id
stringlengths
23
24
text
stringlengths
3
4.68k
anger
float64
0
1
disgust
float64
0
1
fear
float64
0
1
joy
float64
0
1
sadness
float64
0
1
surprise
float64
0
1
language
stringclasses
28 values
yor_train_track_a_00995
Alaafin of Oyo dead: 'Aláàfin ti rí ikú rẹ̀ ṣáájú ọjọ́ tó wàjà, ó sọ̀rọ̀ sílẹ̀ kó tó kú'
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_00996
RRS doola ẹmi ọmọbinrin to fẹẹ binu ko somi l’Ekoo
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_00997
Ẹlerii ti wọn mu lori iku tọkọ-taya tawọn agbanipa sun mọle l’Abokuta ti sa lọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_00998
Wasiu fo fẹnsi wọle onile, lo ba ji jẹnẹretọ nibẹ n’llọrin
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_00999
Sunday Igboho‘s Birthday: Àwọn olólùfẹ́ Igboho rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí ìjọba Benin láti tú u sílẹ̀, wọ́n ní Ó ń jà fún ìran rẹ̀ ni, kìí ṣe apànìyàn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01000
Wọn ti ri awọn akẹkọọ Fasiti Ọlabisi Ọnabanjọ meji ti wọn ji gbe lọ pada
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01001
Oluwo Divorce: Olúwòó ilú Iwo: Èèwọ! Ọba aláde o gbọdọ kọ aya rẹ̀ sílẹ̀
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01002
Nitori bi wọn ṣe ti i mọle lọna aitọ, Sunday Igboho pe ijọba ilẹ Bẹnnẹ lẹjọ, o ni afi ki wọn san Miliọnu kan Dọla foun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01003
Ẹ yé tẹ òfin lójú mọ́lẹ̀ EFCC, ẹ kó láṣẹ láti fòfin gbé wa - àwọn aṣòfin Oyo sí EFCC
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01004
Awọn aṣaaju PDP ẹkun Ọyọ fa Makinde kalẹ lati dupo gomina fun saa keji
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01005
Dino Melaye àti Peter Obi gbéná wojú ara wọn níbí ìtàkurọ̀sọ àwọn olùdíjé sípò ààrẹ
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01006
Michigan school shooting: Ọlọ́pàá fi ṣìkún òfin mú àwọn òbí ọmọ tó yìnbọn pa èèyàn mẹ́rin nílé ẹ̀kọ́
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01007
Latigba ti Buhari ti gbajọba ni wahala Boko Haram ti lọ silẹ-Fẹmi Adeṣina
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01008
Ọwọ osun ni mo fi n nu ogiri gbigbẹ lati ọdun kẹrin, ti su mi, ẹ tu wa ka- Kafayat
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01009
HPV Infection: Àpẹ́rẹ́ àìsàn tó ń fa àrùn jẹjẹrẹ pọ̀ lára àwọn obinrin tó wà ní ìlú Ibadan - Ìwádìí fìhàn
0
0
1
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01010
Ọlọpaa ko le da wa duro, dandan ni ka ṣewọde fun iṣọkan Yoruba l’Ọṣun ni Satide – Ọba Ogboni
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01011
Pneumonia in Nigeria: Ó kéré tán ọmọdé 142,000 sí 160,000 ní àìsàn otútú àyà ń pa lọ́dọọdún ní Nàìjíríà
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01012
2023 Presidency: Kokoko lara mí le, Mo kàn ń gbà ìtọ́jú ni- Tinubu ṣàlàyé ìdí tó sì fi wà ní London
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01013
FIFAWWCUP: Wo ohun mẹ́rin tó jẹ́ ki America tún gbá ife ẹ̀yẹ àgbáyé
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01014
Otuoke attack: Ààrẹ Buhari ní àbò wà fún ẹ̀mí ààrẹ́ àná, Goodluck Jonathan
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01015
Police shooting in Osogbo: Ọlọ́pàá MOPOL yìnbọn fún Ọlabomi, ọlọ́kadà nílùú Osogbo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01016
Owolabi Ajasa police in Yoruba film: Irungbọ̀n tí mi ò ní ló mú mi ṣe oríire kíkó'pa ọlọ́pàá
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01017
Peter Obi wọle ni Delta, Abuja
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01018
Lẹyin iyanṣẹlodi oṣu mẹta, awọn oṣiṣẹ kootu pada sẹnu iṣẹ l’Ọṣun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01019
Wọ̀n tẹ̀ èèyàn méjì pàá nílé jọ́sìn kan nìpínlẹ̀ Eko
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01020
Oyetọla bura fawọn alaamojuto kansu l’Ọṣun, o ni ijọba ko gbọdọ ka iwa ibajẹ mọ wọn lọwọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01021
Ọjọ Ogbo: Àwọn òṣèré tíátà kan ṣàfihàn fọ́tò ọjọ́ ogbó wọn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01022
Ọwọ tẹ Adeolu at’ọrẹ ẹ, awọn ti mọto wọn ba bajẹ soju ọna lalẹ ni wọn maa n ja lole
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01023
Christians in Pakistan: Ọmọbìnrin ọdún méjìlà tó dí ìyàwó tipátipá fún Mùsùlùmí sọ ìrírí rẹ̀
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01024
Ọṣun 2022: Kẹni to ba fẹẹ dije lọọ gba fọọmu, emi o bẹru idibo abẹle o -Oyetọla
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01025
Ab’ẹẹri Sanusi, suuti lo fi tan ọmọkunrin to larun ọpọlọ to fi fipa ba a lo pọ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01026
Wọn ni Wolii Alade-Ẹmi lo fun ọmọ iya ijọ wọn to ku ni majele jẹ
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01027
Iganmu shanty demolition: Oníṣẹ́ ibi pọ̀ tó ń ṣọṣẹ́ lábẹ́ afárá Iganmu yìí ti pẹ́ ṣùgbọ́n.
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01028
Ẹ ṣọra fun jijẹ tọki ati ṣinkin ti wọn ko sinu yinyin wa lati ilẹ okeere, kẹmika ti wọn n lo ni mọṣuari ni wọn n fi si i- NAFDAC
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01029
Timothy Adegoke: Mọ̀lẹ́bí sọ ìdí tí wọn ṣe fẹ́ sin olóògbé
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01030
Oyo Fire: Dukia ṣófo, ọmọ ọdún mẹ́rìnlá faragbọta níbí iná tó jó ọjà Akesan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01031
Lasiko iṣọ oru lawọn Fulani ya bo wọn ni ṣọọṣi CAC Waasinmi, wọn ja wọn lole, wọn tun ji ẹni kan gbe lọ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01032
‘Eeyan mẹrin la ti ta ẹya ara wọn fun oogun owo, bọọlu la n pe agbari, transifọma la n pe ọkan, faanu ni ọwọ’
0
1
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01033
Ẹ gba wa o, ajeji nijọba ipinlẹ Ọṣun fẹẹ yan le wa lori niluu Ekọsin
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01034
LASTMA in Lagos: Awakọ̀ ṣekúpa òṣìṣẹ́ LASTMA
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01035
Ibo abẹlẹ APC Ọyọ: Fọlarin jawe olubori, Adelabu gba ẹgbẹ SDP lọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01036
Ooni of Ife's surprise birthday: Olorì Wòlíì Silekunola Naomi wú olólùfẹ́ rẹ̀, Ooni ti Ile Ife lórí
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01037
Owo de! Adeleke bẹrẹ sisan owo pailetiifu fawọn oṣiṣẹ ijọba
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01038
'Àgbà ló ń ṣe Fasoranti, tó bá yá yóò ronúpìwàdà'
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01039
Nitori ọrọ ti ko to nnkan, alapata yii yọbẹ siyawo ẹ, lo ba kun un bii ẹran
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01040
O ga o! Eeyan mẹta ku ninu ija ilu Ifọn ati Ilobu
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01041
Ọlọpaa ti mu Baba Ijẹṣa onitiata, wọn lo fipa ba ọmọ ọdun mẹrinla lo pọ
0
1
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01042
Ìyàwó lè lo ọwọ́ rẹ̀ fi ba ọkọ ṣeré lásìkò Halaada rẹ̀, èyí kò ba ẹ̀sìn jẹ́- Aafa Abdullateef Lanre
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01043
Ọpẹ o, wọn ti ri akẹkọọ Fasiti Ilọrin ti wọn ji gbe pada, eyi ni bi wọn ṣe ri i
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01044
Ariwo Yoruba Nation yóò lólẹ́ tí Tinubu bá di Ààrẹ - Folarin
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01045
Buhari ko lahun rara, o fun mi lọpọlọpọ owo dọla nigba kan – Fẹmi Adeṣina
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01046
Nikẹ  fi mọto paayan meji nibi ti wọn ti n ṣewọde SARS l’Ekoo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01047
Akinmoorin 5 new year death: Ọkùnrin náà ní pé òun á pààyàn, ó si ṣe bẹ́ẹ̀- Ará ìlú
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01048
Nitori ọda ojo, awọn Musulumi wọle adura l’Ọṣun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01049
Ketu Market Violence: Rògbòdìyàn bẹ́ sílẹ̀ nigba táwọn òǹtàjà kọjú ìjà sí àjọ Task Force
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01050
Ondo APC Primary: Mo ti bẹ̀rẹ̀ sí ń bá àwọn akẹgbé mi nínú ẹgbẹ́ sọ̀rọ̀ kí àláàfíà léè jọba - Akeredolu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01051
Nitori biluu ṣe le koko, Aarẹ Tinubu ni ki wọn ṣayẹyẹ ajọdun ominira ilẹ wa wọọrọwọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01052
Palietiifu: Adeleke kede afikun ẹgbẹrun mẹẹẹdogun Naira fawọn oṣiṣẹ ijọba
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01053
Ẹni tí kò jẹ gbì kò lè kú gbì, eré ọmọdé ni EFCC ń ṣe - Ambode
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01054
Iná sọ nílé Akin Ogunbiyi tó ń díje du ípò gómìnà ní ìpínlẹ̀ Osun, ọ̀pọ̀ dúkìá ṣòfò
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01055
Ọpẹ o, ori ko Bidemi Kosọkọ yọ lọwọ iku ojiji
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01056
Awọn ọmọ ita gbajọba n’Ibadan, wọn fọ ọpọlọpọ ṣọọbu lọsan-an gangan
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01057
Soun Ogbomoso's daughter dies: Ikú tó mú Soun Ogbomosho tún ti mú àkọ́bí rẹ̀ lọ o!
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01058
Awọn ajinigbe n beere aadọta miliọnu lori mọlẹbi kan ti wọn ji gbe l’Ekiti
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01059
Àwọn tó ń fi àìsàn bú Tinubu ti lulẹ̀, ó dàgbà lóọ̀tọ́ọ́, àmọ́ kò ṣàìsàn - APC
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01060
Ọpẹ o, Wọn ti fun Pariolodo ni mọto olowo nla
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01061
Goriola Hassan: Bí o ko ba yọju níwájú ilé, a ó fi ọlọ́pàá gbé ọ́, Alaga Igbimọ pàsẹ fún Goriola Hassan lórí ipò rẹ̀ bi ọba Imobi
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01062
Ile-ẹjọ ni ki wọn lọọ yẹgi fun Ọlabọde to lu iyawo rẹ pa toyun toyun l’Akurẹ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01063
Olubadan Coronation: Olubadan tuntun kéde pé oyè Ibadan kìí ṣe fún títà
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01064
Ọ̀mùtí Ṣójà wa ọkọ̀ pa ọ̀gá rẹ̀ nínu báráàkì ní Eko
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01065
Osinachi Nwachukwu: Àwọn ẹ̀rí tuntun farahàn nípa ikú akọrin Ekwueme
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01066
Nbi ti wọn ti n le adigunjale, sifu difẹnsi yinbọn pa iyaale ile kan lasiko to fẹẹ kirun Yidi
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01067
Ìjàmbá ọkọ̀ gba ẹ̀mí èèyàn mẹ́rìnlá, àwọn mẹ́ta fun farapa ní òpópónà Eko sí Ibadan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01068
Wọ́n ṣá alága ẹgbẹ́ ọlọ́kọ̀ èrò pa l‘Eko lásìkò táwọn jàǹdùkú fẹ́ gbàkóso gáréèjì ọkọ̀
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01069
Lẹyin ọjọ kẹta ti wọn paayan marundinlogoji, awọn agbebọn tun fẹmi aadọta eeyan ṣofo ni Kaduna
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01070
Fani-Kayode: Kò sẹ́ni tó mọ ìgbà táwọn ọmọ Nàíjíríà yóò fárígá láti kọ ìyà tó ń jẹ wọ́n
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01071
35th Lisabi Day: Àwòkọ́se rere ni Lisabi jẹ́ fún ọ̀dọ́ láti jẹ́ ògo Ẹ́gbá àti ilẹ̀ Yorùbá lapapo- Oba Gbadebo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01072
Awọn araalu binu si Tinubu, nitori bo ṣe ni ki wọn maa fawọn darandaran ni ilẹ ti wọn ko ba lo
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01073
Ǹkan márùn ún tí Atiku ní òun yóò ṣe nìyìí tó bá di Ààrẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01074
Afghanistan crisis: Dele Farotimi ní àwọn agbésùnmọ̀mí le gbàjọba Nàíjíríà tí ìjọba kò bá jáwọ́ nínú ojúṣàájú àti ẹlẹ́yàmẹ̀yà
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01075
Domestic Violence: Joy tún gún òǹlàjà, tó jẹ́ ẹ̀gbọ́n ẹni tí wọn jọ ń jà, ní ọ̀bẹ lọ́wọ́ òsì
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_01076
Itusilẹ ni Pasitọ Matthew loun fẹẹ ṣe f’ọmọ ijọ rẹ to fi fipa ba a lo pọ l’Ogijo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01077
Mọ mọ p’ọrọ epo yii n fara ni araalu, ṣugbọn ma a di i fun yin o – Tinubu
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01078
Araalu meji padanu ẹmi wọn nibi ija agba awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01079
Naira Marley: Ẹ̀kọ́ rèé fáwọn Marlians tó pa iléẹ̀kọ́ tì, tí wọn ń fa ṣòkòtò sílẹ̀ kiri
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01080
Insecurity In Nigeria: Ẹ yàgò fún ádùrá ṣiṣe nínú igbó kí ẹ má kò sí ọwọ àwọn ajínigbe-Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01081
Ilé ẹjọ́ Sharia ní Kaduna tú ìgbéyàwó ká nítorí àìbọ̀wọ̀ fún àna
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01082
Baba Suwe: Babatunde Thompson sọ̀rọ̀ nípa ẹni tó wé ikú Moladun mọ́ Babatunde Omidina lọrun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01083
Buhari Oloto: Gbajúmọ̀ ọba tó lo sàá lágbo fàájì ìlú Eko fún ogójì ọdún ó le
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01084
Osun APC crisis: Gomina Oyetola ti pè fún alàáfíà láàrin àwọn ọmọ ẹgbẹ́ APC tí Gboyega Famodun gbé lọ sílé ẹjọ́
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01085
Patako ipolongo Ọṣinbajo fun ipo aarẹ lu ipinlẹ Kwara pa
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01086
Ikọ̀ agbésùnmọ̀mí tó ṣèkọlù sí ọgbà ẹ̀wọn Kuje ní ohun ìjà jù wálọ - Ìjọba Naijiria
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01087
Itunu Lawal allegedly killed by husband: Láàrin ọdún méjì ìgbéyàwó, ọmọ mi àti ọkọ rẹ bẹ̀rẹ̀ ìjà tó gbóná
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01088
Lẹyin ọsẹ kan niluu oyinbo, Tinubu de lati gbọpa aṣẹ Naijiria
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01089
Oṣere tiata tawọn ọlọpaa yinbọn lu, eyi nipo to wa lọsibitu ti wọn gbe e lọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01090
Ìjọba Tanzania yòó fi òfin gbé òbí tí ọmọ rẹ̀ bá sá nílé ẹ̀kọ́
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01091
Oyo state: 615, nọ́mbà tuntun fún ìdáàbòbò àwọn èèyàn ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ̀
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01092
Papa iṣere Ilọrin la ti maa ṣe ayẹyẹ ‘Durbar’ ọdun yii – Ilọrin Emirate
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01093
Kidnap cases in Nigeria: Iléeṣẹ́ ọ̀lọ́pàá ní ọwọ́ tẹ afurasí méjì, méjì míì sálọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01094
Dowen College: Àwọn mọ̀lẹ́bí Sylvester Oromoni bẹ Femi Falana lọ́wẹ̀ lórí ikú ọmọ wọn
0
0
0
0
1
0
yor