji Gbadero: Ó pa Raji Oba nítorí ilẹ̀ nìjọba bá yẹgi fún un
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01885
Ma a pada sinu APC lẹyin ti mo ba di gomina- Adelabu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01886
Agbekoya Protest: Kò sí àtúnṣe òfin 1999, kò sí ìbò ní 2023
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01887
Lesotho vs Nigeria: Nàìjíríà lu Lesotho lu lálùbolẹ̀ mọ́lé wọn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01888
Ẹya yoowu to ba fẹẹ yapa kuro ni Naijiria n wa iparun ni-Pasitọ Iyunade
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01889
Mo kìlọ̀ fún àwọn ọmọ Naijiria ṣáájú ìbò 2015 pé rúgúdù ń bọ̀ àmọ́ wọn kò gbọ́nran – Oyedepo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01890
Assault on LASTMA officers: Ìjọba Eko tí ṣetán láti f'imú ẹnikẹ́ni tó bá tún fi ìyà jẹ òṣìṣẹ́ LASTMA dánrin
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01891
N5mílíọ̀nù ni Chidinma wọ́ kúrò ní àsùwọ̀n owó Usifo Ataga lọ́jọ́ tó kú – Óṣojúmikòró
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01892
Àṣírí tú! Ìlò ìyà ni wọ́n ń lo àwọn dókítà ọmọ Nàìjíríà tó ń lọ sí UK fún iṣẹ́
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01893
Gbogbo aburú tó bá fẹ́ ṣé ọmọ mi Isbae U, orí mi ni kó dà lé - Sir Kay sọ̀rọ̀ sílẹ̀
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01894
Abuja kidnap: ''N15m làwọn Fulani ajínigbé kọ́kọ́ bèèrè kí wọ́n tó gba N2.5m ọ́wọ́ wa l'Abuja''
0
0
0
0
1
0
yor