raw_text
stringlengths 2
128k
|
---|
denzel washington denzel hayes washington jr ọjọ́ ìbí ọ̣jọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 1954 jẹ́ òṣèré àti olùdarí eré ọmọ ilẹ̀ amẹ́ríkà washington ti gba ẹ̀bùn oscar àti ẹ̀bùn wúrà róbótó ní ẹ̀méèjì |
steve biko steve biko 18 december 1946 12 september 1977 je omo ile guusu afrika ti o lodi si eto eleyameya larin odun 1960 si ibere 1970 |
aisan down aisan down je aisan opolo ti n so awon to ba ni di ode a n pe loruko john langdon down eni ti o koko se alaye aisan yi ni odun 1866 |
nomba |
nomba tosoro |
nomba gidi |
nomba odidi |
nomba onipin |
nomba adabaye |
nomba tikosi |
nomba akoko |
ìmọ̀ ìsirò |
èdè látìnì ede latini je ede indo-europe ayejoun ti won n so ni ile romu ati ni ileoba romu |
èdè gríkì èdè gíríìkì jẹ́ èdè àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè gíríìsì àti kipru álífábẹ́ẹ̀tì wọn jáde láti inú phoenician script tí ó wá padà di ìkọsílẹ̀ fún èdè látìn cyrillic armenian coptic gothic àti àwọn ìkọsílẹ̀ mìíràn láti nǹkan bíi ẹgbẹ̀rún ọdún mẹ́ta sẹ́yìn ni wọ́n ti ń sọ èdè gíríìkì ní balkan peninsula ẹ̀rí àkọ́kọ́ tí wọ́n ṣe àkọsílẹ̀ rẹ̀ ni linear b clay tablet tí wọ́n rí ní messenia tí ọdún rẹ̀ jẹ́ nǹkan bíi 1450 àti 1350 bc èyí sì ni ó jẹ́ kí èdè gíríìkì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè tí ó ní àkọsílẹ̀ tó pẹ́ jùlọ |
fránsì fránsì pípè /ˈfræns/ tabi /ˈfrɑːns/ fun ibise gege bi ile faranse olominira je orile-ede ni apa iwoorun europe to ni opolopo agbegbe ati erekusu ni oke okun ti won wa ni awon orile miran fransi je orile-ede onisokan olominira ti aare die ti bi o se n sise wa ninu ipolongo awon eto eniyan ati ti arailu |
faranse |
kameroon |
cm cm je ti kameroon |
goodluck jonathan goodluck jonathan ọjọ́ìbí 20 noveber belu1957 jẹ́ olósèlú ọmọ ilè nàíjíríà àti àare orílé èdè nàíjíríà láti may èbìbi 6 2010 ohun ní igbákejì àare ilè nàíjíríà sí àare umaru músá yaradua kí ó tó dibo fun gégé bí adìbó àare ni 9 february 2010 nítorí aìsàn tó dé ba yaradua mólè léyin ti yar'adua kú ní may èbìbi 5 2010 jónáthàn di bakan yéyé ó tun jẹ gómìnà ìpínlè bàyélsà larin 9 ọpẹ́december 2005 àti 28 ebìbí may 2007 àti igbákejì gòmìnà ipinle igbesi aye ibẹrẹ g goodluck jonathan ní a bi ni 20 oṣu kọkanla ọdun 1957 ni ilu ogbia si idile kristiani kan ti awọn ti n ṣe ọkọ-ọkọ làti ẹya ijaw to kere ni ipinlẹ bayelsa |
ogun agbaye elekeji <ns>0</ns> <revision> <parentid>40817</parentid> <timestamp>2009-05-11t102739z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> </contributor> <comment>redirected page to ogun àgbáyé ẹlẹ́ẹ̀kejì</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> |
alicia keys alicia augello cook ojoibi january 25 1981 to gbajumo pelu oruko ori-itage re alicia keys je olusona olorin ati osere ara amerika |
bob dylan bob dylan oruko ibi robert allen zimmerman ojo ibi may 24 1941 je olorin/akorin omo ile amerika |
pi pi tabi π tabi pai jẹ́ ọ̀kan nínú oǹkà ìmọ̀ ìṣirò mathematics tó ṣe pàtàkì ó fé tó 314159 ó dúró fún ìpín ìyíká obirikiti mọ́ ìlà ìdáméjì rẹ̀ |
zambia orílẹ̀-èdè olómìnira zambia pípè /ˈsæmbiə/ jẹ́ orílẹ̀-èdè tileyika kan ni apaguusu afrika awon orílẹ̀-èdè tó súnmọ ni orílẹ̀-èdè olómìnira toseluarailu ile kongo ní àríwá tanzania ni ariwa-ilaorun malawi ni ilaorun mozambique zimbabwe botswana ati namibia ni guusu ati angola ni iwoorun oluilu re ni lusaka tó bùdó sí apá gúúsù-arin ibe |
apágúúsù áfríkà iha guusu afrika |
ìwọòrùn áfíríkà ìwọ̀orùn áfríkà tàbí apáìwọ̀oòrùn afíríkà ní àgbègbè ilẹ̀ afíríkà tó sún mọ́ ìwòoòrùn jù lọ ní ilẹ̀ áfíríkà |
ìlaòrùn áfríkà iha tabi apa ilaoorun africa jé ïhà tó sumo apa ilà oòrùn jù àwon orílè-ede tówà ní ìlà-oòrùn afrika ní tanzania kenya uganda rwanda burundi eritreaethiopia somalia comoros mauritius seychelles sudan djibouti eritrea madagascar malawi réunion somaliland ìlà-oòrùn afrika ní olùgbé to sumó 464911091 ni 2022 |
àrin áfríkà apa arin afrika |
ọkọ̀ òfurufú ọkọ̀ òfurufú jẹ ọkọ oju-ọrun ti irinṣẹ jet engine n gbe fò loju ofururu oko ofurufu wa ni iwon ati ipele orisirisi on oniruuru iye apa ti o n gbefo loju orun a le fi oko furufu se ise ero kiko lati ibikan si omiran bakan naa ni awon omo ogun oju-orun ma n loo lati fi sise won gbogbo àwọn bàlúù yí náà ni àwọn awakọ̀ òfurufú ma ń gbé ń fò àmọ́ àwọn ọkọ̀ òfurufú kékèké kan tí wọ́n ń pè ní dúróónù ni wọ́n ma ń fò lókè láì rí awakọ̀ kankan awon egbon ati aaburo kan ti a mo si wright brothers ni won se awari imo ti won fi se oko ofurufu baalu akoko ti won si fi o ni odun 1903 gege bi oko ofurufu nla ti o wuwo ju afefe lo ti o si le da fo won gbe ise won kale s'ori ise akanse ti george caylry se lati odun 1799 nigbati o se agbekale ero baalu igbalode ti o si se awon omiran lati maa gbe awon eniyan fo lati ibikan si omiran ati ise omo ile germany akoko ninu ise igbe eniyan fo ninu oko ofurufu otto lilienthal ohun naa se ise iwadi ijinle l'ori awon oko ofurufu ti o wuwo ju afefe lo l'aarin odun 1867 ati 1896 awom igbiyanju lilienthal lati fo ni odun 1891 ni a ri gege bii ibere fifo awon omo eniyan leyin igba perete ti a fi loo ninu ogun agbaye akoko world war i imo ijinle ninu oko ofurufu te siwaju oko ofurufu ni ifesemule ti o nipon ninu awon ogun gboogi ogun agbaye keji world war ii oko ologun ofurufu akoko je ti omo ile jamani ti a mo si heinkel he 178 ni odun 1939 won se ifilole oko ofurufu elero pupo ni odun 1952 ti oruko re si n je de hailland comet oko ofurufu nla boeing 707 je oko ofurufu elero pupo akoko ti o gbajugbaja ni lilo kaakiri orile agbaye o wa ni enu ise fun odun ti o le die ni aadota lati odun 1958 titi di odun 2013 ka fi mo ni bee |
nina simone nina simone oruko abiso eunice kathleen waymon february 21 1933 april 21 2003 je omo ile amerika akorin oluko orin atepiano atorin ati alakitiyan awon eto araalu to ko orin jazz simone fe di atepiano orin klasik bo se n sise lopo iru orin ti ninu won je klasik jazz blues soul folk rb gospel ati pop botilejepe won woarun aisan isiyemeji aisan iyiwapada lainidi ati skitsofrenia simone gbe awon orin to ju 40 jade opo won larin 1958 — nigba to se debut pelu little girl blue — ati 1974 igbesiaye ati ise igba ewe 19331954 simone was born eunice kathleen waymon in tryon north carolina one of eight children in a poor family she began playing piano at age three the first song she learned was god be with you till we meet again demonstrating a talent with the instrument she performed at her local church but her concert debut a classical recital was given when she was twelve simone later claimed that during this performance her parents who had taken seats in the front row were forced to move to the back of the hall to make way for white people simone said she refused to play until her parents were moved back to the front the incident contributing to her later involvement in the civil rights movement |
ethiopia ethiopia je orile-ede ni agbegbe iha ìlàorùn áfríkà |
jẹ́rmánì |
jamani |
rọ́síà rọ́síà pìpè ˈrʌʃə rọ́síà rossiya tabi orile-ede ìparapọ̀ rọ́sìà rọ́síà je orileijoba ni apaariwa eurasia o je orile-ede olominira sistemu aare die alasepapo to ni ipinle ijoba 83 rosia ni bode mo awon orile-ede wonyi latiariwaiwoorun de guusuilaorun norway finland estonia latvia lithuania ati poland lati egbe kaliningrad oblast belarus ukraine georgia azerbaijan kazakhstan saina mongolia ati north korea o tun ni bode omi mo japan lati egbe okun-omi okhotsk ati amerika lati egbe bering strait |
wikipẹ́díà l'édè yorùbá wikipẹ́díà l'édè yorùbá ni àgbéjáde wikipedia ní èdè yorùbá ó bẹ̀rẹ̀ ní osù kẹwàá ọdún 2002 lọ́wọ́lọ́wọ́ ó ní iye àyọkà àti àwọn oníṣe aforúkọsílẹ̀ wikipẹ́díà l'édè yorùbá ní wikipedia ẹ̀kẹta tótóbijùlọ nínú àwọn wikipẹ́díà l'édè áfríkà lẹ̀yìn èdè lárúwábá àti èdè swahili òhun ni wikipedia 105k tótóbijùlọ nínú àwọn èdè lágbàáyé wikipẹ́díà l'édè yorùbá ti jẹ́ ìkan nínú àwọn wikipedia aṣíwájú 3 tàbí 4 wikipedia l'édè áfríkà bóṣejẹ mọ́ iye àwọn àyọkà tó ní láti ọdún 2008 ní ọdún 2012 ní ibi ìpàdé wikimania 2012 jimmy wales fún ìkan nínú àwọn olóòtú wikipẹ́díà l'édè yorùbá ní ẹ̀yẹ ẹ̀bùn wikipedian of the year fún ìkópa àti iṣẹ́ rẹ̀ lórí wikipẹ́díà l'édè yorùbá |
uniform resource locator uniform resource locator tabi url tabi universal resource locator alawari onaigbekele abamu je oro ti a n lo lori internet |
url |
ìmọ́lẹ̀ ìmọ́lẹ̀ tabi titanina |
obáfẹ́mi awólọ́wọ |
ede yoruba |
ààrẹ ilẹ̀ nàìjíríà ààrẹ orílẹ̀-èdè olómìnira ìjọba àpapọ̀ ilẹ̀ nàìjíríà president of the federal republic of nigeria tàbì ààrẹ ilẹ̀ nàìjíríà lásán ni olórí orílẹ̀-èdè àti olórí ìjọba orílẹ̀-èdè olómìnira ìjọba àpapọ̀ ilẹ̀ nàìjíríà ààrẹ ilẹ̀ nàìjíríà náà tún ni aláṣẹ pátápátá àwọn ológun nàìjíríà àwọn ará nàìjíríà ún dìbò yan ààrẹ fún ọdún mẹ́rin àwọn ipò ààrẹ àwọn agbára àti àwọn oyè olórí orílẹ̀-èdè àti olórí ìjọba jẹ́ dídàpọ̀ sí ipò ààrẹ lábẹ́ òfin-ibágbépọ̀ ilẹ̀ nàìjíríà odún 1979 ààrẹ lọ́wọ́lọ́wọ́ bola tinubu bọ́ sí orí àga ní may 29 2023 gẹ́gẹ́bí ààrẹ 16k orílẹ̀-èdè olómìnira ìjọba àpapọ̀ ilẹ̀ nàìjíríà itan nigbati naijiria di ile apapo oselu olominira ni odun 1963 larin awon orile-ede ajoni o diwo mo ona ijoba igbimo asofin ti o jogun lat'owo ile britani nnamdi azikiwe ti o je gomina agba nigbana di aare ipo to je fun ayeye nigbati ti abubakar tafawa balewa si di ipo alakoso agba mu |
umaru yar'adua |
olusegun obasanjo |
murtala mohammed |
shehu shagari shehu usman aliyu shagari bíi ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọn oṣù keji ọdún 1925-2018 jẹ̣́ olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti ààrẹ ilẹ̀ nàìjíríà lati ọjọ́ kínni oṣù kẹwá ọdún 1979 títí di ọjọ́ ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 1983 nígbàtí àwọn ológun gba ìjọba ìgbé yawo shehu shagari fẹ́ ìyàwó mẹtaamina aisha àti hadiza shagari bí ọmọ púpò lára wọn nimuhammad bala shagari àti aminu shehu shagari ní ọdún 2001 ọjọ́ kẹfà dín ni ọgbọ́n ìyàwó rè aisha shagari kú ní ilé ìwòsàn kàn ní lọ dòní ílẹ́yìn sì kí nesi kékeré ganàìsàn covidi ni ó pá ìyàwó shehu shagari ní ọdún 2021 ìgbà tí òkú ni ó jọ méjì dín lọ gbọn oṣù kejìlá ni ọdún 2018 ni ọwọ irole ìṣàn rán pé ní o pá ogbeni shehu shagari ni ìwòsàn àpapọ̀ kàn ní abuja àwọn ìtọ́kasí |
johnson aguiyi-ironsi johnson thomas umunnakwe aguiyi-ironsi ọjọ́ 3oṣù ẹ̀rẹ̀nà ọdún 1924 - ọjọ́ 29 oṣù agẹmọ ọdún 1966 jẹ́ ológun ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà lẹ́yìn tí ológun gba ìjọba ní ọjọ́15 oṣù ṣẹrẹ ọdún1966 aguiyi-ironsi di olórí orílẹ̀-èdè nàìjíríà títí di ọjọ́ 29 oṣù agẹmọ ọdún1966 nígbà tí wọ́n dìtẹ̀ sí ìjọba rẹ̀ tí wọ́n sì pa á ìgbà èwe a bí i ní ìlú umuahia tó wà ní ìpínlẹ̀ abia lónìí ní ọjọ́ kẹ́ta osù kẹ́ta ọdún 1924 fún mazi àti ezugo aguiyi nígbà tó pé ọmọ ọdún mẹ́jọ̀ aguiyi-ironsi kó lo sí ọ̀dọ̀ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ obìnrin anyamma ẹni tó jẹ́ aya theophilius johnson to jẹ́ òṣìṣẹ́ asojú ìjọba fún ilẹ̀ sierra leone ní umuahia nígbà tó tó ọmọ ọdún méjìdínlógún ironsi bọ́ sí iṣẹ́ ológun nàìjíríà botilejepe egbon re lodi si iṣẹ́ rẹ̀ nínú iṣẹ́ ológùn ní ọdún 1942 aguiyi-ironsi dara pọ̀ mọ àwọn ológun gẹ́gẹ́ bí àwọn ọmọ ogun onípò méje ó gbà ìgbéga lẹ́nu iṣẹ́ rẹ̀ ní ọdún 1946 sí ipò méjọ̀ ságéńtì bẹè náà ni wọ́n rán aguiyi-ironsi lọ sí ilé-ìwé staff college camberley england ní ọdún 1946 lẹ́yìn tí ó parí ìwé rẹ̀ ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọ̀gágun kejì ní royal west african frontier force ní ọjọ́ kejìlá oṣù ogúdù ọdún1949 aguiyi-ironsi gba àṣẹ ìgbìmọ̀ ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù èbìbí ọdún 1953 aguiyi-ironsi jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ-ogun tí ó sin ọbabìnrin elizabrth ii tí united kingdom àti ìgbà tí ó wà ní ilẹ̀ nàìjíríà ní ọdún 1956 ní1960 aguiyi-ironsi di ọ̀gá fún àwọn ọmọ-ogun onípò karùn-ún ní ìlú kano orílẹ̀-èdè nàìjíríà pẹ̀lú ìpò ọgáju nínú ọdún 1960 náà ni aguiyi di adarí àwọn ọmọ-ogun àpájàwìrì ti ìlú united nations operation in the congo ní oṣù ṣẹrẹ ọdún 1966 ọ̀gágu chukwuma nzeogwu darí àwọn ọmọ-ogun láti gba agbára lọ́wọ́ àrin-gbùngbùn àti ìjọba agbègbè orilè-èdè nàìjíríà wọ́n pa olórí ìjọba wọ́n sì gbìyàjuh láti gbà ìjọba ṣùgbón wọ́n kùnà nínú ọ̀tẹ̀ wọ́n ọ̀gágun aguiyi-ironsi ṣégun nzeogwu ó sìn tì í sẹ́wọ̀n ọjọ́ mẹ́tàdínlógún oṣù ṣẹrẹ ọdún 1966 aguiyi-ironsi dí olórí orílẹ̀-èdè ó sì di ipò yìí mú títí di ọjọ́ kankàndílọ́gbọ̀n oṣù ṣẹrẹ ọdùn 1966 nígbà tí àwọn ológùn àríwá gbógùn ti ìjọba rẹ̀ tí wọ́n sì pa aguiyi-ironsi |
umuahia umuahia ni ìlú tí ó jẹ́ olú-ìlú ìpínlẹ̀ abia ní gúúsù ìlà oòrùn orílè-èdè nàìjíríà umuahia wà lọ́nà oju irin tí ó wà láàrin port harcourt àti ìlú enugu àwọn ẹ̀yà igbo ni ó wọ́pọ̀ ní umuahia umuahia ní olùgbé 359230 gẹ́gẹ́ bí àbáyọ rí ounka ènìyàn ọdún 2006 ní nàìjíríà ṣe fi léde àwọn ẹ̀yà igbo ni ó wọ́pọ̀ ní umuahia umuahia ní agbègbè ijoba ìbílẹ̀ méjì umuahia north àti umuahia south |
biafra biafra tí a mọ̀ sí orílẹ̀-èdè biafra jẹ́ ìlú tó yapa kúrò nínú apá ìwọ̀-oòrùn áfíríkà tí ó gba òmìnira ní nàìjíríà láàárín ọdún 1967 títí di ọdún 1970 àwọn ẹ̀yà ìgbò ní apá ìlà oòrùn nàìjíríà ni wọ́n kún bẹ̀ fọ́fọ́fọ́ ọgbọ́n ọjọ́ oṣù èbìbí ọdún 1967 ni ológun àti gómìnà ẹkùn ìlà oòrùn c odumegwu ojukwu dá biafra sílẹ̀ lẹ́hìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ làásìgbò ẹlẹ́yà ẹtà àti ìdìtẹ̀gbàjọba lẹ́yìn òmìnira orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní ọdún 1960 tí èyí sì yọrísí ìpakúpa àwọn ìgbò àti àwọn ẹ̀yà mìíràn tí wọ́n ń gbé ní àríwá orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní ọdún 1966 lẹ́hìn náà ni àwọn ọmọ ogun orílẹ̀-èdè nàìjíríà kógun ja biafra lẹ́hìn ìyapa èyí ṣokùnfàfà ìbẹ̀rẹ̀ ogun abẹ́lé orílẹ̀-èdè nàìjíríà àwọn ìlú bí haiti ivory coast tanzania àti zambia ni wọ́n rí biafra bí orílẹ̀-èdè tó kẹ́sẹ járí ṣùgbọ́n àwọn orílẹ̀-èdè yòókù tí kò mọ̀ wọ́n lábẹ́ òfin pèsè ìrànwọ́ ọlọ́gbọ́n ìṣèlú àgbà tàbí ajẹmọ́ ológun fún biafra lára wọn ni france spain portugal norway israel rhodesia south africa àti vatican city biafra gba ìrànwọ́ láti ọ̀dọ̀ àwọn àjọ tí kò rọ̀gbọ̀ lé ìjọba lára wọn ni joint church aid àwọn ajaguntà ilẹ̀ òkèèrè holy ghost fathers of ireland bẹ́ẹ̀ sì ni pẹ̀lú ìdarí wọn caritas internationals àti àwọn ètò ìrànwọ́ àgùdá tí u s bákan náà ni ìdásílẹ̀ san frontieres wáyé gẹ́gẹ́bí èsì sí ìyà náà |
ẹnúgu enugu je oluilu ipinle enugu ni ile naijiria |
ogun abele nigeria ogún abẹ́lé ilẹ̀ nàìjíríà wáyé láàárín ọjọ́ kẹfà oṣù okúdù ọdún 1967 sí ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù ṣẹ́ẹ́rẹ́ tí a tún mọ̀ sí ogun nàìjíríà - biafra tàbí ogun biafra jẹ́ ogun abẹ́lé tí ó wáyé láàárín ìjọba nàìjíríà àti orílè-èdè biafra ìpínlẹ̀ tí ó fé dádúró tì ó ti fẹ́ gba òmìnira kúrò lára nàìjíríà ní ọdún 1967 ọgágun yakubu gowon ni ó ń darí orílẹ̀èdè nàìjíríà lt colonel odumegwu ojukwu sí ń darí biafra èròngbà àwọn olùfẹ́ ẹ̀yà ìgbò tí wọ́n rò pé àwọn kò lè bá ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ṣe pọ̀ mọ torí pé àwọn mùsùlùmí ẹ̀yà haúsá-fúlàní tí àríwá orílẹ̀èdè nàìjíríà tí jẹ gàba ní biafra ìyọrísí ìkọlù yìí láti rògbòdìyàn ìṣèlú ọrọ̀ ajé ẹ̀yà ajẹmáṣà àti ẹ̀sìn ló bí pínpín nàìjíríà láti ọdún 1960 sí 1963 lára àwọn aṣokùnfà ogun ní ọdún 1966 ni ìjà ẹ̀sìn àti ìṣègbè ẹ̀yà ìgbò ní apá àríwá nàìjíríà ìdìtẹ̀gbàjọba àti ìrẹ́jẹ àwọn ìgbò ní apá àríwá naijiria bákan náà ìjẹ gàba lórí ìgbéjáde epo rọ̀bì tó lérè gọbọi lórí ní apa niger delta náà kópa ribiribi nínú ogun abẹ́lé náà láàárín ọdún kan àwọn ọmọ ogun ilẹ̀ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ti yí gbogbo kọ̀rọ̀-kọ́ndú ilẹ̀ ìgbò biafara po tí ó fi mọ́ orísun epo tí ó wà ní ìlú port harcourt wọ́n mọ odi yí wọn ká tínwọn kò sì gbà kí ẹnikẹ́ni nínú ẹ̀yà ìgbò ó jáde síta èyí f a ebi ọ̀pàgbà f'ọwọ́-mẹ́kẹ́ fún tẹ́rú tọmọ wọn láàárín ọdún méjì ati abọ̀ tí ogun náà fi wáyé iye àwọn tí wọ́n jẹ́ ọmọ ẹ̀yà ìgbò tí wọ́ ṣ'aláìsí láti ọwọ́ àwọn ọmọ ogun ilẹ̀ orílẹ̀-èdè nàìjíríà jẹ́ ọgọ́rún kan nígbà tí iye àwọn tí wọ́n ṣ'aláìsí látàrí ebi òpàpàpàlà jẹ́ mílíọ́nù lọ́nà ọgọ́rùn-un márùn-ún ènìyàn nígbà tí yóò fi di àárín ọdún 1968 àwọn oníròyìn bẹ̀rẹ̀ sí ń fi àwòrán àwọn àgbà àti ọmọdé tí ebi ti sọ di aláabọ̀ ara nínú àwọn ẹ̀yà ìgbò léde nínú àwọn ìwé ìròyìn tí wọ́n ń jáde ní àwọn orílẹ̀-èdè òkèrè àwòrán àwọn tí ebi ń pa wọ̀nyí beeẹ̀ sí ń mú kí àwọn ará ilẹ̀ òkèèrè ó beeẹ̀ sí ń fi oju àánú wo àwọn ènìyàn wọ̀nyí tí ó sì mú kí àwọn àjọ 3lẹ́yinjú àánú tí kìí ṣe ti ìjọba ó ma dá owó ounje aṣọ àti àwọn ohun ìgbáyé-gbádùn mìíràn ránṣẹ́ sí wọn orílẹ̀-èdè united kingdom àti soviet union ni wọ́n fẹ̀yìn pọn orílẹ̀-èdè nàìjíríà láti bori biafra nígbà náà nígbà tí orílẹ̀-èdè france àti isreal ṣagbátẹrù fún àwọn biafra láti kojú orílẹ̀-èdè nàìjíríà padà àmọ́ àwọn amẹ́ríkà ní ti wọn kò ṣ'ègbè lẹ́yìn ẹnìkọkan wọ́n kò fara mọ́ ìfìyà-jẹni tí orílẹ̀-èdè nàìjíríà ń fi jẹ àwọn igbo yí bákan náà ni wọ́n bu ẹnu atẹ́ lu ìgbàẹ́sẹ̀ ìyapa àwọn biafra kúrò lára orílẹ̀-èdè nàìjíríà ohun ti bo fa ogun yí ẹlẹ́yà-m'ẹ̀yà ohun àkókọ́ tí ó fa ogun yí ni ó níṣe pẹ̀lú ìdàpọ̀ gbogbo ẹ̀yà orílẹ̀-èdè nàìjíríà lásìkò ìṣèjọba àmúnisìn ní ọdún 1914 èyí ni dídá northern protectorate lagos colony àti southern nigeria protectorate tí a tún mọ̀ sí eastern nigeria papọ̀ láti lè jẹ́ kí ìṣèjọba orílẹ̀-èdè náà ó f'ẹsẹ̀ múlẹ̀ nítorí gbígòòrò tí àwọn agbègbè orílẹ̀-èdè tí a ti mẹ́nu bá lókè yí gbòòrò tí oríṣiríṣi ẹ̀yà sì wà ní ibẹ bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ìdàpọ̀ yí kò fiyè sí ìyàtọ̀ tí ó wà láàárín ẹ̀yà èdè ati ẹ̀sìn tí ó wà láàárín àwọn ènìyàn ilé nàìjíríà lásìkò náà èyí ni ó mú ìbérù ati ìfòyà ó gbilẹ̀ nínú wọn tí ó sì mú kí kálukú àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí ó ma jìjàgùdù lórí ìṣèlú ara-ẹni àti ìmójútó okòwò ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan orílẹ̀-èdè nàìjíríà gb'òmìnira lọ́wọ́ ìjọba àmúnisìn ilẹ̀ britain ní ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá ọdún 1960 nígbà tí gbogbo àwọn ènìyàn tí wọ́n jẹ́ olùgbé ibẹ̀ náà jẹ́ mílíọ́nù márùndínláàdọ́ta ó dín diẹ̀ nígbà tí iye ẹ̀yà tí ó wà níbẹ̀ jẹ́ ọgbàọ́rùn ún mẹ́ta nígbà tí orílẹ̀-èdè nàìjíríà gba òmìnira àwọn agbègbè tí wọ́n tóbi jùlọ ni àsìkò náà ni apá ìlà oòrùn tí àwọn ẹ̀yà igbò ea lásìkò yí wọ́n kó ìdá 6070 nínú iye ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àwọn hausa-fulani lábẹ́ ìṣèjọba ilẹ̀ sultanate of sokoto ni wọ́n kó ìdá 67 lápá òkè ọya bákan náà ni àwọn yorùná ní apá ìwọ̀-oòrùn orílẹ̀-èdè náà kò ìdá 75 lóòtọ́ àwọn ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan wọ̀nyí ni wọ́n ní ilẹ̀ tiwọn tí wọ́n sìntú fọ́nká sí orígun orílẹ̀-èdè náà nígbà tí ogun náà bẹ́ sílẹ̀ ní ọdún 1967 iye àwọn ọmọ ẹ̀yà igbo tí wọ́n wà ní àwọn orígun ilẹ̀ nàìjíríà kò sàn ní ẹgbẹ̀rún márùún pàá pàá jùlọ ní ìlú èkó |
ogun biafra |
odumegwu ojukwu chukwuemeka odumegwu-ojukwu a bíi ní ọjọ́ kẹrin oṣù kọkànlá ọdún 1933 - ó sì kú ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kọkànlá ọdún 2001jẹ́ ológun àti òsèlú ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tẹ́lẹ̀ ó fìgbà kan jẹ gómìnà ológun apá àríwá nàìjíríà lọ́dún 1966 oun ló ṣe égbátẹrù ogun abẹ́lé biafra fi tako ìjọba orile-ede nàìjíríà lọ́dún 1967 sí 1970 |
mùsùlùmí musulumi je eni ti o ti gba esin islam |
yola yola di olú-ìlú àti ìlú tí ó tóbi jù ní f ìpínlẹ̀ adamawa nàìjíríà ìlú náà wà ní olùgbé 336648 ní ọdun 2010 yola pín sí méjì àwọn ni ìlú yola àtijó níbi tí lamido ìlú náà gbé àti ìlú jimeta ìlú jimeta ní àárín ètò ọ̀rọ̀ ajé yola |
yola nigeria <ns>0</ns> <revision> <timestamp>2008-02-18t184319z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> </contributor> <comment>yola nigeria moved to yola</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> |
eṣinṣin àwọn eṣinṣin jẹ́ kòkòrò ninu ito awon oníyẹ̀ẹ́meji diptera lati ede griiki di = meji ati ptera = iye iyato won kedere si awon kokoro miran ni esinsin ni iye ifo meji ni aya-arin ati pair of haltere meji to wa lati iye eyin ni aya-ikeyin awon irueda esinsin kan yato nitoripe won ko le fo awon kokoro miran ti won tun ni iye to unsise ati iru halteres kan ni strepsiptera won si yato si awon esinsin nitoripe awon strepsiptera ni halteres won ni aya-arin ati iye ifo won ni aya-ikeyin |
ẹṣin ẹsin the horse equus ferus caballus is a domesticated odd-toed hoofed mammal it belongs to the taxonomic family equidae and is one of two extant subspecies of equus ferus the horse has evolved over the past 45 to 55 million years from a small multi-toed creature eohippus into the large single-toed animal of today humans began domesticating horses around 4000 bc and their domestication is believed to have been widespread by 3000 bc horses in the subspecies caballus are domesticated although some domesticated populations live in the wild as feral horses these feral populations are not true wild horses as this term is used to describe horses that have never been domesticated there is an extensive specialized vocabulary used to describe equine-related concepts covering everything from anatomy to life stages size colors markings breeds locomotion and behavior horses are adapted to run allowing them to quickly escape predators possessing an excellent sense of balance and a strong fight-or-flight response related to this need to flee from predators in the wild is an unusual trait horses are able to sleep both standing up and lying down with younger horses tending to sleep significantly more than adults female horses called mares carry their young for approximately 11 months and a young horse called a foal can stand and run shortly following birth most domesticated horses begin training under a saddle or in a harness between the ages of two and four they reach full adult development by age five and have an average lifespan of between 25 and 30 years |
uyo uyo ni olú-ìlú ìpínlẹ̀ akwa ibom ní guusu nàìjíríà ibibio ni èdè tí wón sọ ní ìlú uyo uyo di olú-ìlú ìpínlẹ̀ akwa ibom ní ọjọ́ ketalelogun oṣù kẹsànsept 23 ọdún 1987 nígbà tí akwa ibom yapa kúrò lára ìpínlẹ̀ cross river gẹ́gẹ́ bi àbájáde ètò ìkànìyàn nàìjíríà ọdún 2006 iye àwọn ènìyàn tí ó ń gbé uyo àti ní ìlú itu jẹ́ 427873 |
òṣogbo òṣogbo jẹ́ ìlú ńlá kan ní ìpílẹ̀ ọ̀ṣun ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà bákan náà ni ó jẹ́ olú ìlú fún ìpínlẹ̀ náà ní apá ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ nàìjíríà ọ̀gbẹ́ni gbóyèga òyètọ́lá ni gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun lọ́wọ́lọ́wọ́ òṣogbo di olú ìlú fụ́n ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun ní ọdun 1991 bákan náà ni ó tún jẹ́ olú ilé-iṣẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ fún ìlú òṣogbo tí ilé-iṣẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ náà sì wà ní òke báálẹ̀ nígbà tí ìjọba ìbílẹ̀ ọlọ́rundá ń ṣojú agbègbè ìgbóǹnà nílú òṣogbo |
paul kagame <ns>0</ns> <revision> <parentid>524146</parentid> <timestamp>2019-11-06t114500z</timestamp> <contributor> <ip>2121570218</ip> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> paul kagame ojoibi 23 october 1957 lowolowo ni aare orile-ede olominira ile ruwanda ikefa |
rwanda orile-ede olominira ile rwanda je orile-ede ni apa ilaoorun afrika |
kigali kigali je oluilu orile-ede rwanda |
bùrúndì bùrúndì pipe lonibise bi orílẹ̀-èdè olómìnira ilẹ̀ bùrúndì buˈɾundi je orile-ede ademolesarin ni agbegbe awon adagun ninla ni apailaorun afrika to ni bode mo rwanda ni ariwa tanzania ni ilaorun ati guusu ati orile-ede olominira oloselu ile kongo ni iwoorun oluilu re ni bujumbura botilejepe orile-ede na je ademolesarin opo bode re ni apa guusuiwoorun wa niwaju adagun tanganyika awon twa tutsi ati hutu ni won ti ungbe ni burundi latigba ti orile-ede na ti je didasile ni orundun marun seyin burundi je jijoba lelori bi ileoba latowo awon tutsi fun ogorun meji odun sugbon latibere orundun ogun jemani ati belgium gba ori ibe won si so ibe di ileamusin to ruko re unje ruanda-urundi cobalt ati baba ni meji ninu awon ohun alumoni ti burundi ni bakanna burundi unta kofi ati suga àwọn ìpínlẹ̀ ìjọba <ns>10</ns> <id>16733</id> <revision> <id>534273</id> <parentid>122075</parentid> <timestamp>2020-05-17t152113z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> <id>193</id> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> burundi jẹ́ pípín sí ìgbèríko 18 117 communes and 2638 collines hills provincial governments are structured upon these boundaries in 2000 the province encompassing bujumbura was separated into two provinces bujumbura rural and bujumbura mairie the newest province rumonge was created on 26 march 2015 from portions of bujumbura rural and bururi |
wole soyinka |
ebun nobel |
samuel akintola <ns>0</ns> <revision> <parentid>411621</parentid> <timestamp>2013-02-11t181756z</timestamp> <contributor> <username>xqbot</username> </contributor> <minor /> <comment>robot fixing double redirect to samuel ladoke akintola</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> |
ladoke akintola |
action group ẹgbẹ́ ìṣèlú action group jẹ́ ìkan nínú àwọn lààmì-laaka ẹgbẹ́ òṣèlú ajìjà òmìnira fún orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí wọ́n dá sílẹ̀ ní ìlú ìbàdàn n inú oṣù kẹta ọdún 1951 láti ọwọ́ alagba ọbáfẹ́mi awólọ́wọ̀ ìdí tí wọ́n fi dá ẹgbẹ́ yí sílẹ̀ ni láti rú ìmọ̀sílára àwọn ọmọ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà láti gbé ìgbésẹ̀ àti darapọ̀ mọ́ àwọn ẹgbẹ́ ìṣèlú tókù gba òmìnira àti láti dá ẹgbẹ́ ìṣèlú ncnc lọ́wọ́ kọ́ pàá pàá jùlọ ní apá ìwọ̀-oòrùn orílẹ̀-èdè nàìjíríà àwọn ikọ̀ tí wọ́n jẹ́ àpapọ̀ ẹgbẹ́ ọmọ odùduwà tí alàgbà ọbáfẹ́mi awólọ́wọ̀ dá sílẹ̀ nígbà tí ó wà ní london gẹ́gẹ́ bí akẹ́kọ̀ọ́ ìtàn egbé òsèlú náà ni odun 1941 obafemi awolowo bèrè egbé nigerian youth movement ní ìlú ibadan láti ma kó awon òtòkùlú ìlú tí o kàwé ni odun 1945 awolowo tún dá egbé omo oduduwa sílè láti mu ki isopo wa larin yoruba wón ni egbé náà ji se egbe òsèlú sùgbón o wa fun tokunrin tobinrin ile yorùbá láti mu idagbasoke bá yorùbá òpòlopò eniyan ní ìwò-oorun nàìjíríà ló se atileyin fun egbé náà ni march 21 odun 1951 oloye obafemi awolowo da egbé action group kalè ni ìlú ibadan ni osu kerin odun 1951 oloye samuel akinsanya mú àbá wa pé kí wón pé àwon òtòkùlú ènìyàn ní ìwò-oorun nàìjíríà láti darapò mó egbé òsèlú náà òpòlopò òtòkùlú oloye ni o kopa ninú ipade tí o wáyé ni ìbàdàn ní osù kèwá dun 1951 láti da egbé òsèlù náà kalè bi o tilè jé wipé dókítá alabere akinola maja ti o dari ipade náà ki ise oloye |
greesi |
yúrópù |
islàm |
ìjọba ìbílẹ̀ bẹ́núé benue benue ado agatu apa buruku gboko guma gwer east gwer west katsina ala konshisha kwande logo makurdi obi ogbadibo ohimini oju okpokwu otukpo tarka ukum ushongo vandeikya |
chima nwafor chima nwafor alaisi 25 march 2005 je oloselu omo ile naijiria ati igbakeji gomina ipinle abia si orji kalu o ku ni march 21 2005 won si sin in ni september 2 2006 ni ulu re ni umuojima ni ipinle anambra ko pe ti won yo o kuro ni ori oye ti o fi ku won se isn idagbere fun un ni st clement's anglican church umuojima ni osisioma nwa local government ni ipinle anambra alufaa ti o se isn fun un ni ugochuchwu ezeoke |
za za je ti orile-ede guusu afrika |
ìpínlè oyo <ns>0</ns> <revision> <parentid>20277</parentid> <timestamp>2008-08-30t195729z</timestamp> <contributor> <username>redirect fixer</username> </contributor> <comment>ipinle oyo has been moved it is now a redirect to ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> |
adebayo alao-akala christopher adébáyọ̀ àlàó akálà ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹ́ta oṣù kẹfà ọdún 1950 ó sì kú ní ọjọ́ kejìlá oṣù kínní ọdún 2022 1950 - 2022 christopher adébáyọ̀ àlàó akálà jẹ́ olóṣèlú àti gómìnà nígbà kan rí ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ní ọdún 2019 ó díje dupò gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ lẹ́ẹ̀kan si lábẹ́ ẹgbẹ́-òṣèlú action democratic partyadp ṣùgbọ́n ó yára dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ all progressive partyapc kí ìdìbò ó tó wáyé christopher adébáyọ̀ àlàó akálà jẹ igbakeji gomina ipinlẹ ọyọ lati oṣu karun-un ọdun 2003 si oṣu kinni ọdun 2006 ti o tẹle rashidi ladoja nigba ti wọn yọ ọ lẹnu ṣugbọn nigba to tun pada si ọfiisi nigba ti ladoja pada sipo ni oṣu kejila ọdun 2006 ni ọdun 2007 ni wọn dibo yan gomina o tun di ibo lodun 2011 fun abiola ajimobi ti action congress of nigeria o ku ni ọjọ 12 oṣu kini ọdun 2022 |
christopher adebayo alao-akala |
christopher alao-akala |
ipinle lagos |
theodore orji theodore ahamefule orji ni wọ́n bí ní 11/11/1950 ó jẹ́ olóṣèlú ará ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ abia láti ọdún 2007 títí dé 2015 ní ìgbàkan rí ó jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba àti pé ó jẹ́ olórí àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba ní abẹ́ gómìnà orji uzor kalu ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú pdp lọ́wọ́lọ́wọ́ |
robert menzies robert gordon menzies je oloselu omo ile australia ni menzies a bi i ni 1894 o je olootu ijoba ile australia fun odun mokandinlogun ilu jepart ni won ti bi i ni victoria o gba oye ninu ofin ni university melborne ni aarin 1928 si 1934 o wa ni victoria state legislature nigba ti o se o wo federal house of representative o di attorney general ile australia ni aarin 1935 si 1939 leyin igba ti j a lyons ku ni menzies wa di olootu australia o fi ori oye sile funraare ni 1966 |
olusegun agagu olusegun kokumo agagu born 16 february 1948 je oloselu omo ile naijiria ati gomina ipinle ondo lati 29 may 2003 titi di 23 february 2009 nigbati ile-ejo alatunejoda ni ilu benin fagile idiboyan april 2007 nitori pe ko bo fin mu wọ́n bí i ní ferbruary 16 1948 ní òkìtìpupa ondo state ó bẹ̀rẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ ní st luké’s anglican school òkìtì pupa ní 1954 ó tún lọ sí ebenezer methodist school òkè-àdó ìbàdàn ní 1958 ó tún lọ sí baptist primacy school sabon-gari kano ó wá parí ẹ̀kọ́ primary school rẹ̀ ní ebenezer african church school ibadan lẹ́yìn èyí ó lọ sí ìbàdàn grammar school ní 1961 lẹ́yìn èyí ó lọ sí university ìbàdàn láti ka botany torí pé ó mọ geology dáadáa wọ́n fún un ní ẹ̀kọ́-ọ̀fẹ́ gulf oil láti ka geology lẹ́yìn ọdún kìíní lẹ́yìn ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní university ó bá guif oil ṣiṣẹ́ fún ọdún méjì kí ó tó wá gbṣẹ́ sí university of ìbàdàn gẹ́gẹ́ bí assistant lecturer ní 1972 ó lọ kàwé fún oye master rẹ̀ ní university of texas láàrin 1973 sí 1974 ó gbá phd ní petroleum geology ní ní university of ìbàdàn ní 1978 ní 1988 ó fi ui sílẹ̀ ó sì bẹ̀rẹ̀ síi ṣe òṣèlu kò pé lẹ́yìn èyí ó di igbákejì gómínà ìpínlẹ̀ oǹdó o sì ti bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe gómìnà ìpínlẹ̀ oǹdó láti 2003 títí di ìgbà tí a ń kòwé yòí ní 2008 |
ìpínlẹ̀ mississippi <ns>0</ns> <revision> <parentid>516552</parentid> <timestamp>2023-09-25t091853z</timestamp> <contributor> <username>internetarchivebot</username> </contributor> <comment>rescuing 1 sources and tagging 0 as dead #iabot v2095</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> mississippi ipinle kan ni ile amerika ni o n je mississippi awon eniyan ti o wa nibe to 2217000 olu-ilu ibe ni jackson awon ara panyan-an wa si ile yii ni 1540 awon ara faranse wa do si ibe 1699 awon ara geesi segun awon faranse ni 1763 ni odun 1817 ni mississippi dara po mo union awon eru po ni ibe o si ni opolopo plantation o duro ti awon confederate ninu ioja abele ile amerika odo kan wa ni ipinle yii ti o n je mississippi odo yii ni o gun nju ni ile amerika ti a ba pa odo yii ati missouri po awon ni o gun ju ni gbogbo aye mississippi gun to maili 2350 oun ati missouri gun to 3700 ni ibuso odun 1541 ni won se awari mississippi ni memphis tennessee omo ile panyan-an ti o se awari re ni won n pe ni hernando de soto |
ìpínlẹ̀ missouri missouri je ipinle kan ni ile amerika aarin gbungbun iwo-oorun ile amerika ni ipinle yii wa oke kan ti o n je ozark mountain wa nibe ibe naa ni omi kan ti o n je missouri wa apapo omi missouri yii ati mississippi ni odo ti o gun ju ni agbaye ile-ise po ni ipinle tii awon eniyan ti o n gbe ibe to 4667000 jefferson city ni olu-ilu missouri sugbon st louis ati kasas city ni awon ilu ti o tobi ju nibe awon ile faranse ni o gba missouri 1673 ati 1682 awon ile amerika gba a ni 1803 o si di ipinle ni 1821 ninu ogun abel ile amerika awon union ni missouri ja fun |
mojave desert asale mojave california ni asale yii wa ni iwo-oorun amerika awon nnkan ti o wa ni asale yii ni yanrin okuta volcanic rock ati awon adagun odo lake ti o ti gbe o fe to 15000 square mile loooto won ko le dako ni mojave desert won maa n ri awon ohun alumo-onni ile bii goolu silifa ati tungsten ni ibe |
afríkà |
de de je ti ile jẹ́mánì |
odun todogba <ns>0</ns> <revision> <timestamp>2008-02-24t014840z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> </contributor> <comment>redirecting to ọdún tódọ́gba</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> |
apa ilaoorun afrika |
kofi annan kofi atta annan 8 april 1938 - 18 august 2018 je omo orile-ede ghana to je diplomati to wa ni ipo gege bi akowe agba keje agbajo iparapo awon orile-ede lati 1 january 1997 de 31 december 2006 annan ati agbajo iparapo awon orile-ede jo gba ebun nobel fun alafia ni 2001 |
iposieniyan |
blu-ray disc blu-ray disc blu-ray tabi bd je akaaba olojuina-ribiti amounmaworan optical-disc media storage |
walter raleigh <ns>0</ns> <revision> <parentid>414255</parentid> <timestamp>2013-03-08t024411z</timestamp> <contributor> <username>addbot</username> </contributor> <minor /> <comment> migrating 40 interwiki links now provided by on </comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> walter raleigh a bi i ni 1552 o ku ni 1618 soja omo ile geesi ni o si maa n rin irinajo pupo oun ni o mu taba wa si ile geesi ti o si mu 'potato' wa si ireland oun ati sir humphrey gilbert ti o je half-brother ni won jo ja ni ile amerika o tun ja fun ile geesi ni ireland iwe history of the world ti o ko ko pari re titi ti o fi ku won pa a ni nitori pe ko pa ofin mo |
eku eku orisii meji lo wa dudu ati pupa resuresu brown awon eku maa n gun ni iwon insi merindinlogun ninu eyi ti insi mejo re maa n je iru won maa n ba nnkan je pupo ni pataki awon ti o dudu ni laboretiri won maa n sin awon eku funfun kan ti won fi maa n se iwadii |
mẹ́ksíkò àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́síkò aṣọ̀kan estados unidos mexicanos lédè sípéènì tàbí mẹ́síkò ní ṣókí jẹ́ orílẹ̀-èdè ní apá àríwá amẹ́ríkà èdè sípéènì ni wọ́n ń sọ níbẹ̀ apá gúúsù orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà ló wà àwọn ọmọ sípéènì ṣẹ́gun mẹ́síkò lọ́dún 1519 ọ̀pọ̀ àwọn mestizo wà nínú àwọn ènìyàn tó wà ní mẹ́síkò ìyẹn ni àwọn tí òbí wọn jẹ́ apá kan òyìnbó àti apá kan ọmọ ìbílẹ̀ mẹ́síkò lọ́dún 1821 orílẹ̀-èdè yìí gbà òmìnira lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìjà àti ogun wọ́n di orílẹ̀-èdè olómìnira lọ́dún 1824 |
michigan michigan je okan ninu awon ipinle ti o loro ju ni ile amerika ni michigan o fi egbe ti canada ati awon great lakes maraarun awon eniyan to n gbe ibe to 8 875000 won n se kaa pupo ni ipinle yii nitori pe won ni irin detroit je okan lara awon ilu pataki ti won ti n se kaa ni michigan awon ara ile faranse ni o koko te michigan do ni nnkan bii 1600 awon geesi gba a lowo won ni 1763 michigan di ipinle kerindinlogbon ni ile amerika ni 1837 |
ye ye ni amioro orile-ede top-level domain cctld ori internet fun yemen |
wf wf je ti wallis and futuna islands |
vu vu |
vn vn |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.