id
stringlengths 23
24
| text
stringlengths 3
4.68k
| anger
float64 0
1
| disgust
float64 0
1
⌀ | fear
float64 0
1
| joy
float64 0
1
| sadness
float64 0
1
| surprise
float64 0
1
⌀ | language
stringclasses 28
values |
---|---|---|---|---|---|---|---|---|
yor_train_track_a_01295 | Ronke Odusanya: Àwọn olólùfẹ́ Ronke Odusanya Ìdídowó ti ń fọnmú lórí àṣẹ àyẹ̀wò DNA tí iléẹjọ́ pa lórí ọmọ tó bí fún Saheed | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01296 | Haiti earthquake pa èèyàn 304 ilé 1,800 bá ìṣẹ̀lẹ̀ ilẹ̀ rírì lọ ní haiti | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01297 | Abiola Ajimobi one year memorial: Yemi Osinbajo, Aregbesola, Ganduje péjú síbi ìrántí ọdún kan Ajimobi, wọ́n ní àwọn ń sàárò ọgbọ́n ìṣèjọba àti òṣèlú rẹ̀ | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01298 | Jumoke Odetola: Ọ́pọ̀ òṣèré koro ojú sí àṣehàn lásán lẹ́yìn ikú akẹẹgbẹ́ wọn, Williams Aanuoluwapo, Kumbalee | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01299 | Ondo Crisis: Aṣòfin Iroju Ogundeji, Favour Tomowewo àti Williams Adewale ń lọ rọọkún nílé | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01300 | Ọgbọn biliọnu Naira nijọba apapọ fawọn gomina lati yanju wahala ounjẹ to n fojoojumọ wọn-Akpabio | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01301 | Wòlíì Kasali sọ̀rọ̀ nípa awuyewuye pé ó lé ìyàwó rẹ̀ jáde nílé | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01302 | Nitori ibo Satide, ijọba kede Furaidee gẹgẹ bii ọjọ isinmi lẹnu iṣẹ l’Ondo | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01303 | Tshegofatso Pule: Ilé ẹjọ́ ní lóòótọ́ ọ̀rẹ́kùnrin olóògbé ló sanwó pé kí wọn pa aláboyún naá | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01304 | Àwọn afurasí ajínigbé bẹ́ orí kánsélọ̀ tó lọ dóòlà ará ìlú rẹ̀ tí wọ́n jígbé | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01305 | Nitori Bobrisky, ija nla bẹ silẹ laarin awọn oṣere tiata, epe ni wọn n gbera wọn ṣẹ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01306 | Ijó tí mo jó níwájú Ooni Ife ti ayé ń pariwo ẹ̀ kiri, N250,000 ni mo fi pa– Nkechi Blessing Sunday | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01307 | Ẹgbẹ oṣere Naijiria fawọn ọmọ Oloogbe Racheal Oniga ni miliọnu mẹrin naira | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01308 | Pius Adesanmi: Òní ni ẹ̀bí akọni Pius Adesanmi n ṣètò ìkẹyìn fún ogbontarigi náà | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01309 | Eyi lohun ti Gomina Adeleke ni kawọn oṣiṣẹ ijọba ṣe layaajọ ọdun Falẹntain l’Ọṣun | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01310 | Miliọnu mọkanla naira lawọn Fulani to ji awọn iyalọja gbe loju ọna Ọwọ n beere fun | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01311 | 21 years after Bola Ige's death: ọdún mọ́kànlélógún lẹ́yìn ikú Bola Ige, ìjọba kò tíì kéde ẹni tó yìnbọn pa á ní Ibadan | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 1 | yor |
yor_train_track_a_01312 | Awọn ọdọ fẹhonu han n’Ibadan nitori owo Naira ati epo bẹntiroolu, wọn ba dukia rẹpẹtẹ jẹ | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01313 | Yọmi Fabiyi bimọ ọkunrin, ni Tọpẹ Alabi ba rọjo adura le ọmọ tuntun lori | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01314 | Idibo wọọdu di wahala lẹgbẹ PDP l’Ọṣun, eeyan meji ku, ọpọlọpọ fara pa | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01315 | Alaga kansu fofin de ẹgbẹ onimọto, ọkada ati Marwa l’Ekoo | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01316 | Awọn oṣiṣẹ ijọba meji tọwọ tẹ lori ẹsun tita ọmọ were lọna aitọ ti foju bale-ẹjọ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01317 | Kayode Badru Death: ''Candle'' jó Kayode Badru pa lásíkò ètò àdúrà pẹ̀lú Wòlí rẹ̀! | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01318 | Ọọni atawọn ọba kaakiri Naijira wa l’Abuja bayii, Buhari ni wọn wa lọ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01319 | Ìyàwó: Ọkọ mi kúndùn ìbálòpọ̀ kọjá sísọ lẹ́yìn ìgbeyàwó ogun ọdún | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01320 | Auxillary Kidnap Attempt: Akọ̀wé ẹgbẹ́ PMS ní àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ọhún ni kò jẹ́ kí wọ́n rí Auxilliary gbé lọ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01321 | Olapade Agoro: Olùdíje dùpo aàrẹ Nàìjíríà rí, Owatapa ti Itapa Ijesha, Wolii Olapade Agoro jáde láyé | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01322 | Ilukulu bii ewure lawọn iyaale ile n lu ọkọ wọn bayii l’Ekoo | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | yor |
yor_train_track_a_01323 | 60 years married Benjamin Awoyemi: Ó dá mi lójú pé kò sí ẹni tí ọkọ mi ń ro ẹjọ́ mi fún | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01324 | Tinubu loun faramọ bi Sanwo-Olu ṣe fagile owo ifẹyinti awọn gomina Eko | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01325 | Atiku yoo ṣepade pẹlu awọn gomina marun-un tinu n bi ninu ẹgbẹ wa laipẹ -Okowa | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01326 | A ko fọwọ si awọn to n lọ kaakiri ileewe pe ki ominira wa fun ilẹ Yoruba- Ijọba Ọṣun | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01327 | Ọmọ Naijiria 350 ló dèrò ọ̀run nínú ìjàmbá ọkọ̀ ojú omi lọ́dún 2020 | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01328 | Gomina gboriyin fawọn obinrin to dawo kọ ileewe ni Kwara | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01329 | Korona burẹkẹ l’Ekoo, eeyan mẹfa ku, aadọrin le lẹẹẹdẹgbẹta tun ko o | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01330 | Akomolede ati asa Yoruba: Ẹ wá kọ́ nípa àpòtí ìṣura èdè wa lórí BBC Yorùbá | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01331 | Gbogbo awọn to ṣẹ mi ni mo ti foriji, ki awọn ti emi naa ṣẹ jọwọ, dariji mi – Dele Odule | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01332 | Ta bá fẹ́ rí ojú rere Ọlọ́run. Yorùbá gbọdọ̀ wẹ ara rẹ̀ mọ́ lọ́wọ́ ègún àti èpè - Akintoye | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01333 | Obinrin yii ji ọmọ gbe ni Nasarawa, lo ba gbe e sa lọ si Benue | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | yor |
yor_train_track_a_01334 | 'Bí ọ̀pọ̀ ọ̀dọ́ àti obìnrin ṣe forúkọ sílẹ̀ fún PVC kò wúlò tí ...' | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01335 | Ẹkọ ede Yoruba ti di dandan fun gbogbo akẹkọọ bayii- Fasiti ipinlẹ Eko | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01336 | Unilag shut down?: Àwọn aláṣẹ Fásitì UNILAG ti ibùgbé àwọn akẹ́kọ̀ọ́ pa torí ọwọ́jà Covid-19 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01337 | N kò gbà pé omi ló wọ́ ọmọ mi lọ, wọ́n pa á ni - Bàbá Daniel | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01338 | Ijọba mi yoo faaye gba awọn oniṣowo gbogbo nilẹ yii, ki okoowo wọn le burẹkẹ si i- Tinubu | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01339 | O ṣẹlẹ! Tiribuna yọ gomina Kano nipo, wọn ni APC lo wọle | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | yor |
yor_train_track_a_01340 | Ori ko eeyan mejidinlogun yọ lọwọ iku ojiji lasiko ti mọto ero gbina ni Kwara | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01341 | APC Presidential Candidate 2023: Oluwo ní kò sí ìṣọ̀kan láàrín àwọn ọmọ Yorùbá tó ń díje ní APC | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01342 | Àlàyé rèé lórí fọ́nrán fídíò tó ṣàfihàn ẹ̀kun omi lórí afárá Thirdmainland | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01343 | Eyi tun ga o, iyawo ọṣigin binu fi bileedi ge ‘kinni’ ọkọ rẹ danu | 0 | 1 | 0 | 0 | 0 | 1 | yor |
yor_train_track_a_01344 | Ko daju pe Tobi Amusan yoo kopa ninu idije ere sisa agbaye tawọn obinrin lọdun yii | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01345 | Sunday Igboho: Amòfin ní Benin Republic kò ní fa Igboho lé Nàíjíríà lọ́wọ́ torí àdéhùn ọdún 1984 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01346 | Wọn gun ọkunrin yii lọbẹ ni o, nile idibo l’Akurẹ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01347 | Kogi murder: Àwọn agbébọn ṣekúpa akẹ́kọ̀ọ́ tó wà nípele àṣekágbá ní fásítì Kogi | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01348 | Ọmọ Wasiu Ayinde di Oludamọran pataki si Gomina Sanwo-Olu | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01349 | Prince Philip: Ọkọ Ọbabìnrin Elizabeth ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ń gba ìtọ́jú lọ́wọ́ nílé ìwòsàn | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01350 | Sunday Igboho: Àwọn èèkàn ọmọ Yorùbá fárígá lórí ìkọlù ìgbà gbogbo sílé ajìjàgbara | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01351 | Buhari, ìhàlẹ̀ lásán ni ìdúnkòkò rẹ̀, a kò padà sí kíláàsì – ASUU yarí | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01352 | Man allegedly rapes girl: Ọlọ́pàà fi ṣìkùn òfin mú okùnrin tó bá ọmọ ọdún 17 lòpọ́, tí ọmọ náà sì padà kú | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01353 | Lẹyin ti wọn lu u bajẹ: Portable olorin figbe bọnu, ṣe o digba ti mo ba ku kẹ ẹ to gbeja mi ni | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01354 | Ẹ gbagbe nipa pinpin Naijiria, ẹ ja fun iṣọkan wa-Ọbasanjọ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01355 | Lori ọrọ Igangan, mo gba gbogbo ẹbi tẹ ẹ da mi, ṣugbọn iru ẹ ko ni i waye mọ-Makinde | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01356 | Girl Child Day 2022: Inú mi dùn pé ọmọ obinrin nìkan ni mo bi -Tawakalitu Olawale | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01357 | O ṣẹlẹ, ọmọọdun mẹtadinlogun gbe majele jẹ nitori owo ọga rẹ to ṣe baṣubaṣu | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01358 | Sunday Igboho: Ẹgbẹ́ YORNCA ní ìjọba ti kùnà lórí ìpèsè ààbò, Yorùbá fẹ́ ààbò nílànà ìbílẹ̀ | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01359 | Lasiko ti adajọ agba yii fẹẹ wọ kootu fun igbẹjọ lọ ṣubu lulẹ, o si ku patapata | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 1 | yor |
yor_train_track_a_01360 | Wọn ti ri i mu o, dẹrẹba to pa tọkọ-tiyawo sinu ile wọn l’Abuja | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01361 | Àwọn olówó Naijiria 5 tí owó wọn ju owó ìsúnná Naijiria lọ! | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | yor |
yor_train_track_a_01362 | Irọ lawọn ọlọpaa n pa, a o dana sun-unyan mọle ni Gaa Wakili, awọn ni wọn kọkọ yinbọn mọ wa – OPC | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01363 | O ti ṣẹlẹ! Lori ẹsun ikowojẹ, Tinubu gbaṣẹ lọwọ ọkan ninu awọn minisita ẹ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | yor |
yor_train_track_a_01364 | Bayern vs PSG: Haaland báwo? Mbappe ló dáná sun Bayern Munich ráúráú nílé wọn | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01365 | Seyi Makinde Defection: PDP ní ọ̀rọ̀ Fani-Kayode kò ṣé tẹ̀lé, asọ̀rọ̀ àná di bámíì ni | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01366 | Sunday Igboho: Bí ń kò bá jẹ́ èèyàn dáadáa, Ọlọ́run kò ní ṣe oun dáadáa fún mi | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01367 | Ladọja ṣabẹwo si Olubadan ilẹ Ibadan, eyi lohun tawọn mejeeji jọ sọ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01368 | Ohun táa mọ̀ lórí rògbòdìyàn tó wáyé ní ààfin Ikirun rèé | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01369 | Ààrẹ fí ọwọ́ òsì júwe ilé fún Mínísítà tó ń gba owó oṣù láì ṣiṣẹ́ | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01370 | #PantamiMustResign, Isa Pantami: Àwọn ọmọ Naijiria ń fẹ́ ìyọnípò mínístà fún ọ̀nà ìbáraẹnisọ̀rọ̀ nítorí ọ̀rọ̀ tó sọ nípa àwọn agbésùnmọ̀mí | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01371 | Awọn araalu binu dana sun afurasi ajinigbe mẹfa tọwọ tẹ | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01372 | Ọkunrin yii ti dero ọgba ẹwọn o, iyawo alajọgbele ẹ lo n ba ṣere gele | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01373 | Independence Day Nigeria: Lamido Sanusi gbóṣùbà fún ìjọba lórí bó ṣe yọwọ́ ìrànwọ́ epo | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01374 | Mọ̀ síi nípa Olaolu Martins ọ̀kan lára olùdásílẹ̀ ilé oúnjẹ Bukka Hut tó ṣáláìsí | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01375 | PTECSSAN vs MTN: Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ ń gbáradì láti gbéná wojú MTN, lórí bó ṣe ń ṣe àwọn òṣiṣẹ́ rẹ̀ ní Naijiria | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01376 | Awọn ẹlẹwọn mẹjọ ri idariji gba l’Ondo | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01377 | Ibrahim Babangida: Mo rọ àwọn adarí wa láti jẹ́ àwòkaṣẹ́ rere fún aráàlú | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01378 | Oṣere tiata ati tiṣa fipa ba akẹkọọ-binrin kan lo pọ l’Oṣogbo | 0 | 1 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01379 | Oludamọran Fayẹmi lori eto oṣelu kọwe fipo silẹ, o darapọ mo ẹgbẹ SDP | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01380 | Hassan Adesanya, Mr Success: Bọ̀ọ́lù ní mo fẹ́ gbá jẹun ṣùgbọ́n ẹ̀sẹ̀ mi kán ló sún mi dé ìdí àwàdà | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01381 | Awọn agbebọn lati ilẹ okeere ti gbakoso awọn ibi kan nilẹ Yoruba- Akintoye | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01382 | Coronavirus: Àjọ tó ń rí sí ìwọléwọ̀de ní kò s'áàyè f'ẹ́nikẹ́ni tó láárùn yí láti wọlé sí Nàìjíríà | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01383 | Akin gbe ọrẹbinrin rẹ lọ sile Kabiru, lẹyin to fipa ba a lo pọ tan ni wọn ge e si wẹwẹ l’Apomu | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01384 | Nigeria SWAT team, EndSars, End SWAT: Àfiwé owó oṣù ọlọ́oàá Nàìjíríà pẹ̀lú akẹgbẹ́ wọn lókè òkun | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01385 | Gani Fawehinmi: Agbẹjọ́rò àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọniyàn ni Nàìjíríà ti ọ̀rọ̀ tálákà jẹ lógún! | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01386 | Emi o yọ biliọnu marun-un kankan ninu aṣunwọ ijọba Ọṣun-Adeleke | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01387 | Nọọsi meji padanu ẹmi wọn l’Abẹokuta, awọn mẹwaa fara pa, dẹrẹba lo n tẹ foonu lori ere | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01388 | Ọpẹ o! Toyin Araham ti tun loyun, oun ati ọkọ rẹ n reti ọmọ keji | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01389 | Pasitọ wọ gau, ọmọ ijọ ni wọn lo lu ni jibiti | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01390 | Aarẹ Tinubu n lọ sorileede Equatorial Guinea, eyi lohun to fẹẹ lọọ ṣe | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01391 | Lẹyin bii osu meji to kọwe fipo silẹ, Abegunde ti tun pada sọdọ Akeredolu | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01392 | Eemọ, Pasitọ Ṣẹgun riran eke s’ọmọ ijọ rẹ, lo ba fi ọgbọn ba a sun karakara | 0 | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01393 | Adeleke fi ipilẹ ile awọn alalaaji lelẹ l’Ọṣun | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01394 | PDP governors'meeting: Àwọn gómìnà PDP ní Buhari ti dojú ọrọ̀ ajé Nàìjíríà rú, wọ́n ké sí ilé aṣòfin àpapọ̀ láti fọwọ́ sí abá ìlànà ìdìbò Electorral bill fúnra wọn | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
Subsets and Splits
No saved queries yet
Save your SQL queries to embed, download, and access them later. Queries will appear here once saved.