id
stringlengths
23
24
text
stringlengths
3
4.68k
anger
float64
0
1
disgust
float64
0
1
fear
float64
0
1
joy
float64
0
1
sadness
float64
0
1
surprise
float64
0
1
language
stringclasses
28 values
yor_train_track_a_01495
Ẹgbẹ oṣelu PDP Ọṣun lawọn ko ni i kopa ninu idibo ijọba ibilẹ ti OSIEC fẹẹ ṣe
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01496
Awọn Fulani ya wọ oko nla kan n’Ibadan, wọn ji ọmọ oloko gbe
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01497
Ẹfun abeedi! Sodiq gbẹmi ara ẹ, inu kanga lo bẹ si
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01498
Tiago Isola, akẹ́kọ̀ọ́ Fásitì Ibadan: Èdè Yorùbá dùn ún gbọ́ àti láti sọ, mo sì fẹ́ràn kí n máa sọ ọ́ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01499
Akeredolu ni kawọn akẹkọọ maa wọ aṣọ ilẹ wa lọ sileeewe l’Ondo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01500
Ọlọpaa ti ri Alaga ti wọn ji gbe l’Oke-Onigbin, nipinlẹ Kwara, gba pada
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01501
Damilola Olofingboyegun: Gbenga Olofingboyegun kò sí aàbò mọ́, ìrànlọ́wọ́ ni à n fẹ́ lórí ikú Gbenga Olofingboyegun
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01502
Ifá ti mọ ẹni tí yóò jẹ ààrẹ Naìjíríà pẹ̀lú iyì àti ìdùnnú - Àdìmúlà Ila Orangun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01503
Ko si aburu kankan laafin Ọọni o – Ọlafare
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01504
Atiku gba awọn gomina nimọran:Ẹ pe ipade apero apapọ funra yin, ẹ ma duro de ijọba apapọ mọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01505
Tegina Attack: A ti rí ọmọ ilé kéú 11 míì nínú àwón tí agbébọn jí gbé ní ìpínlẹ̀ Niger
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01506
Ojubọrọ ko ṣee gbọmọ lọwọ ekurọ, awa la fi wọn sipo, awa la maa rọpo wọn-Tinubu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01507
Laaarọ Mọnde ni Tunde lọọ digunjale l’otẹẹli l’Abẹokuta
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01508
Mo mọ pe ara n ni yin o, amọ ẹ dibo fun Tinubu ki iṣakoso wa le tẹsiwaju-Buhari
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01509
Visa free: Àwọn Orílẹ-èdè tí wọn fún ọmọ Nàìjíríá lánfàní ìwé igbeluu ọ̀fẹ́
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01510
Ẹ gba mi o, baba mi fẹẹ fi mi lọkọ ni tipatipa-Fatima
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01511
Ibo gomina l’Ekiti: Ṣẹgun Oni jawe olubori ni wọọdu rẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01512
Ohun tí a mọ̀ rèé nípá òṣìṣẹ́ FRSC tí wọ́n fẹ̀sùn kàn pe o fún aláboyún ní ìpá ní ikùn...
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01513
Awọn oṣiṣẹ eleto ilera l’Ọṣun ṣeleri lati fopin si dida abẹ fawọn ọmọbinrin
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01514
Amaechi ki Tinubu ku oriire, o ṣeleri atilẹyin fun un
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01515
Idi ti oludije fun’po aarẹ fi gbọdọ wa lati Aarin-Gbungbun Ariwa ilẹ wa ni 2023 ree-Baraje
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01516
Ekiti 2022: Esi idibo awọn araalu ni yoo sọ ẹni ti wọn fẹ nipo- Ẹlẹka
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01517
Muhammed gun iyawo ẹ pa lọjọ ọdun tuntun, o lo kọle lai sọ foun
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01518
Awọn ọna wa to ti bajẹ la fi ra mọto olowo nla fawọn aṣofin o – Sẹneeti
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01519
Ọlọpaa obinrin lawọn Fulani onimaaluu yii ji gbe o
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01520
Ero rẹpẹtẹ lẹyin Ọṣinbajo lasiko to ṣabẹwo si Ogbomọṣọ, Ibadan
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01521
Driving offence: Àjọ FRSC kìlọ̀ f'áwọn awakọ̀ tó máa tẹ fóònù lórí ìrin ní ìpínlẹ̀ Eko.
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01522
Àwọn dókítà ti ń káyà sókè torí ìlera Ọbabìnrin Elizabeth Keji
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01523
Alawada ni oṣiṣẹ to ba gba ipo tuntun lọwọ Oyetọla
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01524
Awọn akẹkọọ fasiti yii lu ẹlẹgbẹ wọn pa nitori foonu l’Ọyọọ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01525
Igbákejì olórí ẹgbẹ́ Ilana Ọmọ Oodua kọ̀wé fi ipò sílẹ̀
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01526
Yahaya Bello vs Tinubu: Joe Igbokwe ní ọmọdé kò lè ṣèjọba Nàìjíríà, Tinubu ló ní ìrírí jùlọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01527
Osun Hotel Murder: Ìyàwó Timothy Adegoke bú sẹ́kún pé àwọn kan ti ń fi owó lọ abúrò ọkọ òhun lórí ẹjọ́ yìí
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01528
Ẹ wo bí àwọn ọmọ Naijiria mẹ́ta ṣe fí ẹ̀mí wọn wéwu láti rin ìrínàjò lọ sí Spain
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01529
Corruption: Ìwádìí àjọ aṣèṣirò òde, NBS gbé e jáde pé àwọn ọlọ́pàá, adájọ́ àtàwọn aṣọ́bodè ló gba rìbá jùlọ ní Nàìjíríà
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01530
Ondo kidnappers: Àwọn agbébọn pa èèyàn méjì l’Akure, wọ́n ṣá ẹlòmíràn ní àdá lórí
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01531
Kakwenza Rukirabashaija: Òǹkọ̀wé tó dèrò àtìmọ́lé nítorí ó bú Ààrẹ lórí Twitter gba ìtúsílẹ̀
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01532
Terrorism in Nigeria: Ìjọba àná lo jẹ Nàìjíríà run lórúkọ ìgbógun ti ìgbésùmọ̀mí - Malami
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01533
Nilẹ Zambia, eeyan mejidinlọgbọn ko Koronafairọọsi ni kilọọbu kan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01534
Ọkùnrin tí kò wẹ̀ fún àádọ́ta ọdún kú ní ẹni ọdún 94
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01535
Christian Eriksen: Agbábọ́ọ̀lù Denmark, Christian Eriksen, tó dákú lórí pápá ti jí padà níléèwòsàn
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01536
Former NFF president dies: Ààrẹ NFF tẹ́lẹ̀ri Oneya jáde láyé lẹ́ni ọdún 73
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01537
Son Kills Father Over Chicken Head: Orí adìyẹ fà wàhálà láàrin Godwin àti bàbá rẹ̀ nípínlẹ̀ Ondo, ló bá ṣá bàbá rẹ̀ làdá pa
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_01538
Ẹ wo Tolu ọmọ Poli, wọn ni Aafa Yusuf ti fi ọmọ-odo lu u pa o
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_01539
OAU Ile Ife: Àwọn nǹkan tó ka akẹ́kọ̀ọ́ fásitì OAU Ile Ife, Emmanuel Adedeji láya ló mú kó gbẹ̀mí ara rẹ̀
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01540
Wọn yinbọn pa eeyan mẹta, awọn mi-in tun fara gbọta lasiko atundi ibo ile-igbimọ aṣofin Ekiti
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01541
Tinubu rọ awọn ara ilu oyinbo: Ẹ maa pada bọ wale, Naijiria ti daa ju bẹẹ ṣe ro lọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01542
El-Zakzaky: Buhari ló ní kí wọn pa mi, inú rẹ̀ kò sì dùn títí tó fi gbọ́ pé wọn ti sun ilé mi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01543
Video of student burnt in sokoto: Ìjọba Sokoto kéde òfin kóníléógbélé lẹ́yìn ìfẹ̀hónúhàn tó wáyé níbẹ̀
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01544
Kwara Hijab crisis: ìgbìmọ̀ olùwádìí bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ lórí ohun tó ṣokùnfà wàhálà hìjáàbù
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01545
Igbẹjọ Oyetọla/Adeleke: Kootu gba ẹrọ idibo ati iwe-ẹri awọn ileewe ti Adeleke lọ gẹgẹ bii ẹri
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01546
Bobrisky ní òun gba Ọlọrun gbọ́ ju bí àwọn èèyan ṣe lérò lọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01547
Anti-Open Grazing law: Gómìnà ìpínlẹ̀ Ondo buwọ́lu òfín máfi ẹran jẹko láàrín ìgboro
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01548
Civilian JTF: Kí ló mú aṣáájú Yorùbá tako ìgbésẹ ológun láti gbà ọdẹ́ ìbílẹ̀ JTF ṣiṣẹ ní Borno?
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01549
Emi nile-ẹjọ maa ni ki wọn bura fun sipo gomina ipinlẹ Anambra-Oludije ẹgbẹ APC
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01550
Bí wọ́n ṣe ṣàwárí òkú ọmọ ipínlẹ̀ Anambra kan nílé ìtura Bauchi rèé
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01551
Atiku na Tinubu nibudo idibo Buhari ni Katsina
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01552
Lagos Okada ban: Àwọn àkàndá ẹ̀dá ní àwìn làwọn gba kẹ̀kẹ́ táwọn fi ń jẹun
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01553
Eyi ni bi Cote D’Ivore ṣe gba ife-ẹyẹ bọọlu ilẹ Afrika!
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01554
Awọn janduku ja ile ẹru l’Apapa, gbogbo ounjẹ COVID-19 ni wọn n ko sa lọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01555
Ojowu ọkunrin lọọ ba ale ẹ ja nile ọti obinrin kan n’Ikọtun, ibẹ lo ku si
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01556
Eedi ree, ọlọkada yii gun ẹni to n la wọn nija pa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01557
Buhari bẹ awọn ọdọ: Ẹ ni suuru fun mi ki n fi ṣatunṣe si gbogbo ohun to n bi yin ninu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01558
Gbogbo ohun to ba gba la maa fun un lati ri awọn to pa Oluwabamiṣe-Sanwoolu
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01559
Ọwọ ọlọpaa tẹ ọmọ ọdun mẹtadinlogun to fun obinrin mẹwaa loyun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01560
Ijọba ibilẹ tuntun ti wọn kede nipinlẹ Ondo di wahala
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01561
Bamise Ayanwole missing lady in Lagos BRT: Awakọ̀ BRT jẹ́wọ̀ ohun tó ṣẹlẹ̀ tí Bamise fi di òkú lẹ́yìn tó wọ ọkọ̀ rẹ̀
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01562
Amitabh Bachchan: Òṣèré India, Amitabh Bachchan tó lùgbàdì ààrùn Coronavirus ti móríbọ́
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01563
2023 Election: Femi Falana ní òfin kò faàyè gba kí Goodluck Jonathan dupò Ààrẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01564
Irú ààbò tó wà ní Naijiria lásìkò yìí ló tì dara jù láti ìgbà díẹ̀ sẹ́yìn - Lai Mohammed
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01565
Aráàlú, ẹ nàka sáwọn agbébọn tó pa ọlọ́pàá, wọn kò ní lọ láìjìyà – Buhari
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01566
Ukraine- Russia Conflict: Mọ̀ síi nípa ipa tí àáwọ́ Ukraine àti Russia lè ní lórí owó epo àti àwọn akẹ́kọ̀ọ́ nílẹ̀ Afrika
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01567
Akeredolu gbe aba eto isuna ọdun to n bọ lọ siwaju awọn aṣofin
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01568
Twitter ban: Èrò ọmọ Naijiria ṣọ̀tọ̀tọ̀ lórí ìgbésẹ̀ ìjọba àpapọ̀ láti gbẹ́sẹ̀ kúrò lórí Twitter
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01569
Ooni of Ife: Oba Adeyeye Ogunwusi ṣẹ̀ṣẹ̀ fi ẹ̀bùn tuntun ta Olorì lọ́rẹ tán ní, ìfẹ́ wọn dúró, kò sí ìpínyà- Aàfin Oòdúà
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01570
Oúnjẹ alẹ́ lẹ́yìn aago mẹ́sàn án leè fa àrùn jẹjẹrẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01571
Ijọba apapọ kede Ọjọruu, Wẹsidee, bii isinmi lẹnu iṣẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01572
Ikoyi collapsed building: Sanwo-Olu ní ìjọba ìpínlẹ̀ Eko yóò ṣiṣẹ́ lórí àbọ̀ ìgbìmọ̀ olùwádìí ilé alájà 21 tó wó ní Ikoyi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01573
Nitori ẹgbẹrun mẹtadinlọgọta Naira to ji, adajọ ti ni ki wọn lọọ yẹgi fun fọganaisa kan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01574
Ilé ẹjọ́ dájọ́ ikú fún ọlọ́pàá tó pa awakọ̀ èrò nítorí N100
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01575
Akinyele Ibadan land crisis: Àwọn olùgbé Akinyele fí ẹ̀sùn ilẹ̀ gbígbà kan ìjọba ìpínlẹ̀ Oyo, ìjọba Makinde ti fèsì padà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01576
Gomina ipinlẹ Ebonyi, David Umahi, ṣabẹwo si Buhari, o loun naa fẹẹ dupo aarẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01577
Àwọn aya Yekeen Ajileye ló fa ìpinyà láàrin wa débi pé mo fẹ́ pa ara mi - Abija
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01578
Eyi le o! Obinrin yii ji ara ẹ gbe, o loun fẹẹ fi gbowo lọwọ ẹgbọn oun ni
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01579
Awọn alatilẹyin Tinubu lọ si ọfiisi INEC, wọn ni eto idibo ti wọn ṣe daa gan-an ni
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01580
Adeleke sọrọ soke: Ko si ohun to le gba ijo jijo lẹsẹ mi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01581
Ọpẹ o! Ọwọ ti tẹ awọn to pa olori awọn oṣiṣẹ ijọba ipinlẹ Ọyọ tẹlẹ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01582
Ile-ẹjọ to ga ju lọ buwọ lu lilo hijaabu lawọn ileewe nipinlẹ Eko
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01583
Omoniyi and Elizabeth Oke Blind Couple in Ado-Ekiti: Tọkọ-taya Oke ní Ọ́ba òkè ló fi àwọn dá àrà tó wù ú
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01584
Awọn agbebọn ya bo ṣọọṣi Sẹlẹ ni Mowe, wọn ji eeyan meji gbe lọ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01585
Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá pín aṣọ tuntun fún àwọn òṣìṣé
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01586
Babajide Sanwo-olu: Mo ti fi ọgbọ̀n ọdún ṣe iṣẹ́ púlọ́mbà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01587
Mọto pa ọmọ ọdun mẹwaa l’Ọṣunjẹla, lawọn araalu ba fẹhonu han
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01588
Ukraine crisis: Akẹ́kọ̀ọ́ ọmọ Ireland kan ṣì ń gbìyànjú ọ̀nà àti sá àsálà kúrò ní Ukraine
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01589
O ti deewọ fawọn Iya Ọṣun, Iya Ibeji ki wọn maa tọrọ owo ninu ọja-Iyalọja Kwara
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01590
O ma ṣe, awọn agbanipa da obinrin oniṣowo yii lọna, wọn si ṣa a pa l’Akurẹ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01591
Koko ni ara mi le, mo ṣetán láti sìn Nàíjíríà - Bola Tinubu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01592
Kidnapping in Nigeria: Arìnrìnàjò kan ṣàlàyé bí orí ṣe ko yọ lọ́wọ́ ajínigbé
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01593
Revolution Now bẹ̀rẹ̀ ní agbègbè Ojota ní ìpínlẹ̀ Eko
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01594
Peter Obi ṣabẹwo sawọn ti ṣọja ilẹ wa ju bombu fun, o fun wọn lẹbun owo
0
0
0
0
0
0
yor