id
stringlengths
23
24
text
stringlengths
3
4.68k
anger
float64
0
1
disgust
float64
0
1
fear
float64
0
1
joy
float64
0
1
sadness
float64
0
1
surprise
float64
0
1
language
stringclasses
28 values
yor_train_track_a_01595
Church founders allegedly kill member in fellowship: Bí olùdásílẹ̀ ìjọ méjì ṣe sin òkú ọmọ ìjọ láì sọ f'Ọ́lọ́pàá
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01596
Ọlọ́pàá mú ọkùnrin tó dáná sun ọmọ ìyàwó rẹ̀ márùn-ún ní Ondo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01597
Gomina Oyetọla ko ẹṣọ Amọtẹkun jade l’Ọṣun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01598
Ojowu buruku: Iyaale ile la nnkan mọ ọkọ rẹ lori nitori to n ba obinrin mi-in sọrọ lori foonu
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01599
Iyabo Ojo: Tiwa Savage fun ní N500,000, àwọn míì fi màálù méjì, ọtí wáìnì ránṣẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01600
Lẹyin ọjọ mẹwaa nigbele, akọwe ijọba ipinlẹ Ọṣun bọ lọwọ arun Koronafairọọsi
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01601
Igbẹ́jọ́ lórí ikú Timothy Adegoke kọ̀ láti wáyé lónì, ohun tí wọ́n sọ fáwọn Akọ̀ròyìn rèé
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01602
Oduduwa Nation: Kunle Olajide ní kìí ṣe gbogbo ọmọ Yorùbá ló fara mọ ìyapa Nàíjíríà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01603
Akomolede BBC: Onírurú gbólóhùn léde Yorùbá àti irúfẹ́ gbolóhùn tó wà nínú èdè Yorùbá
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01604
Australia: Igbe ayekòótọ́ sàànfàní, ó kó olówó rẹ̀ yọ lọ́wọ́ ikú gbígbóná
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01605
Kwara Hijab Crisis: Ìjọbá ńi akẹ́kọ̀ọ́bìnrin Mùṣùlùmí le lo ìbòrí gẹ́gẹ́ bó ṣe ń wáyé l‘Eko, Osun, Oyo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01606
Ẹ gba wa o! Awọn Ibaruba Kwara n dunkooko mọ ẹmi wa – Igbimọ Yoruba
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01607
Mo ka iyawo mi pẹlu ale rẹ m’ori bẹẹdi ta a jọ n sun, mi o fẹ ẹ mọ-Ọṣundeyi
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01608
Ìgbéyàwó gbajúgbajà òṣèré tíátà, Yomi Gold tí forí sánpọ́n lẹ́yìn ọdún kan!
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01609
Aja ni ọkọ mi maa n fifẹ han si, ko bikita fun emi atawọn ọmọ, mi o fẹ ẹ mọ-Rashidat
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01610
Chris Oyakhilome: Wọn tí fòfin de iléeṣẹ́ ìròyìn Chris Oyakhilome lẹ́yìn tó sọ pé 5G lọ ṣokùnfà Coronavirus
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01611
Covid-19 vaccines: Gómìnà Gboyega Oyetọla, aya rẹ̀ Kafayat gba abẹ́rẹ́ àjẹsára COVID-19 ní ìpínlẹ̀ Ọṣun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01612
Afi ki wọn tun ibo yii di, ki alaga INEC si kọwe fipo silẹ- Okowa ati Datti
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01613
Femi Fani-Kayode's defection: Ẹgbẹ́ OPC s'òkò ọ̀rọ̀ ráńṣẹ́ sí Femi
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01614
Gomina Ọṣun fẹẹ pin irẹsi ọdun faraalu, o tun kede sisan owo-oṣu Kejila awọn oṣiṣẹ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01615
Nigeria movie industry: Àgbà òṣèré, Lere Paimo ní àìgbọràn ló ń da ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn òṣèrè sinimá láàmú
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01616
Buhari ko ṣe ohun aburu kankan nigba to fi wa nipo olori Naijiria- Garba Shehu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01617
Lady Peller: Ọjọ́ ni ọjọ́ tí idán yíwọ́ fún ọkọ mi lẹ́yìn tó gé mi sí méjì, mo kú tán
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01618
AstraZeneca vaccine: Ìdí tí orílẹ̀èdè Denmark àti Norway ṣe wọ́gilé abẹ́rẹ́ àjẹsára Covid-19 tí Naijiria sì ń gbà rèé
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01619
Olufon ti Ifon Murder: Àwọn agbébọn tó pá Olufon ti Ifon ti ṣe ohun èèwọ̀ ní ilẹ̀ Yoruba
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01620
Eyi nidi ti mo ṣe fidi-rẹmi ninu idibo gomina-Fọlarin
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01621
Wọ́n ti iléèwòsàn pa nítorí àwọn àlùjànú tó n fi ipá bá àwọn nọ́ọ́sì lòpọ̀
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01622
Oni POS ni Victor lu ni jibiti tọwọ fi tẹ ẹ n’llọrin
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01623
Jijẹ ọmọ Naijiria pe mi ju jijẹ ọmọ orilẹ-ede Olominira Yoruba lọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01624
Sunday Igboho: Mo ṣé iṣẹ́ mọkaliki ri, bẹ́ẹ̀ sì ní mò tí ṣiṣẹ́ aponmità kí n tó rìnnà ko oríire
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01625
Ogun Police: Bàbá fìdí ọmọ ọdún márùn ún jó sítóòfù gbígbònà, ó di aláàbọ̀ara torí ó jí ẹja
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01626
Eeyan mẹta ku, ọpọ fara pa, ninu ijamba ọkọ l’Akurẹ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01627
Awọn meji ku sinu kanga ti wọn n gbẹ l’Abẹokuta
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01628
O yẹ ki Aarẹ Tinubu dunaa-dura pẹlu awọn afẹmiṣofo ti wọn ronupiwada ni–Ahmad Yerima
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01629
Ọpẹ o! Wọn ti tu awọn ọmọleewe ti wọn ji ko ni Katsina silẹ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01630
O yẹ ki Tinubu fun awa naa nipo ninu ijọba rẹ- Miyetti Allah
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01631
Awọn ọdẹ dara pọ mọ awọn to n ṣewọde SARS l’Ọṣun, wọn lawọn yoo pese aabo fun wọn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01632
Ẹfun abeedi, inu ọkọ oju omi to n rin lọ loju agbami lobinrin yii ti bẹ sodo
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_01633
Sunday Igboho: Ẹgbẹ́ ọmọ bíbí Igboho ké sáwọn Alfa, Pásítọ̀, oníṣẹ̀ṣe láti ké pe Ọlọ́run pẹ̀lú gba ààwẹ̀ àti àdúrà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01634
Ọba tó lu ọkùnrin alásè fọ́ lójú torí ó bá Olorì jó lójú agbo fojú ba ilé ẹjọ́
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01635
Sanw-Olu ti dariji Funkẹ Akindele ati ọkọ ẹ, o ti fawe ẹwọn wọn ya
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01636
Dayo Kujore: Ọmọ olóògbé olórin Juju fi àidunnú rẹ̀ lẹ́yìn tó ní àwọn èèyàn kò kẹ́dùn pẹ̀lú ẹbí rẹ̀
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01637
Iru kileyi! Ẹyẹ abami to n ke lọganjọ oru ni Peter le lọ tile fi wo pa a patapata
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01638
Ọmọọba Ọlagunsoye Oyinlọla ṣọjọọbi, Alaafin ati Ọoni ki i ku oriire
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01639
Nitori ti wọn n gbe ohun ija oloro kiri lọna aitọ, adajọ sọ ọmọ ẹgbẹ okunkun meji sẹwọn n’llọrin
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01640
Ọ̀jọ̀gbọ́n Zainab, to na Ọlọ́pàá-bìnrin tó ń ṣọ́ ọ, dèrò ọgbà ẹ̀wọ̀n
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01641
Aisha Lawal: Ẹni tó kéde pé mo kú yóò rí ìbínú Ọlọ́run
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01642
Wọn ti ge owo ifẹyinti awọn gomina Eko ku si idaji, awọn aṣofin tun wọgile ile kikọ fun wọn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01643
Ojú ogun ni Nàíjíríà wà, ẹ máṣe jẹ́ ká tanra wa jẹ -  Adeboye
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01644
Sokoto Canoe Mishap: Baálẹ̀ abúlé pàdánù ọmọ 5 sínú ìjàmbá ọkọ̀ oju omi tó mú ẹ̀mí 28 lọ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01645
Lọjọ ayajọ ijọba tiwa-n-tiwa, ẹlẹwọn mejidinlọgbọn gba idariji nipinlẹ Ondo
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01646
Awọn agbebọn tun ji akẹkọọ fasiti meji gbe sa lọ  nipinlẹ Taraba
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01647
Nitori owo-ori (VAT) ati ofin ma fẹran-jẹko, awọn ọba ati gomina Oke-Ọya wọle ipade
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01648
Ẹgbẹrun marundinlọgọta naira la maa san fun oṣiṣẹ to kere ju lọ l’Ekoo – Sanwo-Olu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01649
Afẹnifẹre gboṣuba nla fawọn OPC ti wọn mu Wakili Isikilu to n da awọn eeyan laamu n’Ibarapa
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01650
‘’O yẹ ki Tinubu fi Truss ṣe awokọṣe, ko kọwe fipo silẹ’’
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01651
O ma ṣe o, awọn meji ku nibi ti wọn ti n ṣewọde SARS l’Akurẹ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01652
Awọn fijilante pa ajinigbe kan, wọn ri meji mu, wọn tun gba obinrin meji ti wọn ji ni Kwara silẹ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01653
Adejare Adeboye: Àwọn kan ní ṣé ọ̀nà láti gba owó oṣù àkọ́kọ́ lọ́wọ́ ọmọ ìjọ kọ́ ní ìkéde ààwẹ̀ ọlọ́jọ́ 63
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01654
Ọba tí wọ́n jí gbé láàfin rẹ̀ nípìnlẹ̀ Ondo gba òmìnira
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01655
O ma ṣe o, ijamba ọkọ akẹru paayan mẹrin l’Ọyọọ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01656
Gómìnà ìpínlẹ̀ Benue, Samuel Ortom ti parí ìjà láàrin akọ̀ròyìn Channels TV, Pius Angbo àti Ifeyinwa Angbo, ìyàwó rẹ̀
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01657
Oju ole ree: Lati ipinlẹ Anambra ni Chidi ati Obinna ti wa n ja ọkada gba l’Owode Yewa
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01658
Enìyàn mẹ́ta kú nínú ìjàmbá ọkọ̀ ní'lù Abuja
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01659
Biafra Day Celebration, May 30: Àwọn ajìjàngbara Biafra kéde ìsìnmi fáwọn Ibo láti ṣ'àyájọ́ Biafra
0
0
0
1
0
1
yor
yor_train_track_a_01660
EndSARS report: Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú tó kéré jù lọ nílé asòfin sọ pé ìjọba àpapọ̀ ní ẹjọ́ láti jẹ lórí ìpànìyàn Lekki Tollgate
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01661
Iya gbe miliọnu mẹta ti wọn fẹẹ fi ṣiṣẹ abẹ fọmọ ẹ sa lọ, lọmọ ọdun mẹta naa ba dagbere faye
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01662
Ṣọ́ọ̀bù alájà mẹ́ta tó wọ́ mú ẹ̀mí ènìyàn méjì lọ ní Abuja
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01663
Mothers Day: Adebunmi Adeyeye ní òun jẹ gbèsè gbọ́múléláńtà, ìdí iṣẹ́ kabúkabú ni òun ti ri san
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01664
Nitori to le maaluu kuro ninu oko irẹsi rẹ, Fulani ge ọwọ agbẹ ja bọ ni Kwara
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01665
Ọpẹ o, Olori Silẹkunọla Ogunwusi bi ọmọkunrin lanti lanti
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01666
INEC gbe orukọ awọn ti yoo dije funpo gomina nipinlẹ Ọṣun jade
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01667
Buhari, ma tun fakoko ṣofo mọ lati buwọ lu abadofin eto idibo-Awọn gomina PDP
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01668
Ọwọ tẹ Abednego ati ọrẹ ẹ ti wọn n fi ọkada jale l’Akurẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01669
‘Ọkọ mi ko le tẹna kanlẹ fun mi, iṣẹju meji pere lo maa n lo, mi o fẹ ẹ mọ o’
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01670
A maa ṣewadii ẹsun pe ọlọpaa ti wọn lu bajẹ ji apoti ibo gbe sa lọ- Ileeṣẹ ọlọpaa
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01671
Ki lo n ṣẹlẹ: Ijọba Buhari fẹẹ gba Amọtẹkun lọwọ awọn Yoruba!
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01672
Amọtẹkun mu Fẹmi ati babalawo ẹ, ọmọdebinrin kan ni wọn fẹẹ fi ṣogun owo l’Ekiti
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01673
Ọlalere fọlọpaa mu iyawo ẹ n’Ibadan,  o lo fẹẹ jalẹkun ile oun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01674
Ati Fayẹmi, ati Ojudu, ko sẹni kan to gbọdọ le ẹni kan kuro ninu APC
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01675
Wahala owo Naira: Awọn ọdọ fibinu dana sun banki meji, wọn ba dukia jẹ l’Ogun
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01676
Lassa fever: Ìjọba Eko ní akẹ́kọ̀ọ́ fásitì Ebonyi tó wá kẹ́kọ́ ìmọ̀ òfin, ní wọ́n bá Lassa lára rẹ̀
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01677
Afghanistan: Taliban gbé òfin kalẹ̀ lórí àwọn Obìnrin atọ́kùn ètò, bó ojú rẹ tóo bá fẹ́ ka ìròyìn bí bẹ́ẹ̀ kọ́.....
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01678
Wo àwọn orílẹ̀ èdè mẹ́wàá tí kìí ṣe ayẹyẹ ọdún tuntun ní January 1
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01679
Tọkọ-tiyawo to lu jibiti owo nla dero ẹwọn n’Ibadan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01680
Wọn ti mu dẹrẹba mọto to ko awọn ọmọ Naijiria mẹfa wọlu Libya fun okoowo ẹru
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01681
Ọṣun 2022: Ajọ eleto idibo gbe orukọ awọn ti yoo dupo gomina ati igbakeji wọn jade
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01682
Lẹyin ọdun kan aabọ ti wọn ti ti too geeti Lẹkki, wọn fẹẹ ṣi i pada
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01683
Akomolede ati Asa: Mọ̀ si nípa àwọn ọ̀nà tí Yorùbá ń gbà ran ara wọn lọ́wọ́
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01684
Ẹwọn n run nimu Ọladipọ, ile adiẹ lo ti fipa ṣe ‘kinni’ fun ọmọbinrin kan
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01685
Ọpẹ o, wọn ti ri awọn arinrinajo tawọn ajinigbe ji gbe loju-ọna Oṣogbo si Ibokun
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01686
Nibi ti Alabi ti n ko ọpọlọpọ ewurẹ to lọọ ji ko sinu apo ni wọn ti mu un  l’Akurẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01687
Ọpẹ o, wọn ti tu awọn akẹkọọ tawọn agbebọn ji gbe ni Kaduna silẹ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01688
Eyi ni irufẹ awọn akẹkọọ to lẹtọọ si eto ẹyawo tijọba gbe kalẹ – Tinubu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01689
Sylvester Oromoni: Mọ̀lẹ́bí Buruji Kashamu sọ̀rs sókè lórí ẹ̀sùn pé ọmọ rẹ̀ wà lára àwọn tó fìyà jẹ olóògbé
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01690
Osun spider man: Mo ń ṣe ìtanijí láti gbógunti ìdọ̀tí láwùjọ ló sún mi dé ìdí 'Spider-man'
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01691
Dandan ni ki APC bori ibo 2023, a o fẹẹ pẹjọ rara – Adamu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01692
Igbimọ olugbẹjọ da ẹjọ Jẹgẹdẹ nu, wọn l’Akeredolu lo yege
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01693
Nitori ti ko tọju ounjẹ saari fun un, baale ile lu iyawo ẹ toyun-toyun n’Ibadan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01694
Ibọn onike ni John fẹẹ fi gbowo lọwọ oni-POS n’Ikorodu tọwọ fi tẹ ẹ
0
0
0
0
0
0
yor