id
stringlengths
23
24
text
stringlengths
3
4.68k
anger
float64
0
1
disgust
float64
0
1
fear
float64
0
1
joy
float64
0
1
sadness
float64
0
1
surprise
float64
0
1
language
stringclasses
28 values
yor_train_track_a_01195
Pasitọ Ajayi n lọ sẹwọn ba a ṣe kọwe rẹ, ọmọ tẹnanti rẹ lo fipa ṣe ‘kinni’ fun
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01196
Ramadan: Oyetola rọ awọn Musulumi lati tubọ sun mọ Ọlọrun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01197
Seyi Makinde: Màá ṣa ipá láti mú káwọn aráàlú nígbẹkẹ̀lé nínú ìjọba mi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01198
Awọn eeyan n ba iṣẹ aje wọn lọ ni Kwara, ko si iwọde “June 12”
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01199
Twitter ban: Ó ti pé ọgọ́rùn ún ọjọ́ tí ìjọba ti f'òfin de Twitter
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01200
Ogun state lockdown update: 'Èèyàn 104 tó kó covid-19 ní ílééṣẹ́ kan ní Sagamu fihàn pé ààrùn náà ti wà láwùjọ'
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01201
Ammended Terrorism prevention Act: Ẹ̀wọ̀n gbére tàbíì dájọ́ ikú fún ajínigbé títí ẹ̀mí yóò fi bọ́ ni àbájadé òfin túntun lórí ìjínigbé
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01202
Malaysia Church: Ilé Ẹjọ́ fìdájọ́ lélẹ̀, Krìstẹ́nì lẹ́tọ̀ọ́ gẹ́gẹ́ bí àwọn Mùsùlùmí láti pe Ọlọ́run ní Allah
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01203
Adeleke gbọpa aṣẹ l’Ọṣun
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01204
Iskilu Wakili arrested: Ṣé èèyàn máa ń gba ìran ẹ̀ sílẹ̀ kó di ogun ní? - Oyo OPC
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01205
‘Bẹẹ ba tun ri mi nidii ole jija, ohun to ba wu yin ni kẹ ẹ fi mi ṣe’
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01206
Boko Haram sponsors: Àsírí èèyàn 96 tó n gbọ́ búkàátà ìgbésùnmọ̀mí ní Naijiria tú sí ìjọba lọ́wọ́
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01207
Ta lo n purọ: Owo dija silẹ laarin Gomina Makinde ati ileewosan UCH
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01208
Eeyan mẹrinla mi-in tun ko Korona ni Ọsibitu Ọlabisi Ọnabanjọ, ni wọn ba ti ẹka ayẹwo ibẹ pa
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01209
Iru ẹgbẹ APC to lagbara yii lo gbọdọ maa ṣakoso awọn ipinlẹ ni gbogbo Naijiria-Ganduje
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01210
Wisdom fi miliọnu mẹta owo ileeṣẹ ọga rẹ ta tẹtẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01211
Muri Thunder pada sọdọ Saheed Oṣupa, o ko si Oufimọ, ko si orin
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01212
Ẹ lọọ fọkan balẹ, ko ni i si ẹkunwo epo bẹntiroolu nilẹ yii mọ – Tinubu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01213
Baba Ijesha: Àwọn ọlọ́paàá àti àwọn agbẹjọ́rò kan ló fẹ́ gba owó, kí wọ́n to fi Omiyinka sílẹ̀
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01214
Gomina Akeredolu ati Arẹgbẹṣọla pari ija ọlọjọ pipẹ to wa laarin wọn
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01215
Awọn alaṣẹ Fasiti Ifẹ fa afurasi to pa akẹkọọ ẹgbẹ rẹ nitori foonu le ọlọpaa lọwọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01216
Lẹyin ti wọn pa ọlọpaa to n ṣọ wọn, awọn Hausa ji oyinbo mẹta gbe l’Ọṣun
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01217
Tinubu 2023 Presidency: Àwọn ìpèníjà tí Bola Tinubu yóò kojú nìyí nínú ìrìnàjò rẹ̀ lọ́dùn 2023
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01218
Osun Kidnap: Àwọn agbébọn ti jí àwọn arìnrìnàjò gbé ní ìpínlẹ̀ Osun
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01219
Ṣé àwọn ikọ̀ aláàbò tí ìjọba ìpínlẹ̀ dá sílẹ̀̀ lè tán ìṣòro ìpèníjà aàbò tí Nàìjíríà ń kojú?
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01220
Ikú tún ṣọṣẹ́! Àgbà òṣèré Yorùbá míì ti dágbére fáyé!
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01221
Ibo Ọṣun: Ile-ẹjọ Ko-tẹ-mi-lọrun yoo gba ẹtọ wa pada fun wa-Adeleke
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01222
Nigerian Senators deaths: Àwọn sẹ́nẹ́tọ̀ mẹ́rin tó jáde láyé ní Nàìjíríà láàrin oṣù mẹ́fà sẹ́yìn rèé
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01223
Ife-ẹyẹ agbaye:Morocco gbo ewuro soju Spain, wọn wọ kọta faina
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01224
Iya Ife: Said Balogun, Kemi Afolabi àtàwọn òṣèré míràn ń ṣèdárò Iya Ife tó fayé sílẹ̀
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01225
Yahaya Bello: Iléẹjọ́ tó ga jùlọ fòǹtẹ̀ lu Yahaya Bello, wọ́n da ẹjọ́ PDP àti SDP nù
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01226
"""Ẹsẹ̀ mí kẹ̀, ó dojú kọ ara wọn bíi pẹ́rẹ́gi, ìṣẹ́ abẹ kẹta ló mú kó nà padà"""
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01227
Òyìnbó lásán ni 'consequential adjustment' ẹ ò tún gbọdọ̀ gé owó oṣù ní ìpínlẹ̀ mọ́ - NLC
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01228
Ayo Ewebiyi Mama Oriki: Ọwọ́ Òbí, Ìjọba àti àwọn Ọba ni ìdágbàsókè Yorùbá wà lásìkò yìí
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01229
Violence against Women: Wo iye obìnrin lágbàáye tó ń kojú ìwà ipá, àti ohun tó ń ṣokùnfà ẹ̀?
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01230
Ọba ìlú àtàwọn mẹ́ta kàgbákò ajínigbé, ìbọn ba awakọ̀ wọn l'Ondo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01231
Aarẹ Buhari ṣafihan owo Naira tuntun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01232
Ẹ wo ohun ti Bimbọ Ademoye ṣe lẹyin to gbami-ẹyẹ adẹrin-in-poṣonu to daa ju lọ
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01233
Dino vs Adeyemi: Ìyàwó ni Adeyemi lágbo òṣèlú lọ́jọ́kọ́jọ́
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01234
Itajẹsilẹ to n ṣẹlẹ lojoojumọ le fa ibinu Ọlọrun fun Naijiria-Ẹlẹbuibọn
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01235
Oluwoo de ade fun Firdauz, Olori tuntun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01236
Àwọn ọmọ Nàìjíríà kò gbọdọ̀ gba PDP láyè láti ṣàkóso ọrọ̀ orílẹ̀ èdè yìí mọ́ - Tinubu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01237
Coronavirus in Nigeria: Àjọ ètò ìlera lágbayé, WHO kan sárá sí Nàìjíríà lórí aáyan ìdènà àrùn Corona
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01238
Àwọn àgbẹ̀ yarí fún ìjọba Ondo lórí bó ṣe ń ta ilẹ̀ oko wọn
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01239
Tanker Accident: Ọ̀pọ̀ èèyàn tó ń lọ sẹ́nu iṣẹ́ àti okoòwò ló tàn sílẹ̀
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01240
Wọn ji oṣiṣẹ banki ati awakusa gbe n’Ibadan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01241
Lẹyin oṣu kan aabọ, awọn oṣiṣẹ kootu ipinlẹ Ogun fagi le iyanṣẹlodi
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01242
Gowon gba Atiku ati Obi nimọran lori ẹjọ idibo aarẹ ti wọn pe
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01243
Akẹkọọ Fasiti Bowen jẹ ẹbun ọkọ ayọkẹlẹ ninu idije arokọ tijọba ipinlẹ Ọṣun ṣe
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01244
Awọn ileewe girama ijọba apapọ yoo wọle lọjọ kejila, oṣu yii
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01245
Ohun tí a mọ̀ nípa ìṣẹ̀lẹ̀ ikú ìyàwó adarí òṣìṣẹ́ ní ìlú Eko, Adedoyin Raliat Ayinde
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01246
Majek Fashek: Mọlẹbí nìkan ló péjú síbi ìsìnkú gbajúgbajà olórin reggae náà ní Amẹ́ríkà
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01247
Ẹni kan ku, ọpọ eeyan tun fara pa ninu ijamba ọkọ l’Ọba-Akoko
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01248
Insecurity in Nigeria: Ọba alayé rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí ìjọba láti dẹ́kun ìkọlù afurasí Fulani, kó tó di làásìgbò ńlá
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01249
Polio: Bàbá kọ abẹ́rẹ́ àjẹsára kí ọmọ rẹ̀ tó ní àìsàn polio!
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01250
Building Collapses In Lagos: Àlàyé lẹ́nu ará àdúgbò níbi ilé alájà mẹ́ta dàwó l'Eko
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01251
Ni Iragbiji, awọn adigunjale kọlu banki Wema
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01252
Lagos bulding collapse: Mo gbàdúrà kí Ọlọrun tu gbogbo ẹbí Osibona nínú - Abiodun
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01253
Akeredolu pasẹ pe kawọn ileewe maa kọrin ibilẹ Yoruba
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01254
Covid-19 Delta variant Update: Ẹ̀dà Delta Variant COVID-19 ń gbèrú síi ní Nàìjíríà, ìjọba àpapọ̀ ra abẹ́rẹ́ àjẹsára 176,000
0
0
1
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01255
Iru ki waa leleyii: Nibi ti olujọsin yii ti n gbadura lọwọ lo ti ṣubu lulẹ, to si ku patapata
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01256
Amọtẹkun ja wọ ibuba awọn ajinigbe l’Ọyọọ, wọn ko awọn nnkan ija wọn lọ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01257
Manu Dibango: Covid-19 ti pa akọni afúnfèrè Sax ilẹ̀ Africa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01258
Awọn ọba alaye tuntun gbọpa aṣẹ l’Ondo
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01259
Suicide in Lagos: Bí iléeṣẹ́ pàjáwìrì RSS dènà ọkùnrin tó fẹ́ kó sí ''lagoon'' ní Eko ní ọjọ́ ìbí rẹ̀
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01260
Wahala ni Muṣin, ọlọpaa atawọn ọmọọta koju ija sira wọn
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01261
Awọn lọọya mẹta gba kootu lọ, wọn ni ki INEC wọgi le Tinubu, Atiku ati Obi gẹgẹ bii oludije
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01262
Ijọba apapọ ni kawọn akẹkọọ wọle lọjọ Aje to n bọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01263
Coronavirus Update: WHO tí kéde pé Ó ṣeéṣe kí àrùn Coronavirus tànkálẹ̀ gba inú afẹ́fẹ
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01264
Domestic Violence: Ǹkan mẹ́jọ tó máa kọ́kọ́ ṣẹlẹ̀ kí olólùfẹ́ méjì tó pa ara wọn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01265
Ọṣun Oṣogbo: Wọn lu fijilante lalubami nitori to gba ọmọ OPC loogun
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01266
Domestic Violence: Ṣe lóòtọ́ ni pé àwọn obìnrin máa n lù ọkùnrin nínú ilé gẹ́gẹ́ bi olólùfẹ́
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01267
Yoruba Nation One million man march: Àwọn tó ń ṣagbátẹrù Yorùbá Nation ní IPOB kò ṣiṣẹ pọ̀ pẹ̀lú àwọn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01268
Twitter ban in Naijiria: Ìjọba Nàìjíríà ṣàlàyé ibi tí ìjíròrò pẹ̀lú Twitter dé dúró àti ìgbà tó ṣeéṣe kí Twitter padà sẹ́nu iṣẹ́ ní Nàìjíríà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01269
Aṣiri tu, eyi nidi ti ijọba orileede Benin fi ju Sunday Igboho sọgba ẹwọn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01270
Ọwọ ọlọpaa tẹ ogbologboo adigunjale meji to n yọ wọn lẹnu n’llọrin
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01271
Dare Adeboye, #PDee àti #NotTodaySatan, I'm not leaving God: Ẹ wo bí Leke Adeboye, àwọn ọ̀dọ́ ìjọ RCCG ṣe gẹ irun wọn láti bú ọlá fún olóògbé Dare Adeboye
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01272
Awọn eleyii ti rẹwọn he o, owo Naira tuntun ni wọn n ta n’llọrin
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01273
Eeyan kan dero ọrun nibi ija agba awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun n’llọrin
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01274
Ohun akọkọ ni lati ṣatunṣe siwee ofin ilẹ wa ti mo ba di aarẹ Naijiria-Atiku
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01275
Alarafa tuntun, Mercy Aigbe ti lọ si Mecca o
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01276
Ẹ yee maa fenu tabuku Naijiria lori ayelujara- Fagbemi
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01277
Yoruba film: Obìnrin tó bá ń gbé bùkátà kò l'ọ́kọ kódà kó wà nílé ọkọ - Kemi Afolabi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01278
Akẹkọọ ki olukọ rẹ mọlẹ ni Fasiti Ilọrin, o lu u bii aṣọ ofi
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_01279
Ẹni ọdún 27 tó ṣá bàbá rẹ̀ pa l'Ogun dèrò àtìmalé
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01280
Ọkùnrin kan dáná sun ìyàwó rẹ̀ dójú ikú l’Ogun
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01281
Ṣé lóòtọ́ ni àwọn ọmọ ogun Naijiria ń pa àwọn àgbẹ̀ nínú oko wọn nílẹ̀ Ibo?
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01282
YouTube ń polówó àwọn iléeṣẹ ńlá pẹlú àwọn fídíò ayédèrú ìwòsàn ààrùn jẹjẹrẹ
0
0
1
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01283
Wolii fun ọmọ Mohbad ni miliọnu mẹwaa Naira
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01284
Wo fídíò bí ayẹyẹ ìgbéyàwó Ọbabìrin Elizabeth ṣe wáyé lọ́dún 1947
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01285
Yoruba-Fulani crisis: Miyetti ní àwọn ò ní fààye gba kíkó oúnjẹ lọ sílẹ̀ Yorùbá
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01286
Awọn janduku dana sun ọfiisi INEC l’Abẹokuta
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01287
Eyi nidi ti mo fi fẹran lati maa ṣira mi silẹ-Zainab
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01288
Ikunlẹ Abiyamọ o, ina jo awọn ọmọde meji pa nipagọ ogunlende ti wọn wa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01289
Justice Mary Odili: Àwọn agbófinró ya bo ilé Onídájọ́ Mary Odili, àwọn ohun tuntun tó súyọ rèé
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01290
Ilorin accident: Èèyàn mẹ́sàn án jóná kọjá mímọ̀ nínú ìjàmbá ọkọ̀ nílùú Ilorin
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01291
Babatunde Olatunji: Alùlùgbayì ọmọ Nàìjíríà tó fìlù kojú ìdẹ́yẹsí ní Amẹ́ríkà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01292
Kenya Prisioners: Àwọn ẹlẹ́wọ̀n mórí lé ilé-ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn fún ẹ̀kúnwó owó oṣù ẹlẹ́wọ̀n
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01293
Olutoye: Ọmọ ọdọ̀ àgbà ni mí, kò sì yẹ kí èdè Yorùbá parun
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01294
Ọkọ mi ti fẹẹ fi lilu pa mi, adajọ, ẹ tu wa ka-Ayisat
1
0
0
0
1
0
yor