id
stringlengths
23
24
text
stringlengths
3
4.68k
anger
float64
0
1
disgust
float64
0
1
fear
float64
0
1
joy
float64
0
1
sadness
float64
0
1
surprise
float64
0
1
language
stringclasses
28 values
yor_train_track_a_01695
Awọn eeyan Ipetu Ijẹṣa ni ki gomina Ọsun le Ọwa Obokun kuro nipo, nitori to gba kabiyesi wọn leti
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01696
India: Ọkùnrin kan yọ kindinrin ìyàwó rẹ
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01697
Israel Olagadeyo free school on the street: Ẹ̀kọ́ ilé la kọ́kọ́ fi bẹ̀rẹ̀ kó tó di báyìí mó wa lọ́wọ́
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01698
Ẹlẹwọn mẹrin padanu ẹmi wọn lasiko ti wọn fẹẹ sa kuro lọgba ẹwọn n’Ileefẹ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01699
Imaamu jade lọ ko wọle mọ, oku ẹ ni wọn ri lọjọ keji n’ijẹbu-Ode
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01700
Iwadii n lọ lori olukọ ti wọn lo fẹẹ fipa ba akẹkọọ lo pọ ni Fasiti Ifẹ-Awọn Alaṣẹ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01701
Bad road: NLC àtàwọn èèyàn Sango-Ota ti òpópónà Eko sí Abeokuta pa nítorí ọ̀nà tí kò dára
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01702
IPOB: A kò tún gbọdọ̀ rán àwọn ọmọ wá létí pé wọ́n wà lábé amunisin nípa kíkọ orin orilẹ ède Nàìjíría
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01703
Njẹ ẹ ti gbọ, ileeṣẹ Dangote ti bẹrẹ si i fọ epo bẹntiroolu bayii o
0
0
0
1
0
1
yor
yor_train_track_a_01704
Use of hijab: Ìjọba ti buwọ́lu lílo hijab láwọn iléèwé ní ìpínlẹ̀ Osun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01705
'Gbogbo àwọn afurasí tó lọ́wọ́ nínú ikú Sofiat ló ṣì wà ní àhámọ́'
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01706
Awọn akẹkọọ ileewe giga yoo wọle lọjọ kọkanla, oṣu yii, ni Kwara
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01707
Awọn adari ẹgbẹ APC l’Abuja gbe isakoso ẹgbẹ le Akala lọwọ nipinlẹ Ọyọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01708
Olubadan gbe awọn oloye Ibadan kan ga
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01709
Ọlọrun lo yọ Khadizat lọwọ awọn ajinigbe, Kogi ni wọn ti ji i gbe, Imo ni wọn ti ri i
0
0
0
1
0
1
yor
yor_train_track_a_01710
Emi ni mo ni iriri ju ninu gbogbo awọn oludije sipo aarẹ-Ọṣinbajọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01711
Awọn ọlọja  fariga fun ọmọ Tinubu, wọn ni aaye ohun to ṣe l’Ekoo ko si l’Edo
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01712
Àrá sán lù ojú òpó ìgbéra ní pápákọ̀ òfúrúfú, kò sí bàálù tó lé gbéra
0
0
1
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01713
Ọrọ ijọba ibilẹ ni Naijiria nilo adura, ojoojumọ lo n buru si i fun wọn- Ọbasanjọ
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01714
Awọn ti mi o ba rowo ji nile wọn ni mo maa n ba iyawo tabi ọmọọdọ wọn lo pọ – Adeniyi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01715
Awọn Fulani darandaran ya wọnu ọja, wọn paayan mejidinlogun
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01716
Ẹfun abeedi: Oyinbo Amẹrika yii ro o pin, o fẹẹ bẹ sodo ọsa l’Ekoo
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01717
Ìjọba Sanwo-Olu ṣe àgbékalẹ̀ ètò adójútòfò ìlera f'áwọn àgbààgbà òṣèré tíátà Yorùbá
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01718
Ayede Ogbese Kidnap: Wọ́n ti ri ẹni mẹ́wàá tó di àwátì nínú oko tí wọ́n ti ń ṣiṣẹ́ ní Ondo
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01719
Kazeem Tiamiyu: Mo fọṣọ, fọ ilẹ̀, ta omi tútù láti fi tọ Kazeem àtàwọn tó kù - Òbí Kazeem
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01720
Kẹmiisi yii ti ko bara ẹ poo! Ohun to ṣe fun ọmọ ọdun mẹsan-an ti wọn ni ko tọju buru jai
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01721
Lasiko tawọn eleyii n digunjale lọwọ lawọn agbofinro ko wọn n’Ikẹja
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01722
Fungba akọkọ, ijọba fun awọn oṣiṣẹ to fakọ yọ lẹbun ọkọ ayọkẹlẹ l’Ọṣun
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01723
Awọn ọmọ Naijiria yii n lọ bii oko rọba, kokeeni ni wọn ka mọ wọn lọwọ ni Nairobi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01724
Ijọba ti din owo-epo bẹtiroolu ku
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01725
Seyi Makinde: Wo ìdí tí gómìnà Oyo fi pàṣẹ ìdádúró iṣẹ́ fún kọmíṣọ́nà rẹ̀
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01726
Ajalu buruku! Oṣere tiata mi-in tun ku lojiji
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01727
Loootọ ni mo fẹ iyawo Alaafin, ọba lemi naa-Portable
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01728
Àwọn agbésùmọ̀mí kọlu ibùdó àwọn ológun nílùú Abuja
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01729
Sunday Igboho: DSS kò jẹ́ ki mọ̀lẹ́bí tàbí agbẹjọ́rò rí àwọn èèyàn tí wọn ko nílé mi
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01730
Wọn ju ayalegbe to kina bọ ile lanlọọdu rẹ sẹwọn l’Ọyọọ
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01731
Maduka Okoye: Wo ohun tí o lè má mọ̀ nípa Maduka Okoye, aṣọ́lé Nàìjíríà tó ń dá àwọn obìnrin lọ́rùn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01732
Tortured to death: Ilẹeṣẹ́ ìròyìn BBC tú àsírí bí àwọn ọmọ ogun Myanmar ṣe pa àwọn aráàlú
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01733
Ọmọ ẹgbẹ onimọto ti wọn pa nibi ija awọn oloṣelu da ibẹru-bojo silẹ l’Ekiti
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01734
Awọn agbebọn tun paayan marundinlogoji ni Jos
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01735
O ma ṣe o, kọntena ṣubu le mọto akero ati kẹkẹ Marwa mọlẹ, eeyan mẹrin lo ku
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01736
"Mo ti ń làágùn gidi báyìí lórí ọ̀wọ́ngógó ""diesel"" tó bá Nàìjíríà - Obasanjo"
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01737
Pásítọ̀ gún ìyàwó rẹ̀ lọ́bẹ nínú ṣọ́ọ̀ṣì, ló bá tì í bọ ara rẹ̀ náà níkùn
0
0
0
0
1
1
yor
yor_train_track_a_01738
Ṣọja yinbọn pa ọlọpaa to da ọkọ ti ọkan ninu wọn ko igbo sinu rẹ duro
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01739
Ede Poly Rector suspension: Wọ́n ní kí ọ̀gá àgbà Pólì Ede lọ rọ́kún ńlé lórí ẹ̀sùn pé 'ó kan bẹ́ẹ̀dì sí ọ́fíìsì'
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01740
Amotekun security network: Gani Adams rọ gómìnà Yahaya Bello láti dá Amotekun sílẹ̀ ní Kogi
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01741
Ekiti, Ogun atawọn ipinlẹ meji mi-in ni kọmiṣanna ọlọpaa tuntun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01742
Lọjọ ọdun Keresi, ẹjẹ n ṣan bii omi ni Plateau, eeyan ọgọta lawọn agbebọn pa!
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01743
Fọlọrunsho kọja aaye ẹ, adajọ ti ni ko lọọ maa gbatẹgun lọgba ẹwọn Kirikiri
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01744
Alleged rape: Ọwọ́ tẹ bàbá ẹni ọdún 64 tó fi ìpá bá ọmọ ọdún méjì lòpọ̀ ní ìpínlẹ̀ Ogun
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01745
Ẹgbẹ Arewa fẹsun kan Tinubu, wọn ni ọdalẹ ni
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01746
Wo àmójútó tí o gbọ́dọ̀ fún nkan ọmọkùnrin rẹ láti dènà ààrùn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01747
Àwọn ajínigbé ń bèèrè owó tuntun láti tú ẹni tí wọ́n jígbé sílẹ̀
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01748
Ibeji ọran! Taye ati Kẹhinde lọọ fọ ṣọọbu l’Ado-Ekiti, ni wọn ba mu wọn
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01749
Internet Fraud: Iléẹjọ́ ní kí ''Yahoo boy'' lọ darí ọkọ̀ f'óṣù mẹ́ta lẹ́yìn tó tan obìnrin òyìnbó jẹ
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01750
Wo àwọn nǹkan tó yẹ kóo mọ̀ nípa Dókítà Rasaq Oyelami ti NNPP tó ń díje dupò gómìnà Osun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01751
Iyaagba kan ku, ọmọde mẹrin fara pa, lasiko arọọda ojo n’llọrin
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01752
Nitori Korona, Sanwo-Olu sun iwọle awọn oṣiṣẹ siwaju
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01753
Wo àwọn àṣà tó gbalẹ̀ kan lọ́dún 2022
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01754
Timothy Adegoke: Kọmíṣọ́nà ọlọ́pàá Osun ní ọmọbíbí Rahmon Adedoyin tó ni ilé ìtura tí Adegoke kú sí, ló jù òkú rẹ̀ sígbó
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01755
Kayeefi, sọja kan pokunso, o ni ile aye ti su oun
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01756
Makinde fun ijọ Musulumi moṣalaaṣi Ọja’ba ni bọọsi nla
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01757
Ọọni Ile-Ifẹ, Ọba Adeyẹye Ọgunwusi, fun Ajobiewe ni mọto nla
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01758
Onidaajọ Ariwoọla da si ọrọ oye Emir ilu Kano
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01759
Eyi ni ọna tuntun ti NDLEA fẹẹ gba gbogun ti awọn oniṣowo egboogi oloro
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01760
Wọn ma ni Tinubu ti pada de lati London
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01761
Àwọn èèkàn ẹgbẹ́ ní ilẹ̀ Yorùbá ní bí nǹkan ṣe rí pẹ̀lú àbò ní Nàìjíríà, bí aráàlú bá ní ìbọn fún àbò ara wọn kò burú o
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01762
Ìgunnukó: Àwọn Tápà gbà pé ẹni tó bá ń sin Ìgunnukó kò ní ráùn ohun rere
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01763
Akomolede: Akuko Gagara ni ìwé tó ṣàfìhàn ohun tó ń ṣẹlẹ̀ ní Nàìjíríà lásìkò yìí- Fatimo Bola Owokunle
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01764
Komla Dumor: Solomon Serwanjja jáwé olúborí nínú Àmì ẹ̀yẹ BBC
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01765
Tokunbọ Abiru ni APC fa kalẹ lati dije rọpo “Pẹpẹrito” to ku
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01766
Ismaila yii nika ninu o, ẹgbọn ẹ lo sa pa nitori ọrọ ti ko to nnkan ni Kwara
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01767
Mothers Day: Àyájọ́ ìrántí àwọn ìyá àti ìdí tí ẹnu kò fí kò lórí ọjọ́ yìí lágbayé
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01768
Pregnancy sleep tips: Wo ìgbésẹ̀ mẹ́wàá fún aláboyún láti rí oorun ṣùn lálẹ́
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01769
Christmas celebration: Èèyàn méje kú nínú ìjàmbá ọkọ̀ tó ṣẹlẹ̀ ní àárọ̀ Kérésìmesì lọ́nà Sagamu sí Ijebu Ode
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01770
Sanwo-Olu gbe aba eto iṣuna ọdun 2023 kalẹ fawọn aṣofin
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01771
Insecurity in Nigeria: Sheikh Nuru Khalid ní kí Buhari wá nǹkan ṣe sí ìkọlù agbébọn bíbẹ́ẹ̀kọ́...
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01772
Belarus: Ààrẹ orílẹ̀èdè Lukashenko tún wọlé lẹ́yìn ọdún 25 lórí oyè! Kí ló ń ṣẹlẹ̀ gangan?
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01773
Ogun state landgrabbers:Àwọn ajagungbalẹ̀ gba ilẹ̀ tó yẹ fún kíkọ́ iléèwé girama ní ìpínlẹ̀ Ogun
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01774
Igboho released in Benin republic: Sunday Igboho gba òmìnira láti lọ tọ́jú ara rẹ̀ nílé ìwòsàn ní Benin Republic
0
0
0
1
0
0
yor
yor_train_track_a_01775
Florence Onwuasoanya: Mo jẹ́ àsejẹ, mo mu àgbo tí kò ṣe e fẹnu sọ kí ń lè gbé ọmọ jó ṣùgbọn...
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01776
Eyi ni bi ọkọ Dangote ṣe tẹ ọmọ iya mẹta pa l’Akungba Akoko
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01777
Genort Rohr: A ò ní já ẹ̀yin alátìlẹ́yìn wa kulẹ̀ lónìí
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01778
NDA Invasion: Fr Mbaka ní bí Buhari kò bá yíwà padà, díẹ̀ ní ìṣẹ̀lẹ̀ Afghanistan yóò jẹ́
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01779
Fury vs Wilder: Ìbínú ni Wilder fi kúrò níbí ìjà, tó sì ní síbẹ̀-síbẹ̀, akọni ni òun
1
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01780
UNIOSUN : Ètò ìgbaniwọlé orí ayélujára fáwọn akẹ́kọ̀ọ́ tuntun ní fásitì UNIOSUN kò dín iyì ilé ẹ̀kọ́ gíga kù fáwọn akẹ́kọ̀ọ́ wa- VC UNIOSUN
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01781
Kọmiṣanna ọlọpaa Ogun fẹyinti layaajọ Ominira Naijiria
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01782
Eyi ni bi ijamba ina ṣe fi ọkẹ aimọye dukia ṣofo l’Ọffa
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01783
Alaafin Oyo's burial: Oba Lamidi Adeymi darapọ̀ mọ́ àwọn àgbà ìṣáájú, ọ̀pọ̀ ń dárò Kábíèsí
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01784
King burnt in Ogun State: Ọwọ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ogun tẹ afurasí 11 tó dáná sun ọba nílú Agodo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01785
Vincent Enyeama: Aṣọ́lé Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ rí ṣe tán láti padà sórí pápá
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01786
Awọn agbebọn ji iyawo olori ọdọ APC ipinlẹ Ọyọ gbe niṣeju ọkọ ẹ n’Ibadan
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01787
Coronavirus: Wọ́n ti gbé olóòtú ìjọba ilẹ̀ Gẹẹsi, Boris Johnson lọ sí wọ́ọ̀dù aláísàn tó lágbára
0
0
0
0
1
0
yor
yor_train_track_a_01788
Fulani herdsmen attack today: Àwọn Fulani láṣẹ láti gbé níbikíbi tó bá wù wọ́n ní Naijiria - Oluwo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01789
Osun state lockdown update: Awọn òṣìṣẹ́ padà sí ẹnu iṣẹ́ ní ìpińlẹ̀ Osun
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01790
Eto idibo ṣii n lọ lọwọ ni ipinlẹ Edo
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01791
Agbẹjọro lọ si kootu pẹlu aṣọ ẹsin abalaye, o ni idajọ ile-ẹjọ to ga ju lọ loun tẹle
0
0
0
0
0
1
yor
yor_train_track_a_01792
Awọn janduku ya wọ ọgba ẹwọn Okitipupa, wọn tun ọgọta silẹ ninu wọn
0
0
1
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01793
RevolutionNow: Falana àtàwọn míì ṣe àpérò l'Eko lẹ́yìn tí DSS kọ́kọ́ ti gbọ̀ngàn tí wọ́n fẹ́ lò pa
0
0
0
0
0
0
yor
yor_train_track_a_01794
Buhari ki Tinubu ku oriire, o ni ẹni ti ko ba dun mọ ko gba ile-ẹjọ lọ
0
0
0
1
0
0
yor