raw_text
stringlengths
2
128k
balarabe musa balarabe musa je omo orile-ede naijiria ati gomina ipinle kaduna tele
abdulkadir balarabe musa
abba musa rimi abba musa rimi je omo orile-ede naijiria ati gomina ipinle kaduna tele
lawal kaita lawal kaita jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ kàdúná tẹ́lẹ̀
abubakar dangiwa umar abubakar dangiwa umar je omo orile-ede naijiria ati gomina ipinle kaduna tele
tanko ayuba tanko ayuba je omo orile-ede naijiria ati gomina ipinle kaduna tele
mohammed dabo lere mohammed dabo lere je omo orile-ede naijiria ati gomina ipinle kaduna tele
lawal jafaru isa lawal jafaru isa je omo orile-ede naijiria ati gomina ipinle kaduna tele
hammed ali hammed ali je omo orile-ede naijiria ati gomina ipinle kaduna tele
ahmed makarfi ahmed makarfi je omo orile-ede naijiria ati gomina ipinle kaduna tele
ojueweakoko/eka/jeografi • • • • • • • • • • • • •
ojueweakoko/eka/itan • • • • • •
ojueweakoko/eka/asa • • • • • • • • •
ojueweakoko/eka/adanida • •
ojueweakoko/eka/esin • • • • • • • • • • • • •
islam
ojueweakoko/eka/awujo • • • • •
ojueweakoko/eka/ede • •
ojueweakoko/eka/teknoloji • • •
ìmọ̀nàmúṣe
ojueweakoko/eka/sayensi • • • • • • • •
dan quayle james danforth dan quayle ojoibi february 4 1947 lo je igbakeji aare orile-ede amerika ikerinlelogoji labe aare george h w bush 19891993 tele o je asoju ati alagba asofin lati ipinle indiana
miguel juan sebastián piñera echenique
detroit michigan
erykah badu erica abi wright ojoibi 26 oṣù kejì 1971 to gbajumo pelu oruko ori-itage erykah badu je omo orile-ede amerika akorin atokun awo-orin ati osere ise-owo re po mo lati rb hip hop ati jazz o kopa gidigidi ninu igbooro iru orin neo soul ati iru ona toyato to fi n korin ati ona oge re o je mimo gege bi iyafin akoko neo-soul first lady of neo-soul tabi ayaba neo-soul the queen of neo soul
erica abi wright
òfin òfin je sistemu awon ilana kan to se gbe ro nipa ikojopo awon ifidimule kan o un tona iselu ekonomiki ati awujo lorisirisi ona o si je olulaja akoko lawujo fun ibasepo larin awon eniyan ofin adehun un setona ohun gbogbo latori rira tiketi oko de idunadura ni ile pasiparo ofin ohun ini n setoka awon eto ati ojuse to jemo fifun ati nini ohun ini araeni ti a n pe ni ẹrù ati ohun ini gidi bi ile ti ko se mu kuro ofin igbalawin je mo dukiya ti a fi pamo fun idaabo inawolori ati oninawo nigbati ofin ibaje gbani laaye lati gba esan atunse ti eto tabi ohun ini eniyan ba bibaje lowo elomiran ti ibaje yi ba je sisododaran ninu iwe ofin ofin odaran ni yio so bi ijoba yio se fi esun kan iru eni be ofin ibagbepapo un pese ona dida ofin idaabo bo awon eto omoniyan ati idiboyan awon asoju oloselu ofin amojuto lo n sagbeyewo awon ipinu awon ile-ise ijoba nigbati ofin akariaye un dari ìṣe larin awon orile-ede lati tona idunadura ayika tabi imuse ologun ninu iwe to ko ni 350 kj aristotle amoye ara griisi so pe ona to bofin mu dara ju ona enikeni lo
law
mátsù píktsù mátsù píktsù old peak pìpè ˈmɑt͡ʃu ˈpixt͡ʃu ni igba iwaju kolumbia ile inca to budo si loke ipele okun o budo si oke ebe lori afonifoji urubamba ni peru to je ariwaiwoorun cuzco ninu ibi ti odo urubamba gba koja opo awon onimo arkeoloji gbagbo pe machu picchu je kiko gege bi ile fun oluaye inca pachacuti 14381472 o je titoksi bi the lost city of the incas
macchu picchu
ibi ọ̀ṣọ́ àgbáyé ibi ọ̀ṣọ́ àgbáyé unesco je ibi bi egan okeile adagun asale iboji ileigbe complex tabi ilu to wa ninu akojo ti eto oso agbaye akariaye se ti igbimo oso agbaye unesco unsedari to ni awon orile-ede 21 gege bi omo egbe ti won je didiboyan latowo ile-igbimo gbogbogboo fun igba odun- merin kan ibi oso aye je ibi to se pataki fun asa tabi nitori boseri
world heritage site
ónjẹ alẹ́ olúwa ninu ihinrere esin kristi onje ale oluwa ni onje igbeyin ti jesus pin pelu awon aposteli mejila ti won je omo eyin re ki o to je kikan mo agbelebu
last supper
ìhìnrere a ihinrere ni iwe ti a ko to sapejuwe igbesiaye jesus
gospel
iṣẹ́ ẹlẹ́rọ iṣẹ́ ẹlẹ́rọ
industry
iṣé aápọn
iṣẹ́ ápọn
george washington carver george washington carver january 1864 january 5 1943 je omo orile-ede amerika to je onimosayensi onimo ogbin oluko ati oluda a ko mo ojo ibi re pato won gbagbo pe won bi ki won o to pa oko-eru re ni missouri ni january 1864
olú olú
mushroom
èbu èbu
fungus
eukarya
ìbu ìbu ni awon ebu to n hu jade bi ohun elemi oniahamo pupo
ahamo
mold
asean wikisource has original text related to this article the ajose awon orile-ede guusuilaorun asia geesi association of southeast asian nations to je ke kuru si asean pípè /ˈɑːsiɑːn/ occasionally ni geesi to je ede isise won je agbajo oloselu jeografi ati tekonomi awon orile-ede 10 ti won budo si guusuilaorun asia to je didasile ni 8 august 1967 latowo indonesia malaysia awon philippines singapore ati thailand
association of southeast asian nations
èdè xhosa xhosa pìpè ˈkǁʰoːsa isixhosa
xhosa language
èdè swati the swati or swazi language zulu
swazi language
èdè ndebele apágúúsù èdè southern ndebele isindebele or nrebele in southern ndebele
north west province south africa
southern ndebele language
èdè fenda venda bakanna bi tshivenḓa tabi luvenḓa je ede bantu ati ede ibise ni south africa
venda language
limpopo province
àwọn èdè bàntú àwọn èdè bàntú technically narrow bantu languages je idipo to je ikan niu awon ede ibatan niger-congo
bantu languages
èdè sotho apáàríwá northern sotho
northern sotho language
èdè sotho apágúúsù sesotho sotho southern sotho tabi southern sesotho
southern sotho language
unesco world heritage site
world wrestling entertainment world wrestling entertainment inc wwe
john dramani mahama john dramani mahama ojoibi 29 november 1958 je aare ile ghana ati igbakeji-aare orile-ede ghana tele o je didiboyan ni idiboyan odun 2008 teletele o ti je omo ile-igbimo asofin fun bole-bamboi ati omo ile-igbimo asofin gbogbo afrika lati ghana o ti je alakoso eto ibanisoro labe ijoba aare jerry rawlings
joseph arthur ankrah
kofi abrefa busia kofi abrefa busia ọjọ́ kọkànlá oṣù keje ọdún 1913 ọjọ́ kejìdínlọ́gbọn oṣù kejọ ọdún 1978 jẹ́ alákóso àgbà orílẹ̀-èdè ghana lati ọdún 1969 sí ọdún 72
ẹ̀sìn 'ẹ̀sìn ni igbagbo lori idie eda ati ise agbalaaye agaga bo se je nipa ida awon ohun ti oju koleri
jesu kristi
religion
màríà ìyá jésù màríà èdè aramaiki èdè heberu מרים maryām miriam èdè arabuمريم maryam ti awon omo leyin kristi n pe ni mariamo maria wundia tabi maria mimo ati nigba miran madonna je obinrin ju ara nazareth ni galilee ti majemu tuntunmt 1161825 lk 12656 217 tokasi gege bi iya jesu kristi awon musulumi na un pe ni maria mimo tabi syeda mariam to tumosi màríà ìyá wa majemu tuntun se apejuwe re bi wundia griiki παρθένος parthénos awon elesin kristi gbagbo pe o loyun jesu nipa emin mimo
muslims
jesus christ
aramaic language
mary mother of jesus
ẹlẹ́sìn krístì ẹlẹ́sìn kírísítì tàbí ọmọ lẹ́yìn kírísítì tàbí ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ ni eni tó nígbàgbọ́ nínú ẹ̀sìn kírísítì èyí tó jẹ́ ẹ̀sìn abrahamu tó gbà pé ọlọ́run kan ṣoṣo ló wà tó ń darí ayé àti ẹ̀kọ́ jésù ọmọ násárétì tí wọ́n gbà bí messiah tó jẹ́ sísọ tẹ́lẹ̀ nínú májẹ̀mú láéláé àti ọmọ ọlọ́run
christians
roman catholic church
christian
manhattan project the manhattan project ni oruko amioro fun iseowo to waye nigba ogun agbaye keji lati seda bombu atomu akoko orile-ede amerika lo lewaju iseowo yi pelu ikopa britani ati kanada
paul dirac paul adrien maurice dirac om frs pípè /dɪˈræk/ 8 august 1902 20 october 1984 je onimofisiiki oniro ara britani dirac se afikun pataki si ibere isise ero ayosere ati agbaraonina ayosere o di ipo ojogbon aga lukas fun mathematiiki mu ni yunifasiti ilu cambridge o si lo odun merinla togbeyin laye re ni florida state university ninu awon awari re o sagbekale isodogba dirac eyi salaye iwuwa awon fermion eyi lo si faye gba isotele wiwa olodi elo dirac pin ebun nobel ninu fisiksi fun 1933 pelu erwin schrödinger fun sisawari awon iru iro atomu tuntun to wulo igba ewe paul dirac je bibi ni ilu bristol ilegeesi ni adugbo bishopston lo gbe dagba ijapo interneti nínú a ó rí ọ̀rọ̀ tójẹmọ́ '
bristol bristol pípè /ˈbrɪstəl/ je ilu kan ni ilegeesi to wa ni iwoorun london ati ilaorun cardiff
richard feynman richard phillips feynman pípè /ˈfaɪnmən/ may 11 1918 february 15 1988 je was an american onimo fisiiki ara orile-ede amerika
agbéwọ̀ọ́kán
science
ìmọ̀dánidá
james clerk maxwell james clerk maxwell 13 june 1831 5 november 1879 je onimo fisiyiki oniriro ati mathematiiki ara skotlandi aseyori re to se pataki ju ni iro oninagberigberin to sakojopo gbogbo awon akiyesi adanwo ati awon isodogba fun itanna isegberigberin ati optiyiki teletele ti won ko baratan si iru tobaramu awon akojopo isodogba re—awon isodogba maxwell—fihan pe itanna isegberingberin ati imole na je ifarahanjade isele kanna papa oninagberingberin lati igba yi siwaju gbogbo awon ofin ati isodogba awon eka wonyi di iru mimuyanju awon isodogba maxwell ise maxwell ninu isoninagberingberin ti je pipe ni isodokan tolokiki keji ninu fisiyiki leyin ekinni ti isaac newton se maxwell fihan pe papa onina ati gberingberin n gba inu aaye koja gege bi oniriru ati pelu isare imole ti ko yi pada nipari ni odun 1864 maxwell ko iwe a dynamical theory of the electromagnetic field ninu ibi ti o ti koko damoran pe ni ooto imole je irusilesoke ninu ohun kanna to n fa isele onina ati gberingberin maxwell tun seda ipinka maxwell ona statistiki lati sapejuwe awon ese iro imurin awon efuufu awon iwari mejeji yi lo mu igba fisiyiki odeoni waye o se ifilele ise ojo iwaju ninu papa bi ijebaratan pataki ati isise ero atasere maxwell na lo tun da foto alawo akoko ni 1861 o si tun se ipilese idimule opo ati isopo won bi won se je mimulo ninu awon afara opolopo awon onimo fisiyiki gba maxwell pe o je onimo sayensi igba orundun 19 to ni ipa pataki julo lori fisiyiki igba orundun 20 awon afikun re si sayensi je iru kanna bi ti awon isaac newton ati albert einstein ninu iwadi igboro fun egberun odun iwadi lowo awon onimo fisiyiki pataki julo dibo fun maxwell gege bi onimo fisiyiki eketa tolokiki julo ni gbogbo igba leyin newton ati einstein nikan ni asiko ojoibi odun ogorun maxwell einstein fun ra re juwe ise maxwell gege bi eyi to se gbangba julo ati to wulo julo ti fisiyiki ni iriri lati igba newton einstein fi foto maxwell si ara ogiri yara ikawe re pelu foto michael faraday ati newton igbesiaye igba ewe 183139 james clerk maxwell je bibi ni 13 june 1831 ni 14 india street edinburgh fun john clerk maxwell agbejoro ati frances maxwell omo cay iwe fun kika http//wwwsonnetusacom/bio/maxbiopdf retrieved 2008-02-20 awon ijapo interneti nínú a ó rí ọ̀rọ̀ tójẹmọ́ '
wolfgang pauli wolfgang ernst pauli april 25 1900 december 15 1958 je ara orile-ede ostria to je onimo fisiyiki oniriro ati ikan ninu awon asiwaju ninu fisiyiki ayosere ni odun 1945 leyin ti albert einstein ti filoruko re sile o gba ebun nobel ninu fisiyiki fun afikun to se koko nipa iwari ofin tuntun adaba re opo iyasoto tabi opo pauli to jemo iro yiyi to wa labe idimule elo ati gbogbo kemistri
ernest rutherford ernest rutherford 1st baron rutherford of nelson om frs 30 august 187119 october 1937 je onimo kemistri ati onimo fisiyiki lati new zealand to gbajumo gege bi baba nuclear physics
erwin schrödinger erwin rudolf josef alexander schrödinger 12 august 1887 erdberg 4 january 1961 vienna je ara ostria to je onimo fisiksi oniriro to gbajumo fun afikun re si isise ero ayosere agaga isodogba schrödinger fun eyi to gba ebun nobel ni 1933 ninu awon leta ni 1935 si ore re albert einstein o damoran adanwo ironu olongbo schrödinger
eugene wigner eugene paul e p wigner hungarian wigner jenő pál november 17 1902 january 1 1995 je omo hungary amerika to je onimo fsiyiki ati onimo mathematiiki
sts-131 sts-131 iss assembly ifoloke 19a ni iranlose oko-alobo ofurufu to n lo lowolowo o gbera ni april 5 2010 lati itele igbera 39a iranlose yi n je gbigbelo pelu ọkọ̀-àlọbọ̀ òfurufú discovery
ọkọ̀-àlọbọ̀ òfurufú enterprise
space shuttle enterprise
pierre curie pierre curie 15 may 1859 19 april 1906 je omo orile-ede fransi to je onimo fisiyiki asiwaju ninu kristalografi isegberingberin piezoelectricity ati radiolilagabra ati elebun nobel ni 1903 o gba ebun nobel ninu fisiyiki pelu iyawo re maria skłodowska-curie ati henri becquerel fun idamo ise pataki ti won se nipa iwadi papo won lori isele itankakiri ti ojogbon henri becquerel se awari