id
stringlengths 23
24
| text
stringlengths 3
4.68k
| anger
float64 0
1
| disgust
float64 0
1
⌀ | fear
float64 0
1
| joy
float64 0
1
| sadness
float64 0
1
| surprise
float64 0
1
⌀ | language
stringclasses 28
values |
---|---|---|---|---|---|---|---|---|
yor_train_track_a_01395 | Child Abuse: Amòfin ní ọmọbìnrin náà leè rí ara rẹ̀ bíi ẹni tí kò wúlò | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01396 | Aarẹ Pakistan: Idájọ ikú ni wọ́n fun Musharraf nitorí ẹ̀sùn Iditẹ̀ gbà ìjọba | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01397 | FIFA ní kí àjọ bọ́ọ̀lù ní Nàìjíríà, NFF ó san N156m owó gbà máà bínú fún Gernot Rohr akọ́nimọ̀ọ́gbá rẹ̀ tẹ́lẹ̀ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01398 | Fire accident victim: AbdulQudus Bello ṣàlàyé bí òun ṣe dí aláàbọ̀ ara nítorí pọpọ́ọ̀fù àti ìbínú jàǹdùkù àdúgbò | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01399 | Awọn agbebọn ti pa mẹta ninu awọn akẹkọọ fasiti ti wọn ji gbe ni Kaduna | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01400 | Aarẹ wa balẹ si Bamako, ni Buhari ba bo imu ẹ pinpin | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01401 | Ibọn tawọn kọsitọọmu yin lo pa Ṣọla nibi to ti n ṣiṣẹ ẹ jẹẹjẹ l’Ayetoro | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01402 | Ìdí tí èmi Pásítọ̀ ṣe ń bu owó tabua fáwọn ọ̀dọ́ ní Ṣọ́ọ̀ṣì mi, tí mo tún ń bá olórin Davido, Portable Zazzu ṣe rèé | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01403 | A ó ṣe ìfẹ̀họ́núhàn káàkiri Naijiria bẹ̀rẹ̀ láti óní lórí ààbọ̀ owó oṣù tí ìjọba san fún wa– ASUU | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01404 | 'Kò yẹ kí Ọlọ́run dá obìnrin sáyé rara' | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01405 | Nitori bawọn Hausa ṣe dawọ kiko ounjẹ wa silẹ Yoruba duro, awọn kọmiṣanna eto ọgbin nipinlẹ Yoruba ṣepade | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01406 | Ibo abẹle APC: Wọn ti din awọn ti yoo dije ku si marun-un | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01407 | Ijọba Ogun ti gbe fọọmu sode fẹni to ba fẹẹ darapọ mọ ẹṣọ Amọtẹkun | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01408 | Oluwo: Ọ̀pọ̀ ọ̀dọ́ láwọn aṣíwájú orílẹ̀èdè Nàìjíríà ti fi ìwà àjẹbánu àti ìjẹkújẹ lé dànù sí òkè òkun | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01409 | Gomina Ademọla Adeleke di Aṣiwaju ilu Ẹdẹ | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01410 | Ọlọpaa n wa awọn ọmọ ọba meji, nitori ade iṣẹmabaye ti wọn ji lọ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01411 | Ẹni mẹ́ta wọ gbaga ọlọpàá nítori ajílẹ̀ tí wọ́n kó tà ní ọja Daleko ní Mushin | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01412 | Ọdọọdun ni Tinubu ni ka maa gbaayan ṣiṣẹ ọlọpaa bayii-Ẹgbẹtokun | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01413 | Lọjọ kan ṣoṣo, eeyan mẹjọ ku ninu ijamba ọkọ ni marosẹ Eko s’Ibadan | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01414 | Ọpẹ o, awọn Fulani ti tu Basit, ọmọ Damilọla olorin Islam silẹ o | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01415 | Prematured Menopause: Òògùn lílò àti àwọn nkan mìí tó le mú kí nkan oṣù obìnrin dáwọ́ dúró láìpé ọjọ́ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01416 | Nigerian Navy Ondo: Ikọ̀ ọmọogun orí omi fi páńpẹ́ mú olè mẹ̀rìnlélógún tó ń jí epo rọ̀bì | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01417 | Ajalu buruku lagbo tiata! Sisi Quadri ku lojiji | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01418 | Ogun kidnap: Ajínigbé ń bèèrè owó ìtúsílẹ̀ N10m, Codiene, igbó àtí oúnjẹ fún ìtúsílẹ̀ èèyàn mẹ́ta tí wọ́n gbé | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01419 | Ẹgbẹ APC yoo ṣepade lori eto idibo abẹle wọn ni ogunjọ, oṣu Kẹrin | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01420 | Nigeria at 61: Ẹ wo àwọn olóṣèlú méje pàtàkì tó jà fún òmìnira Nàìjíríà | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01421 | Ritual Murder: Bàbá akẹ́kọ̀ọ́bìnrin LASU tí ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀ fi ṣ'òògùn owó ń bèèrè fún ìdájọ́ òdodo | 1 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01422 | ILana Omo Oodua: Ẹgbẹ́ IOO jáwé gbélé ẹ fún Otunba Olukoya, fòǹtẹ̀ lu Adeleye àti Akinwande | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01423 | Nitori idibo ijọba ibilẹ to n bọ, awọn tọọgi APC fi ada ati kumọ da ipade awọn SDP ru n’Idanre | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01424 | Olubadan ti sọrọ o: Abẹ akoso Baalẹ Ṣaṣa ni Seriki Ṣaṣa wa | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01425 | Ọ̀dá owó ló sọ mi di alábárù, iṣẹ́ àbárù sàn ju olè jíjà lọ-Alábárù | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01426 | Tinubu lo n lewaju nipinlẹ Sokoto | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | yor |
yor_train_track_a_01427 | Àwọn agbébọn pa ènìyàn méjì ní ìpínlẹ̀ Kwara, jí ọ̀pọ̀ gbé lọ | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01428 | Dandan ni fawọn akẹkọọ wa ni UNIOSUN lati ni imọ nipa iṣẹ ọwọ – Ọjọgbọn Adebooye | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01429 | Eeyan mẹrin gan mọ’na, ọpọ fara pa, lasiko ajọdun ni ṣọọṣi Kerubu l’Abule-Ẹgba | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01430 | DR Congo: Ọ̀pọ̀ ẹmí lo ti sọ́nù ninú ìjàmbá ọkọ̀ òfurufú tó wáyé lóòní | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01431 | Abisayo Fakiyesi breast cancer survivor: 'Gbogbo irun orí, ti abẹ́, abíyá pátá ló fá lọ, ahọ́n àti èékáná mi dúdú! | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01432 | Wọ́n rẹ ọrùn ọmọ ọdun méjìlá, gbé òkú rẹ̀ sín àpótí | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01433 | Aṣiri nla! Idi ti Pasitọ Bakare fi d’ọrẹ Tinubu lojiji ree o | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | yor |
yor_train_track_a_01434 | Nigeria Police: Ìwádìí ti bẹ̀rẹ̀ lórí ọlọ́pàa'tó lo ‘POS’ fi gba rìbá’ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01435 | Ṣọọṣi Ridiimu pese aaye itọju aisan kindirin si ọsibitu OOUTH, wọn tun ra irinṣẹ si i | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01436 | Nnkan de! Awọn afẹmiṣofo ti ya wọ awọn aginju igbo kaakiri ilẹ Yoruba | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01437 | Laipẹ yii ni wahala ẹgbẹ oṣelu PDP yoo rokun igbagbe – Oyinlọla | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01438 | Idowu atọrẹ ẹ yọ ẹya ara baba agbalagba lọ, wọn lawọn fẹẹ fi ṣoogun owo | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01439 | Taribo West: Àwọn aláìní ní Italy ní mò ń fi owó ìjọ mi ràn lọ́wọ́ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01440 | Reluwee fori sọ bọọsi BRT l’Ekoo, eeyan meji ku, ọpọ fara pa yannayanna | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01441 | Insecurity in Yorubaland: Olugbon ní àwọn ọba ṣetán láti ti olóòtọ́ọ́ oníṣẹ̀ṣé lẹ́yìn lórí ìpèsè àbò | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01442 | Ọṣinbajo, Tinubu, Arẹgbẹṣọla, Omiṣore atawọn agbaagba Yoruba wọle ipade l’Ekoo | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01443 | Igbakeji gomina Ogun ni yoo dari igbimọ ipolongo idibo ijọba ibilẹ APC | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01444 | Kwara Local Government: EFCC jú alága ìjọba ibílẹ̀ 16 si àhámọ́ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01445 | Nitori ifẹhonuhan awọn Musulumi, eyi lohun ti Ṣọun Ogbomọṣọ ṣe | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01446 | Blind Oniru: Muinat Abdulfatai ní òun ro ara òun pin àmọ́ irú títà fún òun ní ìrètí ọ̀tun | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01447 | Obateru Akinruntan: Wíwá ohun tá jẹ títí láé ló gbé wa kúrò nílé Ife | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01448 | Shasha crisis aftermath: Alága àwọn òntàjà lóun pàdánù N20m níbi ìjà tó ṣẹlẹ̀ | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01449 | Oja Odan killing: 'Accident' ọlọ́kàdá ló tú àṣírí àwọn afurasí méjì tí a bá orí eèyàn nínú àpò wọn- Oba Oyebamiji | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01450 | Ọkunrin yii ma daju o, lẹyin to fipa ba ọmọdebinrin yii sun tan lo tun ṣeku pa a | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01451 | Woman, Ethiopia's Tigray crisis: Ọmọbìnrin ọdún 18 ṣàlàyé bí ó ti gé lọ́wọ́ nígbà tí sọ́jà kan fẹ́ fipá bá a lòpọ̀ | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01452 | Alleged incest: Ọkùnrin kan dèrò àtìmọ́lé lórí ẹ̀sùn fífi ipá bá ọmọ bíbí inú rẹ̀ méjì lájọṣepọ̀ ní ìlú Akure | 0 | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01453 | Sunday Igboho yoo fara han nile-ẹjọ lorileede Benin | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01454 | Afenifere sọ̀rọ̀ àbùkù sí agbẹnusọ Buhari lẹ́yìn tó tako àwọn tó ń bu ẹnu àtẹ́ lu ìjọba rẹ̀ | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01455 | Ko bojumu bi Gomina Adeleke ṣe ki oṣelu bọ ọrọ Fasiti Ileṣa-Ọdẹyẹmi | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01456 | O ma ṣe o, tẹgbọn-taburo lọọ wẹ lodo, ni wọn ba bomi lọ lọjọ ọdun Keresi | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01457 | Afghanistan Women vs Taliban: Ìdí rèé tí Taliban fí gbé òfin kalẹ èyí tó de kí obìnrin dá rírìn àjò tó kọjá 45 miles | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01458 | 2023 presidency: Wo àwọn ọmọ Yorùbá mẹ́fà tí ẹnu ń kùn lórí ìbò ààrẹ ọdún 2023 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01459 | Osun Bank Robbery: Àwọn adigunjalè ti kọlu báǹkì kan ní ìpínlẹ̀ Osun | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01460 | Awọn agbebon ji Aafaa Jẹlili atọrẹ ẹ gbe l’Ayetoro, ni wọn ba n beere miliọnu mẹẹẹdogun leyin ti wọn pari ọbẹ tiyawo ẹ sẹsẹ se | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01461 | Ọwọ́ ọlapàá tẹ obìnrin tó jí ẹ̀ṣọ́ ara okù | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | yor |
yor_train_track_a_01462 | Fake Naira: DSS gbé afurasí mẹ́jọ tó tẹ ayédèrú ₦98m àti $1.5m lọ sílé ẹjọ́ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01463 | Togo Elections: Ààrẹ Gnassingbe díje fún sáà kẹ́rin, òun àti bàbá rẹ̀ ti ṣèjọba Togo fún àádọ́ta ọdún lé | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01464 | Wikie ṣeleri fun Obi: Gbogbo ‘atilẹyin’ to ba yẹ ni ma a fun ẹ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01465 | Polongo ibo nile ẹsin ko o rẹwọn he – INEC | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01466 | Ewu nla n rọ dẹdẹ lori Naijiria pẹlu bi wọn o ṣe fi Sunday Igboho silẹ yii- Ẹgbẹ Oodua Worldwide | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01467 | Boko Haram Insurgency: Ẹ̀yin oníròyìn ẹ rọra máa pariwo ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ nípa àwọn adigunjalè, ẹ ń kóbá iṣẹ́ agbófinró - Àjọ NBC | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01468 | A maa ṣakoso ijọba orileede yii ni, a ko ni i jẹ gaba lori araalu-Tinubu | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01469 | Oyetọla fopin si konilegbele l’Ọṣun | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01470 | Coronvirus in Nigeria: Àjọ NCDC ti kede pé ènìyàn méji míran ti ni àrun náà | 0 | 0 | 1 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01471 | Religion tolerance in Nigeria: Obìnrin Mùsùlùmí ní òun ṣe ilé àlùfà ní ọ̀ṣọ́ kérésì láti polongo ìrẹ́pọ̀ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01472 | Hijab Crisis: Elebuibon ní àwọn ẹlẹ́sìn ìbílẹ̀ náà fẹ́ káwọn ọmọ wọn máa wọ ìlẹ̀kẹ̀ lọ sílé ìwé | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01473 | Ilé ẹjọ́ ju àyédèrú LASTMA sẹ́wọ̀n oṣù mẹ́rin | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01474 | Inu mọto tawọn ọmọ iya mẹta ti n ṣere looru mu wọn pa si n’llọrin | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01475 | Ọdọ́bìnrin kan dáná sun ara rẹ̀ lẹ̀yin tí àwọn òbi kọ̀ fún lati fẹ́ ọlọ́kadà | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01476 | O ma ṣe o! Igbeyawo oṣere ilẹ wa yii ti daru, eyi lohun to fa a | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01477 | Igisekele: Àwọn àgbà ọ̀jẹ̀ akọrin Fuji ń ṣèdárò Amoo Igisekele tó jáde láyé | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01478 | Baba Suwe: Fún ojú lóúnjẹ nípa àwọn gbajúmọ̀ òṣèré tó yọjú síbi ìsìnkú Baba Suwe | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | yor |
yor_train_track_a_01479 | ‘Korona ni ko ti jẹ ka ṣafikun si ẹgbẹrun lọna ọgbọn naira ataabọ ti oṣiṣẹ to kere ju lọ nipinlẹ Ọyọ n gba’ | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01480 | Adajọ agba ilẹ wa, Tanko Muhammad ti kọwe fipo silẹ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01481 | Abikẹ Dabiri binu si ileeṣẹ tẹlifiṣan Arise | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01482 | Ìjọba ti ṣọ́ọ̀ṣì tí wọ́n ti n ta 'omi ayẹta ìbọn' fun àwọn olùjọ́sìn ní Kogi | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01483 | Yoruba kings that died recently: Alaafin, àti ọba ilẹ̀ Yorùbá márùn-ún mìí tó wàjà láàrin oṣù márùn-ùn péré | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01484 | Eeyan mẹjọ padanu ẹmi wọn nibi ija awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01485 | ‘Jibiti ni ofin ọdun 1999, afi ki wọn fagi le e’ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01486 | Awakọ̀ èrò tíjọba ta ọkọ̀ rẹ̀ lo oṣù mẹ́ta lẹ́wọ̀n, ọmọ rẹ̀ ọdún mẹ́ta tún kú | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01487 | Awọn ileewe ilẹ Yoruba yoo ṣi loṣu to n bọ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01488 | Awọn adigunjale to yinbọn pa oṣiṣẹ ileepo Akurẹ d’ero ile-ẹjọ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01489 | Wasiu Ayinde ṣiṣẹ abẹ ni Naijiria, o dupẹ lọwọ awọn dokita to ṣe e fun un | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01490 | Ikú ṣọṣẹ́! Ọ̀gá àgbà ilé ẹ̀kọ́ gíga KWASU jáde láyé | 0 | 0 | 0 | 0 | 1 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01491 | Ìpènijà márùn ún tí yóò kojú olóòtú ìjọba tuntun ní UK | 0 | 0 | 1 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01492 | Transgender: Ilé ìwòsàn wọ gàù torí kò sọ ewu tó wà nídìí ìyípadà ìṣẹ̀dá kan sí òmíràn | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01493 | Salawa Abẹni: ₦50 péré làwọn èèyàn fí ń pè mí fún ayẹyẹ nígbà tí mó bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ̀ | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
yor_train_track_a_01494 | Sotitobire: Àwọn ọmọ ìjọ yarí, wọ́n ní ejò lọ́wọ́ nínú lórí ìdájọ́ tí wọ́n dá fún Alfa Babatunde | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | yor |
Subsets and Splits
No saved queries yet
Save your SQL queries to embed, download, and access them later. Queries will appear here once saved.