raw_text
stringlengths
2
128k
pierre abelard
janez drnovsek janez drnovsek may 17 1950 february 23 2008 a bí ní ọdún 1950 ó jẹ́ olóòtú ìjọba slovenia ní 1992 sí 2002 lẹ́yìn èyí ni ó di àrẹ ilẹ̀ náà ní ọdún 1999 ni àìsàn kan ń bá a jà ní kíndìnrín ẹ̀kọ́ nípa ‘economics’ ni ó kà ó sì di ọmọ ilẹ́ asòfin ilẹ̀ slovenia ni ọdún 1986 iṣẹ́ ribiribi ni ó ṣe láàrin ọdún mẹ́wàá tí ó fi ṣe olóòtú ìjọba ó jẹ́ kí ilẹ̀r eẹ̀ dara pọ̀ mọ́ european union àti nato ní 2004 oṣù kéjìlá ọdún 2007 bí ó fi ipò àrẹ ilẹ̀ slovenia sílẹ̀ ó kú nígbà tí ó di ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógọ́ta
mohammed yunus muhammad yunus bẹ̀ngálì pipe ojoibi 28 june 1940 je omo ilè bangladesh wón bí i ní 1940 fún ebí olówó kan ní chittagong gosimíìtì ni bàbá rè ìyá rè jé sofia khatun mama rè yìí máa n ran àwon òtòsì lówó ìwà yìí sì ran mohammed nígbà tí òun náà dàgbà ó dí ilé-ìfowópamó tí a ti lè máa yá àwon òtòsì lówó sílè won kò nílò láti ní ìdúró kankan irú bánkì yìí ni í wá di community bank lóde òní mohammed yunus ló kókó dá a sílè yunus tí ní irú bánkì yìí nínú abúlé tó tó 35000 nínú abúlé 68000 tí ó wà ní bangladesh ó ti yá òpòlopò ènìyán kówó obìnrin ló pò jù nínú àwon tí ó n yáwó lówó rè òun ni ó gba ẹ̀bùn nobel ti 2006
ede yoruba
napoleon bonaparte <ns>0</ns> <revision> <parentid>544362</parentid> <timestamp>2021-04-27t121130z</timestamp> <contributor> <username>agbalagba</username> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> napoléon bonaparte 15 august 1769 5 may 1821 jẹ́ olórí ológun àti adarí òṣèlú àti ọmọ bíbí ìlú corsica ní ilẹ̀ faranse ó di ìlú-mọ̀ọ́ká ní àsìkò ìyípadà ìṣèjọba ilè faranse tí ó sì léwájú àwọn ìjangbara oríṣiríṣi ní àsìkò ogun gẹ́gẹ́ bí napoleon i òun ni ọba ilẹ̀ faranse láti ọdún 1804 sí ọdún 1814 àti 1815 napoleon ṣe àkóso ìjọba ilẹ̀ yuroopu àti àgbáyé fún bí ọdún mẹ́wá nígbà tí ó ń léwájú nínú àwọn ogun oríṣiríṣi tí a mọ̀ sí napoleonic wars ó ja ọ̀pọ̀lọpọ̀ ogun tí ó sì borí àwọn ogun tí ó sì mu láti gba àwọn ilé lọ́pọ̀lọpọ̀ fún ìjọba faranse tí ó sì darí ilẹ̀ yuroopu lápapọ̀ ṣáájú kí ìjọba rẹ̀ tó ṣubú ní ọdún 1815 ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn adarí ní orílẹ̀ àgbáyé tí wọ́n sì ń kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìṣèjọba rẹ̀ jákè-jádò àgbáyé ó sì wà nínú àwọn adarí tí ó gbayì jùlọ ní inú ìtàn àgbáyé
àwọn ogun napoleon ogun napoleon ìjàgbara tí a ń pe ní revolution tí ó ṣẹlẹ̀ ní france jẹ́ kí fance ní ọ̀tá púpọ̀ ní ìlú òyìnbó èyí ni ó sì fa ogun tí ó ṣẹlẹ̀ láàrin 1792 sí 1815 tí ó fẹ́rẹ̀ máa dáwó dúró ní àsìkò ogun yìí ilẹ̀ faransé ní ọ̀gágun kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ napoleon bonaparte ọ̀pọ̀lọpọ̀ ogun ni napoleon ṣẹ́ lẹ́yìn ìgbà tí ó ti ṣẹ́gun wọ̀nyí ó sọ ara rẹ̀ di emperor ní 1804 lẹ́yìn ìgbà tí ó ti di olórí ilẹ̀ faransé tán ó tún fẹ́ di olórí gbogbo ìlú òyìnbó nítorí ìdí èyí gbogbo ìlú òyìnbó ni ó wá gbógun tì í kí àbá rẹ̀ yìí má baà lè ṣẹ àwọn ìlú tó ń bá ilẹ̀ faransé jà nígbà náà ni austria prussia russia britain àti spain àwọn ọmọ ogun ilẹ̀ faransé pọ̀ gan-an ni wọ́n ṣẹ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ogun àwọ́n eléyìí tí ó ṣe pàtàkì jù ni ogun marengo àti hohenlinden ní 1800 ti austerlitz ní 1805 àti ti jena ní 1806 ìṣẹ́gun yìí fún napoleon ní agbara láti máa darí ilẹ̀ ìlú òyìnbó ṣùgbọ́n sá àwọn ológun ojú omi ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì lágbára gan-an ni ọ̀gá wọn ni lord nelson wọ́n ṣẹ́gun ọmọ ogun ilẹ̀ faransé ní ogun nile ní 1798 èyí ni kò jẹ́ kí ilẹ̀ faranse rí ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì gbà inú bí napoleon kò jẹ́ kí àwọn ọja ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì kọjá sí àwọn ilẹ̀ ìlú òyìnbó mìíràn mọ́ àìrí ọjà ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì yìí dá wàhálà sílẹ̀ fún àwọn ilẹ̀ yòókù spain yarí ó gbógun ti napoleon ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì lọ ran spain lọ́wọ́ ẹni tí ó ṣaájú ọmọ ogun ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì lọ ni arthur wellesley tí ó padà wá ń jẹ́ duke of wellington wọ́n ṣẹ́gun àwọn ìja kan ó ṣe russia dara pọ̀ mọ́ ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì àti spain napoleon ṣígun lọ sí russia ṣùgbọ́n gbogbo ọmọ ogun rẹ̀ ni ó kí sí ọ̀hún torí gbogbo ìṣẹ̀gun wọ̀nyí bsritain prussia sweden russia àti astria para pọ̀ láti bá ilẹ̀ faranse jà wọ́n ṣẹ́gun wọ́n wọ paris ní 1814 ní 1815 wọ́n lé napoleon lọ sí elba ó sá àsálà ó sì wá bá ọmọ ogun britain àti prussia jà ni waterloo wọ́n ṣẹ́gun napoleon wọ́n wá lé e lọ sí st helena
konrad adenauer wọ́n bí konrad adenauer ní 1876 ó kú ní 1967 òun ni chancellor west german federal republic ní 1949 sí 1963 òun ni ó dá christain democratic party sílẹ̀ òun sì ni alága rẹ̀ láti 1945 títí di 1966 lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n ti ṣẹ́gun jẹ́mánì tán ó fún jẹ́mánì ní òfin constitution tí ó fi ni lọ́kàn balẹ́ ó sì jẹ́ kí àwọn ìlú òyìnbó yòókù fún jẹ́mánì láyè nínú ẹgbẹ́ àfọwọ́sowọ́pọ̀ western alliance wọn ó sa gbogbo agbára láti jẹ́ kí ìparí ìjà wà láàrin ilẹ̀ fransi àti jẹ́mánì ṣùgbọ́n kò fi àyè accommodation gba rọ́síà
kàlẹ́ndà gregory kalenda gregory ni kalenda ti o n je lilo julo kakiri
oṣù osù jemó ìgbà tàbí àkókò tí a n lo ìwé-ìwo ojó fún tí àyípadà rè sì máa n pé bíi ojú ojó tí ó sì farapé bí òsùpá se n sisé osù àti òsùpá ní ìbásepò tó dánmórán kí a tólè mo bí osù se n sisé a gbódò ní òye púpò nípa bí òsùpá se n sisé òdiwòn tí òsùpá àti osù fi n sisé kòju ókàn dín lógbòn sí métà lé láàdóta ojó lo 2953 days
people's democratic party <ns>0</ns> <revision> <parentid>571115</parentid> <timestamp>2023-06-12t180358z</timestamp> <contributor> <username>enitanade</username> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> peoples democratic party pdp ẹgbẹ́ dẹmokrátíkì àwọn aráàlú jẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú alátakò ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà wọ́n dá ẹgbẹ́ òṣèlú yìí sílẹ̀ lọ́dún 1998 àwọn ni ọmọ ẹgbẹ́ wọn ṣe ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀ èdè nàìjíríà títí di ọdún 2015 kí ẹgbẹ́ òṣèlú all progressives congress tó gbàjọba àpapọ̀ lọ́wọ́ wọn ààrẹ orílẹ̀ èdè nàìjíríà mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ olúṣẹ́gun ọbásanjọ́ umaru musa yar'adua àti goodluck jonathan ni ẹgbẹ́ yìí jẹ kí ẹgbẹ́ apc tó dà wọ́n lágbo nù lọ́dún 2015 tí ààrẹ muhammadu buhari tí ẹgbẹ́ apc fi wọlé gẹ́gẹ́ bí ààrẹ
pdp <ns>0</ns> <revision> <parentid>532124</parentid> <timestamp>2020-04-25t214334z</timestamp> <contributor> <username>emausbot</username> </contributor> <minor /> <comment>bot fixing double redirect to people's democratic party</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format>
alfred adler alfred adler jẹ́ oníṣègùn òyìnbó ọmọ orílẹ̀-èdè austria wọ́n bí adler ní ọdún 1870 ó kú ní ọdún 1973 is ó jẹ́ oníṣègùn àrùn ọpọlọ tàbí wèrè psychiatrist òun ni ó dá ilé-ẹ̀kọ́ tí ó n jé ‘school of individual psychology’ sílẹ̀ ọ̀gbẹ́ni freud ni ó kókó n tè lé sùgbón ó yapa kúrò ní òdò rè lọ́dún 1911 ó tako ìtẹmpẹlẹ mọ́ ọ̀rọ̀ ìbá ra-ẹnì lòpò sex lójú rẹ̀ wàhálà tí ènìyàn ni láti sa agbára láti yọ ara eni kúrò ní ipò eni àá fojú ténbélú inferiority complex
robert adam robert adam wọ́n bí adam ní 1728 ó kú ní 1792 yaléyalé architect ni ọmọ ilẹ̀ scotland ni ọkùnrin mẹ́rin ni àwọn òbí rẹ̀ bí ó jẹ́ ọkan nínú wọn díẹ̀ lára àwọn ilé tí ó yà ni harewood house york osterley park kedleston hall derbyslire luton hoo bedfordshire àti kenwood
john adams john adams je oloselu omo ile amerika wọ́n bí adams ní 1735 ó kú ní 1826 òun ni ó jẹ president ilẹ̀ àméríkà lẹ́yìn washington òun ni ó kọ́kọ́ lọ ṣe ambassador ilẹ̀ oní-republic tuntun yìí ní ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì
john couch adams john couch adams wọ́n bí adams ní 1819 ó kú ní 1892 ọmọ ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì ni onímọ̀ ìṣirò mathematics ni astronomer sì ni pẹ̀lú òun àti leverrier astronomer ọmọ ilẹ̀ faransé kan ni wọ́n jọ gba ogo ṣíṣe àwárí neptune ní 1846 òtọ̀ọ̀tọ̀ ni wọ́n ṣe iṣẹ́ tí wọ́n gba ògo rẹ̀ yìí
samuel adams wọ́n bí adams ní ọdún 1722 ó kú ní 1803 olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ àmẹ́ríkà ni tí ó ń fẹ́ kí àyípadà wa boston ni wọ́n ti bí i láti nǹkan bíi 1765 ni ó ti ń sọ pé ẹni tí kò bá ní aṣojú kò gbọdọ̀ san owó-orí no taxation without representation ó gbé ‘boston tea-party’ ga ní 1776 ó fi ọwọ́ sí ìwé òmìnira declaration of independent
william adams william adams wọ́n bí adams ní 1564 ó kú ní 1620 iṣẹ́ ọkọ̀ ojú omi navigation ni ó ń ṣe dillingham kent ni wọ́n ti bí i ní ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì òun ni ọmọ ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì àkọ́kọ́ tí yóò lọ sí japan shogun ieyasu ní ìfẹ́ sí i gidi ni nítorí ìdí èyí wọn fi ibi tí àwọn gẹ̀ẹ́sì àti dutch ti lè máa ṣòwò lélẹ̀ ní japan eléyìí sì wà títí di 1616
jane addams jane laura addams a bí addams ní 1860 ó kú ní 1935 ọmọ ilẹ̀ àméríkà ni onímọ̀ nípa ẹ̀kọ́ tí wọ́n ń pè ní sociology ni òun ni ó dá hull house chicago sílẹ̀ ní 1889
joseph addison joseph addison je olukowe omo ile geesi wón bí addison ní 1672 ó kú ní 1719 ònkòwé ni addison olósèlú sì ni pèlú ó kópa nínú ‘taller’ òun àti steele ni wón sì jo dá ‘spectator’ sílè
adelard ará bath adelard ara bath tabi adelard de bada latin adelardus bathensis c 1080 c 1152 je omowe ara ilegeesi ni orundun 12th scholar o gbajumo fun ise akoko re ati fun iyipadaede awon iwe sayensi pataki ni iworawo itorawo imoye ati mathimatiki latede griki ati larubawa si ede latin lati atejade larubawa latibe ni won ti mu won wa si apaiwoorun europe o keko ni tours o soluko fun gba die ni laon layin re lo rinajo lo si apaguusu italia syracuse ni sicily ati antioch ni asia kekere o budo si bath ni ilegeesi ni odun 1122 o je eni igba kanna pelu william ara conches o si je eni to mo sode eye to si mo fere fan
olú agúnlóyè olu agunloye ‘geophysicist’ ni dr olú agúnlóyè ‘ administrator’ sì ni wón bí dr agúnlóyè ní ojó kerìndínlógún osù késàn-án odún 1948 wón bí i ní erusu-àkókó ní ìpínlè ondó ó kàwé ní university of ibadan láàrin 1971 sí 1974 unversity of reading uk ní 1974 àti massachusetts institute of technology òun ni corps marshall àti chief executive federal road safety commission télè òun sì ni minister of state for defence fún àwon navy télé
ìyípo
naijiria
egbe oselu olominira ti puerto rico
ibadan
abuja
obafemi awolowo
alumíníọ̀mù chemical element with atomic number 13 alumíníọ̀mù tabi aluminomu e wo spelling labe je apilese kemika kan ninu adipo boron to je funfun bi fadaka to se mo o ni ami-idamo al ati nomba atomu 13 ko le yo ninu omi fun ra ara re aluminiomu je onide to po repetejulo ninu igbele aye ati iketa to po repetejulo nibe leyin oksijini ati silikoni ohun ni o je bi 8 bi iwuwo oju ile aye aluminiomu ndarapomora mo awon kemika yioku kiakia gidigidi nitorie ko le da wa fun ra re gege bi onide bibeeko a le ri ni didapo mo orisirisi awon alumoni bi 270 orisun aluminiomu ni adalu irin bauxite
irin irin je àdàlú ni pataki julo idẹ pelu akoonu adú larin 02 and 17 or 204 ni iwuwosi adu ni o dinwoju lati se adalu mo idẹ sugbon a tun le lo adalu awon apilese miran manganisi kromiomu banadiomu ati wolframu adu ati awon apilese miran n sise bi imule sinsin lati dena ifo ninu atomu ayonu
tld
la <ns>0</ns> <revision> <parentid>387859</parentid> <timestamp>2013-03-08t133434z</timestamp> <contributor> <username>addbot</username> </contributor> <minor /> <comment> migrating 68 interwiki links now provided by on </comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> la je amioro orile-ede internet ti top-level domain cctld fun orile-ede laos
lb lb je ti orile-ede lebanon
ke
kg kg je ti ile kyrgyzstan
kh kh ni amioro orile-ede ti top-level domain lori internetcctld fun cambodia
ki ki
km
kn kn je ti ile saint kitts ati nevis
kp
kr kr je ti orile-ede guusu korea
kw kw
nf nf ile erékùsù nọ́rúfọ́lkì
ne ne
nc nc
na na
mz mz je ti ile mozambique
my my je ti malaysia
mx mx je ti meksiko
mw mw je ti orile-ede malawi
mv mv je amioro orile-ede ti internet fun top-level domain cctld fun orile-ede maldives
mu
lc lc ni amioro orile-ede lori internet ti top-level domain cctld fun saint lucia
li li jẹ́ ti ilẹ̀ líktẹ́ństáìnì
lk lk je ti ile sri lanka
lr lr je ti ile liberia
ls
lt lt
mt mt
ms ms
mr mr
mq
mp mp is the internet country code top-level domain cctld for northern mariana islands
mo
lu lu je amioro orile-ede top-level domain cctld fun internet ti luxembourg
lv lv ni amioro orile-ede top-level domain cctld lori internet fun latvia
ly ly je ti orile-ede libya
ma
mc mc ni amioro orile-ede top-level domain cctld ori internet fun monaco
md md je ti ile moldofa
me me je amioro internet fun ile montenegro
mg
mh mh ni amioro orile-ede ti internet fun top-level domain cctld fun marshall islands
mk mk
ml ml ni amioro orile-ede lori intrnet fun mali
mm mm ni àmì ọ̀rọ̀ orílẹ̀-èdè ti ìpele tí ó ga jùlọ lórí ẹ̀rọ ayélujára cctld fún burma lónìí gẹ́gẹ́bí ìṣọ̀kan ilẹ̀ myanmar ó jẹ́ fífifún ní ọdún 1997 síwájú 1989 àmì ọ̀rọ̀ iso 3166-1 fún burma ní bu ṣùgbọ́n bu cctld kọ̀ jẹ́ lílò rí rárá
mn mn je ti ile mongolia
julius nyerere julius kambarage nyerere 13 april 1922 - 14 october 1999 fi igba kan je aare ile tanzania ati ti tangayika tele
bòtswánà <ns>0</ns> <revision> <parentid>575751</parentid> <timestamp>2023-10-04t020023z</timestamp> <contributor> <username>internetarchivebot</username> </contributor> <comment>rescuing 1 sources and tagging 0 as dead #iabot v2095</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> bòtswánà lóníbiṣẹ́ bíi orílẹ̀-èdè olómìnira ilẹ̀ bòtswánà tswana jẹ́ orílẹ̀-èdè àdèmọ́àrinlẹ̀ tó bùdó sí apágúsù áfríkà àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè únpe ara wọn bíi batswana ẹyọìkan motswana sugbon awon elede miran unpe won bi ara botswana teletele o je ibi-abo britani to unje beshuanalandi botswana gba oruko tuntun leyin ominira ni ojo 30 osu kesan 1966 latigba na lo lo ti unse idiboyan oselu to gbomitoro botswana je petele be sini 70 je bibomole pelu aginju kalahari o ni bode mo orile-ede guusu afrika ni gusu ati gusuilaorun namibia ni iwoorun ati ariwa ati zimbabwe ni ariwailaorun bode re mo zambia ni ariwa nitosi kazungula zambia ko fi be nitumo sugbon ko gun ju bi ogorun mita lo botswana ko ni ju eniyan to to egbeegberun meji lo nitorie o je ikan ninu awon orile-ede alabugbe kekere julo ni agbaye nigba ti botswana gba ilominira latowowo ilẹ̀ọba aṣọ̀kan ni 1966 o je ikan ninu awon orile-ede to talaka julo ni afrika pelu gdp ti enikookan bi us70 latigbana botswana ti yira re pada lati di ikan ninu awon ti okowo re undagba julo lagbaye de eyi to ni gdp agbara iraja ti enikookan to to bi 14000 bakana asa oselu asoju gbale daada nibe ìtàn <ns>10</ns> <id>16733</id> <revision> <id>534273</id> <parentid>122075</parentid> <timestamp>2020-05-17t152113z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> <id>193</id> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> ni orundun 19k ogun sele larin awon tswana ti won ti ungbe botswana ati awon eya ndebele ti won sese unko bo si agbegbe yi lati ariwa-ilaorun bakanna rogbodiyan sele pelu awon ateludo boer lati transvaal ni ilaorun leyin itoro awon olori batswana bi khama iii bathoen ati sebele fun iranlowo ijoba britani fi bechuanaland si abe abo re ni ojo 31 osu keta 1885 ibi-ile apaariwa nigbana wa labe imojuto taara bi ibiabo beshuanalandi ibe lasi mo loni bi botswana nigba ti ibi-ile apaguusu di apa ileamusin cape loni o je apa igberiko ariwaiwoorun orile-ede guusu afrika opo awon eniyan to unso ede setswana loni ungbe ni orile-ede guusu afrika nigbati isokan ile guusu afrika je didasile bi orile-ede ni 1910 latinu awon ileamusin gbangba britani ni agbegbe na ibiabo bechuanaland basutoland loni bi lesotho ati swaziland eyun high commission territories ko je ara re sugbon eto wa nigbana lati safikun won lojowaju ipinnu ni pe ijiroro yio sele pelu awon alabugbe ibe botileje pe awon ijoba guusu afrika mura lati da awon ibi-ile na pada fun won britani dina eyi nitorie ko sele idiboyan ijoba asetolorile-ede ni odun 1948 to pile eto apartheid ati ikesejade guusu afrika kuro ni egbe kajola ni 1961 fi opin si ero pe awon ibi-ile yi yio bo si owo orile-ede guusu afrika ifidimule ijoba britani ati idasile ijoba ibile fa idasile ni 1920 igbimo agbero meji lati soju awon ara afrika ati ara europe awon ikede ni 1934 selana ijoba ati agbara ibile igbimo agbero ara afrika ati ara europe kan je didasile ni 1951 be sini isepo 1961 selana igbimo asofin adamora ni osu kefa 1964 britani fowo si aba idasile ijoba-araeni olselu ni botswana ibujoko ijoba kuro ni mafikeng ni guusu afrika ni 1965 si ilu tuntun ni gaborone cara mendapatkan kuota gratis 3 10 gb terbaru 2017 ti kkojinna si bode re isepo 1965 fa idiboyan gbogbogbo wa ati ilominira ni ojo 30 osu kesan 1966 seretse khama olori ninu awon egbe irinkankan fun ilominira ati ajoye ngwato je didiboya bi aare akoko o si tun ti je atundiboyan lemeji latigbana ipo aare bo sowo igbakeji aare quett masire to jje didiboyan fun ra re ni 1984 ati lemeji si ni 1989 ati 1994 masire feyinti ni 1998 igbakeji re festus mogae je didiboyan fun ra re ni 1999 ati lekan si ni 2004 ni 2008 ipo aare bo sowo ian khama omokunrin aare akoko to fi ipo re sile bi olori ile-ise iseabo botswana lati le ba bo si ipo oloselu yi ijiyan lori bode pelu namibia lori caprivi strip je lilaja latowo ile-ejo akariaye fun idajo ni osu kejila 1999 pe erekusu kasikili je ti botswana ìṣèlú àti ìjọba <ns>10</ns> <id>16733</id> <revision> <id>534273</id> <parentid>122075</parentid> <timestamp>2020-05-17t152113z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> <id>193</id> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> boilerplate seealso>ẹ tún wo foreign relations of botswana iselu ni botswana unwaye labe eto orile-ede olominira oloselu asoju nibi ti ààrẹ ilẹ̀ bòtswánà ti je olori orile-ede ati olori ijoba ati labe sistemu egbe oloselu pupo agba apase wa lowo ijobat agbara asofin wa lowo ijoba ati iléaṣòfin ilẹ̀ bòtswánà idiboyan aipe ikewa iru re waye ni ojo 16 osu kewa 2009 lati igba ilominira oselu ni botswana ti je gigaba latowo egbe oloselu botswana adajo ni ilominira latodo apase ati asofin gege bi isekedere akariaye se so botswana ni orile-ede afrika to ni iwa ibaje to din julo be sini ipo re sunmo portugal ati korea guusu nevertheless the country is considered to have the most secretive public institutions orin-iyin orile-ede ni fatshe leno la rona àwọn ìpín àmójútó <ns>10</ns> <id>16733</id> <revision> <id>534273</id> <parentid>122075</parentid> <timestamp>2020-05-17t152113z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> <id>193</id> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> botswana je pinpin si sàkání 15 sakani oko 9 ati sakani ilu 6
ìhà ìwọ̀-oòrùn
1 e10 m² to help compare orders of magnitude of different geographical regions we list here areas between 10000 km² and 100000 km² see also areas of other orders of magnitude definition 1 e+10 m² = formula_1 m²
perú peru je orile-ede ni apa guusu amerika lima ni oluilu
àkójọ àwọn orílẹ̀-èdè bí àwọn ènìyàn wọn se pọ̀sí list figures indicated by un estimate are based on the july 1 2009 estimate by the united nations department of economic and social affairs population division
port harcourt port harcourt tabi ebute harcourt ugwe ocha ni èdè igbo oborokiri ni ede ijo je ilu ni naijiria ati oluilu ipinle rivers
kàdúná kàdúná je ilu ni naijiria ati oluilu ìpínlẹ̀ kàdúná
gb gb gb je alfabeti yoruba pataki a b c d e ẹ f g gb h i j k l m n o ọ p q r s ṣ t u v w x y z
gúúsù amẹ́ríkà gúúsù amẹ́ríkà
guusu amerika
rakunmi
hàítì haiti je orile-ede ni apa ariwa amerika ni erekusu karibeani ti a mo si hispaniola
gámbíà gambia tabi orile-ede olominira ile gambia je orile-ede ni apa iwoorun afrika
liberia làìbéríà tabi orile-ede olominira ile làìbéríà je orile-ede ni iwoorun afrika o fi ègbé kan ilè sàró tí a mò si sierra leone ní ìwǫ oòrùn orílę èdè guinea ni gúúsù ati orílę èdè côte d'ivoire ní ìlà oòrùn etí òkun làìbéríà kún fún ijù igi mangrove nìbitì ilę nínú loun pęlú èrò kékeré ję kìkì ijù tí ó na apá sí ìtélè ewéko gbígbe ilu naa ni o ni 40 ninu eyi ti o seku ni igi iju guinea ti apa guusu afefe ilu làìbéríà je ti gbigbona ila idameji aye pelu òjo pupo ni osu may titi di osu october ni asiko òjò ati afefe oye lile fun iyoku odun
senegal sẹ̀nẹ̀gàl tabi orile-ede olominira ile senegal je orile-ede ni iwoorun afrika senegal ni okun atlantiki ni iwoorun mauritania ni ariwa mali ni ilaorun ati guinea ati guinea-bissau ni guusu sinu die lo ku ko yipo gambia ka patapata si ariwa ilaorun ati guusu ibi to se ku nikan ni eti okun atlanti gambia ifesi ile senegal fe to 197000 km² be si ni o ni onibugbe bi 137 legbegberun dakar ni oluilu re to wa lori cap-vert peninsula ni eti okun atlantiki bi iye ida kan ninu meta awon ara senegal ni won n gbe labe ila aini kakiriaye to je us 125 lojumo
ilaoorun afrika
iwoorun afrika
àríwá áfríkà
kristina fermandez de kirchner
kristina fernandez de kirchner
godwin babátúnde kofi akran godwin babatunde kofi akran a bí ọba akran ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹ́sàn-án ọdún 1936 lọ sí salvation army school kakawa lagos láàrin 1946 sí 1947 methodist school badagry àti methodist teachers training college ìfàkì-èkìtì láàrin 1956 sí 1957 ó lọ sí international press institute university of east africa nairobi kenya ní 1977 ó di reporter fún west african plot ní 1961 news editor new nigerian newspapers 1975-1977 ó di ọba ìlú badagry gẹ́gẹ́ bíi de whenọ ahọlu mẹnu toyi 1 ní ọdún 1977
tunji braithwaite tunji braithwaite je oloselu omo ile naijiria lọ́ọ́yà ni dr t́únjí braithwaite olóṣèlú sì ni wọ́n bí dr braithwaite ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹ́sàn-án ọdún 1943 òun ni ó dá nigeria advanced party nap tí wọ́n ti parẹ́ sílẹ̀ ó gbé àpótí fún ipò ààrẹ ilẹ̀ nàìjíríà lábẹ́ ẹgbẹ́ grassroots democratic advanced movement dam
káyọ̀dé ẹ̀ṣọ́ bobakayode eso 18 september 1925 - 16 november 2012a bí justice kayọde èsó ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹ́sàn-án ọdún 1925 ó lọ sí holy trinity school iléṣà láàrin 1933-1939 àti trinity college durban láàrin 1949-1953 wọ́n pè é sí bar ní lincoln inn london ní 1954 òun ni chief judge àkọ́kọ́ ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ní western court of appeal ipimle naa wọ́n yàn án ní justice supreme court lagos ní 1978 ó ti fẹ̀yìn tì báyìí