id
stringlengths
23
24
text
stringlengths
3
4.68k
anger
float64
0
1
disgust
float64
0
1
fear
float64
0
1
joy
float64
0
1
sadness
float64
0
1
surprise
float64
0
1
language
stringclasses
28 values
yor_train_track_a_01095
Ọrọ Sunday Igboho: A o ni i sọ iṣẹ ti a n ṣe lori ẹ sita, ṣugbọn a ko dakẹ rara – Afẹnifẹre
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01096
Bọjẹẹti 2021 ti dofin o, Aarẹ Buhari ti buwọ lu u l’Abuja
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01097
Dukia to to miliọnu meje naira jona raurau nibi ijamba ina to ṣẹle niluu Iwo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01098
Inu Awolọwọ ko le dun lọrun si bi Naijiria ṣe ri loni-in- Tokunbọ Awolọwọ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01099
Awọn ajinigbe ji arinrin-ajo mẹfa gbe ni aala ipinlẹ Ondo ati Ekiti
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01100
Ẹ fi papa iṣere Ilọrin sọri Rashidi Yẹkini- Pinnick
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01101
Fani Kayọde ni Sunday Igboho ti bẹ Ọọni, o lọrọ toun sọ ja bọ ni
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01102
APC Oyo: Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ní wọ́n ti sin oku aṣàájú olóṣèlú náà lọ́sàn-án Ọjọ́bọ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01103
Tinubu, awọn araalu ko ri ipa owo iranwọ epo tijọba rẹ n fun awọn gomina loṣooṣu o – TOM
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01104
Ile-ẹjọ faini DPO to lu telọ rẹ lalubami n’Ibadan
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01105
Nyesom Wike: Gómìnà Wike dá rúgúdù sílẹ̀ láàárín ọlọ́pàá, Sífú dìfẹǹsì lórí ẹsùn fàyàwọ́ epo rọ̀bì
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01106
Shebaby: Àwọn Eléégún ní òṣèré yóò kú láàrin ọjọ́ méje
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01107
Ṣoworẹ gbe awọn oloṣelu to n ra ẹrọ ata faraalu ṣepe
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01108
Ọkunrin yii gbe awọn ibẹta niyawo lọjọ kan naa, o ni wọn ti jọra wọn ju
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01109
Ọṣinbajo atiyawo ẹ dibo n’Ikẹnnẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01110
Òṣìṣẹ́ ètò ìlèra yóò jẹ́jọ́ lórí ikú Maradona
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01111
Nibi tawọn eleyii ti n digunjale lọwọ n’Iju-Ọta lawọn ọlọpaa ka wọn mọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01112
Ilé ẹjọ́ rán igbákejì Ààrẹ Argentina lẹ́wọ̀n ọdún mẹ́fà lórí ẹ̀sùn àjẹbánu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01113
BBC World: Iléeṣẹ́ BBC fi ètò tuntun lọ́lẹ̀ fún àwọn àkàndá
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01114
Wo bí Ife ṣe pa ara rẹ̀ lẹ́yìn tó dáná sún Bolu ọkọ rẹ̀ torí pé ó ká 'chat' pé obìnrin míì lóyún fún ún
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01115
Olùkọ́ Kano sọ abiyamọ sí ìbànújẹ́, Ó lu akẹ́kọ̀ọ́ ọmọ ọdún mẹ́sàn án pa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01116
National Sports Festival: Ìjọba àpapọ̀ ní kò sí ohun tó jọ pé ìdíje náà yóò párí l'Ọ́jọ́bọ̀
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01117
Ìdẹ̀rùn yóò báwọn ọmọ Nàìjíríà, tí Tinubu bá di Ààrẹ - Aisha Buhari
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01118
Babalawo to ni Iyabọ Ojo maa ku lori ọrọ Baba Ijẹṣa ti ku o
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01119
Military plane crash: Ọkọ̀ òfurufú tó kó ọmọogun méjìléláàdọ́rùn ún tó fẹ lọ́ kojú àwọn alakatakiti ẹsín já lulẹ̀
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01120
”A ko ni i gba ẹnikẹni laaye lati da ogun silẹ laarin ilu Ifẹ ati Mọdakẹkẹ”
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01121
L’Ọṣun, awọn janduku pa Qudus, wọn tun dana sun aafin
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01122
Gun control in Nigeria: Wo ọ̀nà márùn ún tí o lè gbà dábòbò ara rẹ lọ́wọ́ ìjàmbá!
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01123
Ẹ wo Wasiu atawọn ọrẹ ẹ, ipinlẹ mẹta ọtọọtọ ni wọn ti lọọ ja wọn lole ọkada
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01124
Jumoke‘s Death Trial: Ìyá olóògbé ní kíjọba gbé òkú ọmọ òun fún sílẹ̀ láti sín lẹ́yìn ọjọ́ pípẹ̀
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01125
Ọrẹ meji dero ẹwọn ni Kwara, ọrẹ wọn ni wọn lu pa nitori ẹgbẹrun mẹrindinlọgọta Naira
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01126
Latari akọlu awọn Fulani darandaran, awọn to n fẹhonu han ti geeti ṣẹkiteriati pa l’Ọsẹ
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01127
Ṣẹyin naa ti gbọ ohun to ṣẹlẹ laarin Funkẹ Akindele ati ṣọọṣi Sẹlẹ
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01128
Lagos: Àwọn olùgbé Kosofẹ́ figbe ta pé iná, bátírì, dígí, àti ẹ́ńjínì ọkọ̀ láwọn olè ń jí gbé lóru
0
0
1
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01129
52 year old man rapes daughter: Ọwọ́ tẹ bàbá ẹni ọdún 52 tó ti ń bá ọmọ rẹ̀ lòpọ̀ fún ọdún
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01130
Oyetọla ni ile-ẹkọ awọn olukọni agba niluu Ileṣa yoo di fasiti laipẹ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01131
Garba Shehu: Inú aráàlú kò dùn sí ìwọ́dé Yoruba Nation àti IPOB tó wáyé l‘Amẹ́ríkà
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01132
Ife-ẹyẹ idije Afrika poora ni Egypt
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01133
Eyi ni bi awọn kọsitọọmu ṣe gba ẹgbaagbeje ọmọ Naijiria lọwọ iku ojiji
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01134
Anthony Joshua vs Pulev highlights: Ẹ̀bùn ọdún Kérésìmesì ni àseyọrí Joshua lẹ́yìn tó na Pulev lálùbolẹ̀ - Dapo Abiodun
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01135
Ibadan Accident: Tírélà agbépo ṣekúpa ọmọ ìyá méjì àtàwọn mẹ́ta míì
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01136
Ọlọpaa gba eeyan mejilelogun silẹ lọwọ ajinigbe
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01137
Antonio Oladeinde Fernandez: Ìtàn ìgbé ayé ọmọ Naijiria to ni ọkọ̀ òfúrufú mẹ́fà àti owó ní báǹkì láwọn orílẹ̀-ède méje
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01138
Ijamba gaasi paayan mẹta n’Ishaga, ọpọ ile ati mọto lo jona
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01139
Adajọ sọ awọn ọmọ ‘Yahoo’ mẹwaa sẹwọn n’Ilọrin
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01140
Boya ni Dare ati Felix yoo bọ ninu okun adajọ o, awọn ọmọ keekeeke ni wọn fipa ba lo pọ l’Akurẹ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01141
Adajọ ju ọlọkada to lu ọlọpaa sẹwọn l’Ọsun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01142
Awọn aṣofin Ondo ti da awọn ẹgbẹ wọn mẹrin ti wọn yọ nipo pada
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01143
Ikú dóró! Wo bí àwọn ajínigbé ṣe pa òṣìṣẹ́ Hótẹ́ẹ̀lì tó jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ LAUTECH àti oníṣòwò lẹ́yìn tí wọ́n gba N5m
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01144
Kogi 2019: Àwọn ará ìlú sọ̀rọ̀ lórí ìrètí wọn lọ́wọ́ Yahaya Bello
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01145
Kulikuli ni Rianat fẹẹ lọ ra ti wọn fi pa a, ẹgbẹrun lọna ogun naira lawọn afiniṣowo ra apa ẹ l’Ọffa
0
1
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01146
Ìjàmbá ọkọ̀ mú ẹ̀mí èèyàn mẹ́fà lọ l’Ondo, mẹ́rin dèrò ilé ìwòsàn
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01147
Ọmọ́táyọ̀ Olútóyè: Àwọn ǹkan tó yẹ kí ẹ mọ̀ nípa Ọ̀jọ̀gbọ́n obìnrin àkọ́kọ́ nínú ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá lágbàyé
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01148
Eeyan mẹẹẹdọgbọn jona ku lasiko ti mọto akero meji fori sọra wọn
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01149
Nasarawa lecturer viral video: Ọlọ́pàá mú olùkọ́ fásitì Lafia tí òun àti ọmọ rẹ̀ já ọmọ obìnrin kàn sí ìhòhò
0
1
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01150
Richard Okorogheye death: Bí wọ́n ṣe rí òkú rẹ̀ nínú adágún omi ní UK lọ́sàán gangan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01151
Olubadan stool: Rashidi Ladoja ní àṣà ilẹ̀ Ibadan kò nó dàrú lórí òun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01152
Husand, wife kidnap baby: Tọkọtaya kó sí gbaga ọlọ́pàá fẹ́sùn jíjí ọmọ ọjọ́ mẹ́fà gbé
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01153
Awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun ṣa Quadri pa l’Oṣogbo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01154
Ondo state citizen killed in Jos: Ẹ̀gbọ́n tó jẹ́ arọ, bàbá tí kò lẹ́sẹ̀, ọ̀pọ̀ ìyàwó àti ọmọ ni àbúrò mi tí wọ́n pa ní Jos fi silẹ́ ní Ondo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01155
Eeyan meji pere ni mo ti fibọn mi pa lọdun yii, mo fi n daabo bo ara mi -Jẹmbẹ
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01156
Joy gun ọmọ ẹ to ṣẹṣẹ bi pa, o niyaa oun lo ni koun ṣe bẹẹ
0
1
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01157
Fasiti Ilọrin le akẹkọọ mẹsan-an danu, eyi lohun ti wọn ṣe
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01158
Pasito Kumuyi, olori ijọ Deeper Life, kọ Bibeli tuntun
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01159
Aarẹ Tinubu ti wọgi le awọn ileeṣẹ ijọba wọnyi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01160
Ikeja gas fire: Dúkìá sòfò níbi ti iná ti ṣẹ́yọ lágbègbè Sheraton ní Ikeja l'Eko
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01161
Awọn obinrin fẹhonu han lọ saafin ọba, ni wọn ba dana sun ile kabiesi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01162
Ondo Blocks price hike: Búlọ́kù N200 to di N400 ní ìpínlẹ̀ Ondo fẹ́ mú kí ìjọba àtàwọn olówò búlọ́kù tutọ́ sójú ara wọn
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01163
Lai, wá wi tẹnu rẹ lóri bílíọnu mẹ́jì àbọ owó DSO
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01164
Sanwo-Olu yan igbimọ ileeṣẹ to n ri si ọrọ ijọba ibilẹ tuntun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01165
PDP Primaries: Gbọ́ nkán tí ẹgbẹ́ PDP sọ nípa ìròyìn tó gbòde pé ìdìbò owó lọ́wọ́ ẹyìn nílẹ̀ ní wọn n ṣé l'Abuja
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01166
Minisita fọrọ awọn oṣiṣẹ, Ngige, loun ko dupo aarẹ mọ o
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_01167
Awọn araalu maa bẹrẹ si i jẹgbadun iṣẹ idagbasoke ti Aarẹ Tinubu n ṣe- Ganduje
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01168
Olubadan yoo gbalejo Ọṣinbajo, Tinubu atawọn ọmọ Yoruba mi-in
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01169
Nkechi Blessing: Gbajúmọ̀ òṣèré, Nkechi Blessing ṣàlàyé pé òun ti kán lu agbami ìfẹ́ míràn lẹ́yín ìjákulẹ̀ àjọṣepọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú Opeyemi Falegan
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01170
O ṣẹlẹ! Pasitọ n ba ọmọde yii sun, o tun n fun un loogun ti ko fi ni i loyun
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01171
Kaduna strike : NLC fòpin sí ìyanṣẹ́lódì Ọlọ́jọ́ mẹ́rin ní Kaduna
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01172
Ansoogun jagunjagun Iresa Adu Ogbomoso tó máa ń bínú gba ẹbọ- Oloye James Olawale
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01173
Unilag VC: Folasade Ogunsola ni obìnrin àkọ́kọ́ tó jẹ ọ̀gá àgbà fún ibùdó ẹ̀kọ́ṣẹ́ ìṣègùn Fáṣítì Eko
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01174
O ma ṣe o, ile ya pa awọn ọmọ ileewe meje
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01175
Wahala l’Ararọmi Owu, araalu lawọn ko fẹ ọba to wa nipo, lawọn janduku ba dana sun aafin
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01176
Rohingya sue Facebook: Àwọn ẹ̀yà kan rèé tó pe iléeṣẹ́ Facebook lẹ́jọ́, wọ́n ń bèrè $150b owó gbà mábìnú
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01177
Tobilọba ati Ṣeun maa fẹwọn ọdun mẹta jura, gbaju-ẹ ni wọn ṣe
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01178
"""Ẹ wo àwòkọ́ṣe Osinbajo, ẹ dẹ́kun lílọ sókè òkun fétó ìwòsàn"""
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01179
Lagos-Ibadan Expressway Fire: Kíló fa iná tó sọ ní òpópónà Ibadan sí Eko tó gbẹ̀mí ènìyàn tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọkọ̀ sì jóná?
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01180
Lẹyin ti wọn gba miliọnu marun-un, awọn ajinigbe tu ara ilu oyinbo ti wọn ji gbe silẹ
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01181
Wọn ti mu Jide, ọkan ninu awọn ogbologboo adigunjale to n yọ awọn eeyan Akurẹ lẹnu
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01182
Àjọ NSCDC mú àwọn ọ̀dọ́ tó ń jó ijókíjó ní Gombe 'nítorí ó ń dúnkookò mọ́ ètò ààbò'
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01183
Atiku Appeal: Ilé ẹjọ́ tó ga jùlọ ní Nàìjíríà yóò gbẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn PDP lọ́jọ́rùú
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01184
Lẹyin tawọn Fulani ba oko Dayọ jẹ tan ni wọn tun ṣa a pa l’Ajọwa Akoko
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01185
Akinyele murder: Àwọn aṣekúpani tún ti pa ọmọ ọdún 16 ní Akinyele nípìnlẹ̀ Oyo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01186
Falana sòkò ọ̀rọ̀ sì agbẹnusọ Ọlọ́pàá tó ní aráàlù kò le gbẹ̀san, bí ọlọ́pàá bá gbá a létí
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01187
'Gbogbo èèyàn 43 tó súnmọ́ ẹni tó kó Monkey Pox wọ Kwara láti rí'
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01188
Yahoo Yahoo: Ọkùnrin kan rí ẹ̀wọn ọdún kan àbọ̀ he lẹ́yìn tó lu obìrin ní jìbìtì ìfẹ́ lórí ayélujára
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01189
Africa Eye: Coronavirus di adákẹ́jà ní Somalia, ikú ọ̀wọ́ọ̀wọ́ ń peléke si
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_01190
Tori pe ṣọja fọ ọrẹ wa leti lo jẹ ka lu u pa-Sambo
0
1
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01191
Oyin Elebuibon: Olórìṣà ni mí, ẹ yé é fi ojú ẹni ibi wo àwa ẹlẹ́sìn àbáláyé
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01192
Nitori ọrọ ti ko to nnkan, awọn akẹkọọ Fasiti KWASU mẹrin dawọ jọ lu ẹlẹgbẹ wọn pa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01193
Seriki Williams Abass: Ọba Badagry tó jẹ́ ẹrú, tó tún padà di olówò ẹrú
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01194
Sunday Igboho: Àwọn ọmọ ogun, ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ DSS àtawọn òṣìṣẹ́ NSCDC ló dá mi lọ́nà
0
0
0
0
1
0
yor